Yoruba Past Questions

Study and practice Yoruba past questions with answers and detailed explanations. Then test your knowledge using our interactive CBT practice platform and prepare confidently for your upcoming examinations.

63 questions JAMB 79 WAEC 794 CUSTOM 1
Download PHP app Ask a Question Check Syllabus Past Question Videos Topic Video Lessons

Take a test

Past Questions

63 questions
Question 1 of 20 63 total questions
Question 1
waec 2016

AŞA

Ewo ló je mó işé àgbède?

 

AEbiti
BApásá
CKànnàkànnà
DEwiri
View Explanation & Discuss
Question 2
waec 2016

AŞA

 Sångó ni à ń ki ní

 

ALákáayé, Oşin imolè
BEní sojú, tó şemú
COgiri oko
DOlójú orógbó
View Explanation & Discuss
Question 3
waec 2016

AŞA

  Ogidíolú ni à ń kí ọmọ tó

 

Aní ika-owó méfà
Bmésè wáyé
Cdojú délè nígbà tí a bí i
Dwà nínú àpò nígbà tí a bí i
View Explanation & Discuss
Question 4
waec 2016

AŞA

 Ninú àşà ibílė Yorůbá, kí ni a kókó fi ń kí àlejò káàbò?

 

AOwó
BOmi
CObì
DOúnje
View Explanation & Discuss
Question 5
waec 2016

AŞA

Erèé ni a fi ń se

 

Aàkàrà
Bèko
Còjojò
Dàádùn
View Explanation & Discuss
Question 6
waec 2016

AŞA

Erèé ni a fi ń se

 

Aàkàrà
Bèko
Còjojò
Dàádùn
View Explanation & Discuss
Question 7
waec 2016

AŞA

Awọn wo ni wón ń lo 'èdán? 

 

AOlósun
BOlógbòóni
COlóbàtálá
DOlórò
View Explanation & Discuss
Question 8
waec 2016

AŞA

Awọn wo ni wón ń lo 'èdán? 

 

AOlósun
BOlógbòóni
COlóbàtálá
DOlórò
View Explanation & Discuss
Question 9
waec 2016

AŞA

llà tỉ àwọn ọmọ  Aláàfin mảa ń kọ ni

Apélé
Bkéké
Càbàjà
Dgònbó
View Explanation & Discuss
Question 10
waec 2016

 AŞA
Kí ni itumo "ògbọ rùn'"?

 

 

AÖgbèri wà nitòsi
BAlágbára ba dfefé jé
CEgbin kan wà nítòsí
DOgbò ti bàje
View Explanation & Discuss
Question 11
waec 2016

ERÉ ONÍTÀN: ADÉRÍBIGBÉ, M.: ré Mi 

  Idí tí Kúnbi kò se dá Fémi lóhùn dáadáa  ni pé

 

AFémi kò rewà lókùnrin
BFémi so èdè Giriiki
Càwọn asogbà wà nitòsi
DFémi kò múra bí olówó
View Explanation & Discuss
Question 12
waec 2016

ERÉ ONÍTÀN: ADÉRÍBIGBÉ, M.: ré Mi 

  Ibi tí Fémi fé kí won júwe fún òunni

 

AIyàrá Şolá
Bilé oúnję olóògùn ebi
Cgbòngàn eré idárayá
Diyàrá ikàwé
View Explanation & Discuss
Question 13
waec 2016

ERÉ ONÍTÀN: ADÉRÍBIGBÉ, M.: ré Mi 

 "idí tí gbogbo kóosi se ń dàbí Gíriki létí rè nìyen", ta ló sọ orò yii?

 

AŞolá
BFémi
Cİyá Fémi
D
View Explanation & Discuss
Question 14
waec 2016

LÍTÍRĖŞÒ ÀPILÈKO: iTÀN ÀRÒSO AJÉWOLÉ, 0.: Igbèyin Laláyò N ta.

 Ta ni wón pa ti?

 

 

 

AAmopé
BIgárá
CAsàké
DAkowé
View Explanation & Discuss
Question 15
waec 2016

LÍTÍRĖŞÒ ÀPILÈKO: iTÀN ÀRÒSO AJÉWOLÉ, 0.: Igbèyin Laláyò N ta.

  "Ojà ò ní í kún ká má má màfín",'àfín' tóka sí

 

Aakòwé
Bbàbá
Cadájó
Diyá
View Explanation & Discuss
Question 16
waec 2016

LÍTÍRĖŞÒ ÀPILÈKO: iTÀN ÀRÒSO AJÉWOLÉ, 0.: Igbèyin Laláyò N ta.

Kí ni işòro Aşàké?

 

AAirómobí
BAbókùnrin
CAinísé
DAiráyè-tójú oko
View Explanation & Discuss
Question 17
waec 2016

LÍTÍRĖŞÒ ÀPILÈKO: iTÀN ÀRÒSO AJÉWOLÉ, 0.: Igbèyin Laláyò N ta.

  Omo kelòó ni Öjó İsòbò ń kó nígbà tí àwon alágbàşe sùn sí abà rè? 

 

Aİkéwàá
Bİkésàn-án
Cİkejo
Dİkéfà
View Explanation & Discuss
Question 18
waec 2016

LÍTÍRĖŞÒ ÀPILÈKO: iTÀN ÀRÒSO AJÉWOLÉ, 0.: Igbèyin Laláyò N ta.

 Öjó İsòbò jé 

 

Aalágbàko òpe
Bará Ijerò
C
Dògbójú adáhunşe
View Explanation & Discuss
Question 19
waec 2016

LÍTÍRĖŞÒ ÀPILÈKO: iTÀN ÀRÒSO AJÉWOLÉ, 0.: Igbèyin Laláyò N ta.

 Éwo ni kì í se orúko inagije Obíşèsan?

 

AArimólè-tapo-sí
BArikùn-je-dùnndú
COba ikán
DÅgbàtíògò
View Explanation & Discuss
Question 20
waec 2016

ERÉ ONÍSE

ÀJÙWÒN, B.: Irèmojé Eré İşípà Ode

Ninú "A ki í kò ở", kí ni 'ớ tóka sí?

 

Aİpà ode
BAláàárů
COkorin Irèmòjé
DElégbè
View Explanation & Discuss
Question Navigator
Current
MathsFaculty