Yoruba Past Questions

Study and practice Yoruba past questions with answers and detailed explanations. Then test your knowledge using our interactive CBT practice platform and prepare confidently for your upcoming examinations.

794 questions JAMB 79 WAEC 794 CUSTOM 1
Download PHP app Ask a Question Check Syllabus Past Question Videos Topic Video Lessons

Take a test

Past Questions

794 questions
Question 1 of 20 794 total questions
Question 131
waec 2018

ÀRÒKO

 Déèti kíko pọn dandan nínú àröko

Aonilétà
Boníròyin
Caşàríyànjiyàn
Daşàpėjúwe
View Explanation & Discuss
Question 132
waec 2018

ÀRÒKO

"Işé olůkó" ję mó orí ro fún àròko

 

Aaşàpèjúwe
Bajemó işípayá
Caşàríyànjiyàn
Doníròyin.
View Explanation & Discuss
Question 133
waec 2018

ÀRÒKO

Ewo ni ó je mó àròko asàríyànjiyàn?

 

Aowó lègbón, omọ làbúrò
Boba ilú mi
Cipàdé egbé akómolédè tí ó kọjá
Dèké.
View Explanation & Discuss
Question 134
waec 2018

ÀRÒKO

 "Ayęye igbéyàwó kan tí ó sojú mi" ję àpęęrę orí òrò fún àròko

 

Aoníşoròngbèesi
Başàpèjúwe
Coníròyin
Daşàríyànjiyàn.
View Explanation & Discuss
Question 135
waec 2018

Åkolė tŕ ó bá àyòká yii mu jùlo ni

 

Aojó mánigbàgbé
Boúnje omọ
CAdéagbo, bàbả nóosi
Dirinàjò Adéagbo sí ilú òyinbó.
View Explanation & Discuss
Question 136
waec 2018

Ohun tí ó je Adéagbo lógún ni

 

Aişé işègůn
Bişé onímò èro
Cèkó omo
Dirinàjò Adéagbo sí ilú òyinbó
View Explanation & Discuss
Question 137
waec 2018

 Traka nínú àyòká yií túmo sí

 

 

Arin irinàjò
Bfi opé fún Olórun
Cgbiyànjú
Dramotò.
View Explanation & Discuss
Question 138
waec 2018

 Akóbí idíle yíí ni ó di.

Aonímo,ero
Bnóòsi
Coníşègun
Dtisà.
View Explanation & Discuss
Question 139
waec 2018

Ka àyokà isàlè wònyii, kí o sì dáhùn àwon ibéèrè tí ó tèlé òkòòkan won.

Ojó mánigbàgbé, ojó ayò, lójó ti Adétutù gbé Adéagbo àti Ajibikèé tí wón jé òbí rè lo sí ilú oyinbó. Awon méjèèji si fopé fún Olorun pé àwon ti ipase omọ là. 

Wón kò bả olá nílé şùgbón èkó àwon omo won je wón lògún Wón tiraka láti rán àwon omo won nílé èko. Âwon omọ náà sì kàwé yanjú.  Akíntòmídé, àkóbí won, di ògá onímò èrọ. Adétutů gba oyè imo ijinlè nínú işé iségun: Olúwaşeun di Omowé nínú isé olůkoni. Abiímbolá, àbikéyin won yan işé nóosi láàyò. Oun nikan ni ó ń şişé ní orilè èdè Nàijíríà. Àwon yà yòókù si fi Okè Ökun şe ibùgbé. BÍ Adéagbo àti Ajibíkėé, iyàwó rè şe padà sí orílè èdè Nàijíríà, ilé tí Abímbolá kó fún won ni wón dé sí. Motò obokùn olóyé tí Olúwaşeun rà fún wọn ni ó wá gbé wọn ní pápáko ofurufú.

  —— ni ó ń şişè ní orile èdè Nåijiriä?

 

AOlúwaşeun
BAkíntomídé
CAdétutu
DAbímbolá
View Explanation & Discuss
Question 140
waec 2018

İmòràn tí a fún Şàngó ni pé kí ó 

 

Apa àwon jagunjagun
Bfa ojú àwon jagungun móra
Cdin inú bibí re kù
Dsóra fun àwon iyàwó re.
View Explanation & Discuss
Question 141
waec 2018

Orúko iyá Şàngó ni

 

AOşun
Boya
C
DTorosí
View Explanation & Discuss
Question 142
waec 2018

Timi Àgbàlé àti gbonkaaebiri

 

Amú inú Şàngó bàjé
Bdi odò
Cfi orò lọ iyàwỏ
D
View Explanation & Discuss
Question 143
waec 2018

 —— ni iyá Şàngó ni féràn jů 

AOba
BOya
COşun
DTorosí
View Explanation & Discuss
Question 144
waec 2018

Ka àyokà isàlè wònyii, kí o sì dáhùn àwon ibéèrè tí ó tèlé òkòòkan won.

 

İtàn àbláyé so pé Oba ni Şàngó lóde Oyó nígbà ayé rè. Omo İlú Tápà ti Elénpe ni Torosí iyá rè. Àwọn iyàwó métèèta tí Şàngó fé ni wón di odò léyiìn ikú won: Oya bíņú di odo Oya, Obà di odò Obà tí ó la İwổ kòja Sun sì di odò Oşun tí ó la Òsogbo kojá, Aágbára ni Şàngó, ó láyà, ó sì lóògùn débi pé ó máa ń yoná lénu bí inú bá ń bí i, Éyi mủ kí èrù rè máa bá tẹrú tọmọ láşikò náà. lóde Òyó tó, Tìmì Ágbàlé àti Gbòńkáà Ebiri. tí won si jé kí inú Şàngó dun rárá. ó forò náà tó Oya tí ó jé ààyò rè létí. ya si gbà á nímoràn láti wá onà tí yóò fi yęjú àwon méjèèji.he

 

Ohun ti ó mú erù Sàngó bả âwon ará ilú ni pé Ú.

Afé iyàwó méta
Bjé oba Oyó
Cmáa ń yo iná lénu
Djé omọ Tápå.
View Explanation & Discuss
Question 145
waec 2016

AŞA

Ewo ló je mó işé àgbède?

 

AEbiti
BApásá
CKànnàkànnà
DEwiri
View Explanation & Discuss
Question 146
waec 2016

AŞA

 Sångó ni à ń ki ní

 

ALákáayé, Oşin imolè
BEní sojú, tó şemú
COgiri oko
DOlójú orógbó
View Explanation & Discuss
Question 147
waec 2016

AŞA

  Ogidíolú ni à ń kí ọmọ tó

 

Aní ika-owó méfà
Bmésè wáyé
Cdojú délè nígbà tí a bí i
Dwà nínú àpò nígbà tí a bí i
View Explanation & Discuss
Question 148
waec 2016

AŞA

 Ninú àşà ibílė Yorůbá, kí ni a kókó fi ń kí àlejò káàbò?

 

AOwó
BOmi
CObì
DOúnje
View Explanation & Discuss
Question 149
waec 2016

AŞA

Erèé ni a fi ń se

 

Aàkàrà
Bèko
Còjojò
Dàádùn
View Explanation & Discuss
Question 150
waec 2016

AŞA

Erèé ni a fi ń se

 

Aàkàrà
Bèko
Còjojò
Dàádùn
View Explanation & Discuss
Question Navigator
Current
MathsFaculty