Yoruba Past Questions

Study and practice Yoruba past questions with answers and detailed explanations. Then test your knowledge using our interactive CBT practice platform and prepare confidently for your upcoming examinations.

37 questions JAMB 79 WAEC 794 CUSTOM 1
Download PHP app Ask a Question Check Syllabus Past Question Videos Topic Video Lessons

Take a test

Past Questions

37 questions
Question 1 of 20 37 total questions
Question 1
waec 2020

     EWÌ

BABALOLÁ, A.: Awon Oríki Orilė Métàdínlógbòn (pp. i-116)

Nínú Oríki "Iran Arèsà",——ni ó sọ pé ðun lè fọ epo

 

AÖpòló
BYímíyímí
CÀKókó
DAlákàn
View Explanation & Discuss
Question 2
waec 2020

Ta ni enu rè rí tóósín? 

 

AAsín
BIjàpá
Còkéré
Dojà
View Explanation & Discuss
Question 3
waec 2020

İtàn "Asín àti Òkéré"

Kí ni ljàpá lọ tà lójà?

 

AIsu
BAwo
CIgi
Díresi
View Explanation & Discuss
Question 4
waec 2020

ÀMÒÓ, A.: Åkójopò Aló Åpagbė

Nínú itàn "İlú àwon Eranko", Ikún ni ó

Aji ilù Ekùn
Bpe gbogbo àwon eranko
Cjí ní kùtùkùtù
Dkan ilù tire
View Explanation & Discuss
Question 5
waec 2020

 "Oúnję ń pe oúnje ránşé" jé àpeerę

Aifòrògbeòrò
Bàfiwé tààrà
Càsorégèé
Diforòdárà
View Explanation & Discuss
Question 6
waec 2020

Ewo ni won so pé ki í "rinde Òsán"?

 

AJàndùkú
Bİjàkùmò
CÀdán
DÅfin
View Explanation & Discuss
Question 7
waec 2020

 "ÀIo á dára; àbò á sunwoh" jé àpęęrę 

Aikilo
Bikéde
Ciwúre
Dipolongo
View Explanation & Discuss
Question 8
waec 2020

 Èwo ni a máa ń šun?

 

 

 

AOlele
BIjálá
CEsa
DOfo
View Explanation & Discuss
Question 9
waec 2020

Túmò òkòòkan gbólóhùn tí ó wà ní ibéèrė yíí  sí ojúlówó èdè Yorùbá.

 It is a bitter-sweet issue

 

AOrò náà ň korò dùn
BÒrò náà kò yé èniyàn
CỘrò nắà kò dùn kò korò
DÒrò náà só sí ni lénu, ó. buyò sí i
View Explanation & Discuss
Question 10
waec 2020

Túmò òkòòkan gbólóhùn tí ó wà ní ibéèrė yíí  sí ojúlówó èdè Yorùbá

  Serve the food round.

 

APín oúnję náà tán
BPín oúnję náà kárí
CPín ooúnje náà lóbiírípo
DPín ounję náà kiri
View Explanation & Discuss
Question 11
waec 2020

Túmò òkòòkan gbólóhùn tí ó wà ní ibéèrė yíí  sí ojúlówó èdè Yorùbá

 It is according to the custom of Erínje people

 

ABí àşà àwon ará Erínję
BAşà tí àwọn ará Erírję ló jo
CGégé bí àşà àwon ärá Erínję ni ó je
DGégé bí àşà àwon ará Erínje
View Explanation & Discuss
Question 12
waec 2020

 Túmò òkòòkan gbólóhùn tí ó wà ní ibéèrė yíí  sí ojúlówó èdè Yorùbá

 Forgiveness is the fruit of repentance.  

Aidáriji nií şaájú ironúpiwàdà
Bİdáriji lèrè ironúpiwàdà
Cidáríji ati ironúpiwàdà ni Ogboogba
Dİdáríji lè fa ironúpiwàdà
View Explanation & Discuss
Question 13
waec 2020

GÍRÁMÀ

 İpín sí mófíimů "akóbàtà" ni

 

Aa-kó-bàtà
Ba-kóbàtà
Cakó-bàtà
Da-köbà-tà
View Explanation & Discuss
Question 14
waec 2020

GÍRÁMÀ

Nínú "kunle màà n jeun ,'' 'màà n je' ibá-ísele

 

Aàşetán
Batérerę
Càdáwà
Dbárakú
View Explanation & Discuss
Question 15
waec 2020

GÍRÁMÀ

Nínú "Mo lo sí Èkó"; Ekó' jè. 

 

Aoro-àpèjúwe
Borò-orúko
Còrò-àpónlé
Dorò-işe
View Explanation & Discuss
Question 16
waec 2020

GÍRÁMÀ

 Ewo ni ó ní awé-gbólóhùn aşàpèjúwe nínú? 

AJoké ni orúko mi
BGómìnà kọ ilé ńlá
CAşo tí mo wó dára
DBídèmí jé omo olólá
View Explanation & Discuss
Question 17
waec 2020

GÍRÁMÀ

 Nínú Mo ti dé", mo'jé oro-arópo- orúko  

Aenikínní eyo olùwà
Benikínní eyo àbò
Cenikeji opo àbò
Deniketa opo àbo
View Explanation & Discuss
Question 18
waec 2020

            GÍRÁMÀ

Nínú "Ojó rí mi', 'mi' jé omo

 

Aèpón
Bolùwà
Càbò
Dèyán
View Explanation & Discuss
Question 19
waec 2020

Orò tí a lè fi dípò 'àkókò' ni

Aígbà
Bigbá
Cigba
Dígbá
View Explanation & Discuss
Question 20
waec 2020

Éwò ni àrànmó wáyé nínú isèdá rè?

ADífá
BOòsà
CÁfèmi
DKósé
View Explanation & Discuss
Question Navigator
Current
MathsFaculty