Yoruba Past Questions

Study and practice Yoruba past questions with answers and detailed explanations. Then test your knowledge using our interactive CBT practice platform and prepare confidently for your upcoming examinations.

59 questions JAMB 79 WAEC 794 CUSTOM 1
Download PHP app Ask a Question Check Syllabus Past Question Videos Topic Video Lessons

Take a test

Past Questions

59 questions
Question 1 of 20 59 total questions
Question 1
waec 2024

".. lákáayé, Oşinmolė", jé àrà oriki

AEsů
BÖgún
CObàtálá
DOrúnmilà
View Explanation & Discuss
Question 2
waec 2024

______ jé òkan lára àwọn ohun èlò fún híhun

AIgi ewé iran
BIgi oparun
CIgi opę
DIgi ewé akòko
View Explanation & Discuss
Question 3
waec 2024

Äjótàpá ni a máa ń jó

Agángan
Bkęríkeri
Cbènhbé
Dbàtá
View Explanation & Discuss
Question 4
waec 2024

Ohun iní òkú ni à ń pè ní

Aoro
Bogún
Colá
Dikógun
View Explanation & Discuss
Question 5
waec 2024

A máa ń pa ààlè lé ohun iní eni láti

Amọ iye èniyàn tó kọjá níbè.
Bmú ohun iní náà pé lówo eni.
Cdékun olè jjà.
Dfi Opin sí aáwo.
View Explanation & Discuss
Question 6
waec 2024

Omọ wo ni à ń ki báyií: "Bí iyá lè kú, kó kú..?

AIgè
BAiná
CAjàyi
DDàda
View Explanation & Discuss
Question 7
waec 2024

_________ ni à ń kí ní 'Àborúboyè

AQdę
BOlósàn-ányìn
CBabaláwo
DAkỳpę
View Explanation & Discuss
Question 8
waec 2024

Àkóbí omọ lókùnrin ní ààfin ni

Abéérè
Bàrèmo
Ciwàlė
Ddáódù
View Explanation & Discuss
Question 9
waec 2024

Ta ni ó jérií sí owó tí Adú gbé fún Dėjo?

AÀbèní
BBòsípò
CÁdió
DBayo
View Explanation & Discuss
Question 10
waec 2024

ÀWon woni ó máa ń ra àwòrán ní egbélégbè náirà?

ATálákà
BOníşòwò
COlówÓ
DAlákòwé
View Explanation & Discuss
Question 11
waec 2024

Kí ni won fi şe àlejò bàbá àgbà nígbà tí ó wá túf?

AEran
BOmi
CEbà
DBúrédi
View Explanation & Discuss
Question 12
waec 2024

Ninú ewi "Má Yò Mi", irúgbin wo ni akéwi so pé ó lè kó?

AOgómò
BIlá
CIşin
DEwe
View Explanation & Discuss
Question 13
waec 2024

Lára kí ni a ti lèrí awo?

AKòlòkòlò
BIgún
CAòni
DAgbò
View Explanation & Discuss
Question 14
waec 2024

Ta ni agbára ń pa bí otí?

AOdésanmí
BOmidan
CBàbá
DAwááyékú
View Explanation & Discuss
Question 15
waec 2024

Níbo ni Olúrónbí rò pé àwon Ugbó ti pa Délàjà?

AOko
BEnúwà
CLàgèrè
DÖkèrèwè
View Explanation & Discuss
Question 16
waec 2024

Móremí àti ta ni ó te ilé ilá dó?

AOnífádé
BElújoba
COkànbí
DOlálomí
View Explanation & Discuss
Question 17
waec 2024

Kíni ó se atónà Móremí tití tí ó fi dé ilú ilá Òràngún?

AEkòló gòdògbà
BOpá àşe
COdò Esinmirin
DEşin funfun
View Explanation & Discuss
Question 18
waec 2024

Eyí tí ó je yọ nínú oriki orilè Owu ni

Aomo-o-bóogùn boògùn
Bomo-èpè-ò-jà
Como-ilè ń yò porangandan
Domo Epínrín tí ń ta dídùn
View Explanation & Discuss
Question 19
waec 2024

Agbègbè wo ni wón tỉ ń kọ orin senwelę?

Aİbàdàn
Bİlorin
Cijèsà
Dİjèbú
View Explanation & Discuss
Question 20
waec 2024

Eni tí okorin kì ní Omo kàlá ogun nínú ogun" ni

AAjijolá
BOşólùadé
CAkíntòńdé.
DLábérinjo
View Explanation & Discuss
Question Navigator
Current
MathsFaculty