Yoruba Past Questions

Study and practice Yoruba past questions with answers and detailed explanations. Then test your knowledge using our interactive CBT practice platform and prepare confidently for your upcoming examinations.

58 questions JAMB 79 WAEC 794 CUSTOM 1
Download PHP app Ask a Question Check Syllabus Past Question Videos Topic Video Lessons

Take a test

Past Questions

58 questions
Question 1 of 20 58 total questions
Question 1
waec 2011

Ewo ni obìnrin nínú àwon wònyí? 

AApènà
BAjànà
COlúwo
DErelú
View Explanation & Discuss
Question 2
waec 2011

 "Ìka tó bá sè loba ń gé" je mó àsà

 

Aòràn dídá àti ijiyà
Bikíni àti ibòw fágbà
Ciranraenilówó
Dogún pinpín
View Explanation & Discuss
Question 3
waec 2011

Ewo ni odún ibilè? 

Aodún kérési
Bodún itúnu ààwè
Codún Osun Osogbo
Dodún àjíñde
View Explanation & Discuss
Question 4
waec 2011

Eni ti ó seni ní idí bàbá tàbí iyá ni.

Aalábàárò eni
Biserun eni
Colówó eni
Diwòfà eni
View Explanation & Discuss
Question 5
waec 2011

PÍN D: À

 Bi a bả fi osùn ránsé sí èniyàn, ó túmo si pẻ  rè ti bím

 

Aó léjó láti jé
Bòré re kan ti kú
Coba ń pè é
Daboyún rè ti bímo
View Explanation & Discuss
Question 6
waec 2011

PÍN D: ÀSA

 Aláboyún kò gbódò rin lósàn-án jé eewo

Aaàbò
Bimótótó
Cèsin
D
View Explanation & Discuss
Question 7
waec 2011

Àbèó İPÍN D: ÀSA

Ewo nínú àwon wònyí ni ó jé iwà rere?

AIfaradà
BOfófó
COlè
Dimele
View Explanation & Discuss
Question 8
waec 2011

Àbèó İPÍN D: ÀSA

 Ilepa je yo nínú àsà

Aigbéyàwó
Bisomolórúko
Ciranraenilówó
Disinkú
View Explanation & Discuss
Question 9
waec 2011

ERÉ ONÍTAN: Awé, D.: Ápótí Alákàrà

........ni iyàwó Kàrímù

ASèrí
BAńwòó
CAlàké
DÀbèó
View Explanation & Discuss
Question 10
waec 2011

ERÉ ONÍTAN: Awé, D.: Ápótí Alákàrà

"Rèi, làwon okùnrin ń dà léyin rè bí àgbébò adię olómọ yoyo". 

 

AAńwòó
BAbèó
CAàké
DŞèrí
View Explanation & Discuss
Question 11
waec 2011

ERÉ ONÍTAN: Awé, D.: Ápótí Alákàrà

Ta ni alága nibi ayeyę ikékòó-gboyè Arówólò?

AKàrímù
BOyè
CÖjògbede
D
View Explanation & Discuss
Question 12
waec 2011

 EWİ: LAYIWOLA, A.: Akòwé i wúrà àti àwon ijinlè àròfo miíràn

Ninú ewi "òle ", akéwi so pé òle kò nisé sùgbon ole ni

Aariwo enu
Bako ajá
Cojú àánú
Doko lójúde
View Explanation & Discuss
Question 13
waec 2011

 EWİ: LAYIWOLA, A.: Akòwé i wúrà àti àwon ijinlè àròfo miíràn

 Nínú ewi "Akowé ko wúà", kí ni akéwi fi ikojúsíni alákòwé wé?

AAko irè
Bobe òsikí
COde etilé
DEyin díndín
View Explanation & Discuss
Question 14
waec 2011

 EWİ: LAYIWOLA, A.: Akòwé i wúrà àti àwon ijinlè àròfo miíràn

Nínú ewi "Erò Lobèe Gbègiri", Akéwi so pé eni tí ó mu gaàrí sùn yóò

Ayàgbé
Blálàá wakò ojú-omi
Clálàá wa kèké
D
View Explanation & Discuss
Question 15
waec 2011

 İTÀN ÀRÒSO ÈSÓ-OLÚBORODE, S.: Olorunsogo

 Eni tí ó lu Bídèmí tí ó fi dákú ni

AÍsúmáilà
BOláníyi
CÉsan
DFémi
View Explanation & Discuss
Question 16
waec 2011

 İTÀN ÀRÒSO ÈSÓ-OLÚBORODE, S.: Olorunsogo

İdí tí Gbolá fi kò láti fé Títí ni pé

Akií gbóràn
Bkò mowé
Ckò yááyi
Dkò lajú
View Explanation & Discuss
Question 17
waec 2011

 İTÀN ÀRÒSO ÈSÓ-OLÚBORODE, S.: Olorunsogo

Olólùfé Rónké ní ilé-iwé sekóndiri ni

AÀbèfé Adéníyi
BÀdisá Láyí
CFémi òòsàfúnminíyi
DKúnlé Åmòsá
View Explanation & Discuss
Question 18
waec 2011

ERE ONÍSE: ÖGÚNNÍRAN, L.: Eégún Alåré 

 Oko İyádùn-ún-ní ni

ADáşofúnjó
BÖjè Lárinnàká
CDúdúyemí
DÖjékúnlé
View Explanation & Discuss
Question 19
waec 2011

ERE ONÍSE: ÖGÚNNÍRAN, L.: Eégún Alåré 

 Ta leni tí ó kókó ru èkú eégun?

ADúdúyemí
BLáinnàká
COlógbojò
Djelànàdé
View Explanation & Discuss
Question 20
waec 2011

 ERE ONÍSE: ÖGÚNNÍRAN, L.: Eégún Alåré

. Awon àgbà òjè kò fé kí Ojéládé di èniyàn léyin tí ó di òni nítorí pé

Aòkan lára won fé gbàyàwó rè
B
Có ń pidán jù wón lo
Dkò júbà won rárá
View Explanation & Discuss
Question Navigator
Current
MathsFaculty