Yoruba Past Questions

Study and practice Yoruba past questions with answers and detailed explanations. Then test your knowledge using our interactive CBT practice platform and prepare confidently for your upcoming examinations.

138 questions JAMB 79 WAEC 794 CUSTOM 1
Download PHP app Ask a Question Check Syllabus Past Question Videos Topic Video Lessons

Take a test

Past Questions

138 questions
Question 1 of 20 138 total questions
Question 1
waec 2025

Ta ni ó máa ń tà ìlú lólobó ní ayé àtijọ́ bí ogun bá fẹ́ wọ ìlú lójijì?

AAlóre
BOníbodè
CBalógun
DÀṣípa
View Explanation & Discuss
Question 2
waec 2025

Olóyè tí ó n mojútó kárákátà ní àárín ìlú nígbà àtijọ́ ni

AOlógun
BAlápinni
COlúwo
DPàràkòyí
View Explanation & Discuss
Question 3
waec 2025

Ta ni olórí àgbòólé nínú àṣà ìbílẹ̀ Yorùbá?

AÀṣípa
BBaale
CỌba
DÌjọyè
View Explanation & Discuss
Question 4
waec 2025

Èwo ni ó ga jù nínú ìgbàgbọ́ Yorùbá?

AỌba
BỌkú-òrùn
COlódùmarè
DỌ̀rìṣà
View Explanation & Discuss
Question 5
waec 2025

Àwọn tí ó ń jagun fún ìlú ni a ń pè ní

Aesó
Bilari
Cẹrú
Dìwọ̀fà
View Explanation & Discuss
Question 6
waec 2025

Ọ̀kan nínú àwọn ìjọyè nínú awo Ifá ni

AAláàgbàà
BAraba
CAjànà
DErelu
View Explanation & Discuss
Question 7
waec 2025

Ajíṣefìnì' jẹ́ àpẹrẹ orúkọ

Aabíkú
Bàmútorunwá
Càbísọ
Dilaje
View Explanation & Discuss
Question 8
waec 2025

Èyí tí ó jẹ́ mọ́ ọrọ̀-aje nínú àṣà ìbílẹ̀ ni

Aopó ṣíṣú
Bẹ̀tọ́ ikẹ̀sẹ̀ ayé
Cìwọ̀fà yíya
Dawo Egúngún
View Explanation & Discuss
Question 9
waec 2025

Bàbá Adió ni ó

Aká Oládéjọ mọ́ ilé Adió
Brà ọjà àwìn lọ́wọ́ Adíjá
Cfowó taaká lójú àgbo
Dtẹ̀lé ọkọ lọ sí Kútònù
View Explanation & Discuss
Question 10
waec 2025

Kí íṣe tó bo lọ́wọ́ rẹ, Adió jẹ́

Aawakọ
Bakòwé
Conìtajà
Donílù
View Explanation & Discuss
Question 11
waec 2025

Ta ni Adió bere lọ́wọ́ rẹ pé "ṣé ó fẹ́ pa òun ni?"

AOladejo
BAdíjá
CỌkùnrin Ẹ̀rù
DAdù
View Explanation & Discuss
Question 12
waec 2025

Nínú èwì "Epo Robi Nìkan Kò Ní Ọlá", ipo wo ni akéwì to epo robi sí nínú àwọn agbára tí ó ń gbé ọrọ̀-ajé orílẹ̀-èdè rò?

Akerin
Bkinni
Ckeji
Dketa
View Explanation & Discuss
Question 13
waec 2025

ÈWÌ - AKANÍ, A.: Ọ̀rọ̀ Ẹ̀nu AkéwìNínú èwì "Agbà ò sí nílú", akéwì sọ pé ẹni tí ó bá ṣèṣi agbà, onítòhún á tẹ, kò níí

Agbón
Bdéní àpọnlẹ̀
Cdàgbà
Dtó abéré
View Explanation & Discuss
Question 14
waec 2025

ÈWÌ - AKANÍ, A.: Ọ̀rọ̀ Ẹ̀nu Akéwì

Nínú èwì "Pàtàkì Àṣà", akéwì sọ pé àṣà Yorùbá tí a pa tì lo fa

Aìwọ̀kúwọ̀ aṣọ.
Blílé tiróò
Ckíkún osùn
Dkíkọ orin irèmojé
View Explanation & Discuss
Question 15
waec 2025

Ta ni àwọn olóyè àti ará ilú bínú sí pé ó ń ṣàkóso ilú méjì pọ̀?

AỌ̀rànmíyàn
BỌbàwinrìn
CỌlúọ̀rọ̀gbò
DỌlálọmí
View Explanation & Discuss
Question 16
waec 2025

Ta ni Diwúrà pè ní "ojú kan èpà, oju kan erèé"?

AỌmọ rẹ̀
BÌyàwó-Ọmọ rẹ̀
CỌkọ rẹ̀
DỌmọ ọmọ rẹ̀
View Explanation & Discuss
Question 17
waec 2025

Ọ̀nà ibò ni ilé alàgbà Elújoba wà?

AÌtaakogun
BÒkèrèwẹ̀
CỌkọ òkè-egàn
DLàgèrè
View Explanation & Discuss
Question 18
waec 2025

ÈGÈ, ÈRÉ ONÍṢE - RAJI, S.: Ẹ̀gẹ̀ DídáÌjora tí ó wà láàrin ẹ̀gẹ̀ dídá àti rárá sísùn ni pé

Aohùn kan náà ni wọn ń lò fún àwọn méjèèjì
Bàdúgbò kan náà ni àwọn méjèèjì ti ń wáyé
Ca ń fi rárá kì Ọba; a ń fi ẹ̀gẹ̀ náà kì Ọba
Dàwọn olórò ló ní àwọn méjèèjì
View Explanation & Discuss
Question 19
waec 2025

ÈGÈ, ÈRÉ ONÍṢE - RAJI, S.: Ẹ̀gẹ̀ Dídá Ẹ̀gẹ̀ dídá fi ara pé

AÈṣù pípè
Bekún iyàwó
Corin obìtùn
Dorin etiyèrí
View Explanation & Discuss
Question 20
waec 2025

ÈGÈ, ÈRÉ ONÍṢE - RAJI, S.: Ẹ̀gẹ̀ Dídá

Ohùn ègè ni a fi n pe

Ape Orò
Bsun ìjálá
Csun irèmojé
Dkì Ifá
View Explanation & Discuss
Question Navigator
Current
MathsFaculty