Yoruba Past Questions

Study and practice Yoruba past questions with answers and detailed explanations. Then test your knowledge using our interactive CBT practice platform and prepare confidently for your upcoming examinations.

794 questions JAMB 79 WAEC 794 CUSTOM 1
Download PHP app Ask a Question Check Syllabus Past Question Videos Topic Video Lessons

Take a test

Past Questions

794 questions
Question 1 of 20 794 total questions
Question 111
waec 2018

ÀŞÀ

Orúko miiràn fún "yánko" ni. 

 

Aètů
Bàdi
Ceyin
Daró,
View Explanation & Discuss
Question 112
waec 2018

ÀŞÀ

— ni à ń pe omo tí ó wà nínú àpò nígbà tía bí

 

Aòní
BÌgè
CÌlộrí
DÒké
View Explanation & Discuss
Question 113
waec 2018

ÀŞÀ

—ni Yorùbá gbàgbó pé ó máa ń gbé ire ko ni. 

Aowó
Benu
Corí
Desè
View Explanation & Discuss
Question 114
waec 2018

ÀŞÀ

Onígbàjámo ni ó máa ń.

 

Adi irun
Bfá irun
Clu ilù
Drọ okó
View Explanation & Discuss
Question 115
waec 2018

ERÉ ONÍTÀN: Adéríbigbé, M.: Oré Mi

Ibo ni bàbá Şolá ti ń şişé? 

 

Ailé-işé işokò
Bởgbà itókòşe
Cogbà Yunifásíti
Dréluwèé
View Explanation & Discuss
Question 116
waec 2018

ERÉ ONÍTÀN: Adéríbigbé, M.: Oré Mi

 "Òdòdó abèmí" wo ni ebí Olápeléke wá lọ sí idilé Egbédá ? 

 

 

AŞadé
BFikémi
CKúnbi
DŞoláyídé.
View Explanation & Discuss
Question 117
waec 2018

ERÉ ONÍTÀN: Adéríbigbé, M.: Oré Mi

Olóyè Odùnowó ni ó tún ń jé.

 

ATẹjúmówó
BKáyodé
COlápeléke
DKólá
View Explanation & Discuss
Question 118
waec 2018

EWI: Fádíyà, 0.: tyá Ảtảtà

Kí ni ó ń fa eni lé ikú àitójó lówó?

 

Aowó òkùnkùn
Bişé òkùnkùn
Cọmọ eríwo
Diràwò àsán
View Explanation & Discuss
Question 119
waec 2018

EWI: Fádíyà, 0.: tyá Ảtảtà

  Ta ni olórí egbé òkùnkùn àkókó?

 

ALúsíféri
BĀpáta páàrá
Cipánre
Djàndùkú
View Explanation & Discuss
Question 120
waec 2018

EWI: Fádíyà, 0.: tyá Ảtảtà

 Nínú ewi "Obìnrin Ológo", oba àwon ęja ni.  

AAgùalà
BÀkárákudà
CQrí
DÒjí
View Explanation & Discuss
Question 121
waec 2018

LÍTÍRÉŞO ẢPILĘKO - İTÀN ÀRÒSO

Ajéwolé, 0.: Igbèyin Laláyò Ń Ta

  Ibo ni gbómogbómo ti gbé Obí?

 

AĪbàdàn
Bİşéyin
Cİjerò
DIkóro.
View Explanation & Discuss
Question 122
waec 2018

LÍTÍRÉŞO ẢPILĘKO - İTÀN ÀRÒSO

Ajéwolé, 0.: Igbèyin Laláyò Ń Ta

 Ta ni "omo Oré-Ewi"?

Aİyá Òbí
Bègbón Òbí
CBàbá Òbí
Dòré Òbí
View Explanation & Discuss
Question 123
waec 2018

LÍTÍRÉŞO ẢPILĘKO - İTÀN ÀRÒSO

Ajéwolé, 0.: Igbèyin Laláyò Ń Ta

İyàwó mélòó ni bàbá Òbíşèsan ní?

 

Améfà
Bmérin
Cméta
Dméji
View Explanation & Discuss
Question 124
waec 2018

ERÉ-ONÍŞE: Àjùwòn, B:

Irèmòjé Eré Isipà ode 

Omisin Ogún ni à ń pè ní.

 

AAlukósó
BAlágùnta
CAlůlégò
DAlàwòrò
View Explanation & Discuss
Question 125
waec 2018

 ERÉ-ONÍŞE: Àjùwòn, B:

Irèmòjé Eré Isipà ode 

 Òru ni a mảa ń.

Asipà ode
Bsàríyå odę
Csin ode
Ddègbé ode
View Explanation & Discuss
Question 126
waec 2018

 ERÉ-ONÍŞE: Àjùwòn, B:

Irèmòjé Eré Isipà ode 

 Òrişà wo ni ó ni Irèmòjé?

AObàtálá
BOgún
CEşù
DŞàngó
View Explanation & Discuss
Question 127
waec 2018

 Ewi: Babalolá, A.: Àwon orikì oríle métàdínlógbòn (pp.iii-116)

 İyá Alááfin òpómúléró ni.

Aİwànù omọ pa- wón-dà
BMorejè n'Murệ
CObàrànbirí
DMóríléwá
View Explanation & Discuss
Question 128
waec 2018

 Ewi: Babalolá, A.: Àwon orikì oríle métàdínlógbòn (pp.iii-116)

Nínú oriki "Ìran opómúléró", ta ni ó lọ sógun tí kò padà mộ? .

AAbímbéşú ,
BAfibirin
CÀbídòrí
DÀfonjá. ,
View Explanation & Discuss
Question 129
waec 2018

LÍTÍRÉŞO ALOHÙN -İTÀN ÀRÒSO Àmoó, A.: Àkójopò Àló Åpagbè
  Nínú itàn "ilệ àti Olórun", ta ni ó gbé èbọ lọ sorun? 

 

Ababaláwo
BOba
Ceyę iğún
Deku emó.
View Explanation & Discuss
Question 130
waec 2018

LÍTÍRÉŞO ALOHÙN -İTÀN ÀRÒSO Àmoó, A.: Àkójopò Àló Åpagbè
Kí ni oba şe fún eni tí ó pa Abuké Oşin?  

Aó pa á
Bó sọ ó doré kòríkòsùn
Có dá a lóla
Dó fún un ní eşin ńlá kan.
View Explanation & Discuss
Question Navigator
Current
MathsFaculty