ÈTÒ İRÓ
[d] jé kóńsónáħti
Study and practice Yoruba past questions with answers and detailed explanations. Then test your knowledge using our interactive CBT practice platform and prepare confidently for your upcoming examinations.
Create and set up a CBT environment with your preferred subjects.
Practice JAMB CBT with real UTME past questions in CBT format.
CB-WASSCE styled past question practice.
SSCE & GCE styled past question practice.
ÈTÒ İRÓ
[d] jé kóńsónáħti
ÈTÒ İRÓ
Fáwėli èbäkè iwájů ni
ÀROKO
Ori-orò fún àròko aşàríyànjiyàn ni
ÀROKO
"Işé aşo hihun", lè jé orí-orò fún àròko
ÀROKO
Ewo ni ó ję mộ àròko oníròyín?
ÀROKO
Létà àigbagbèfė nikan ló máa ń ní
Akolé ti ó bả àyokà yii mu jùlo ni?
Foláhànmí jé?
Foláhànmí jé?
Ibòdi ni ?
Bádéjo pinnu láti tộ ằwọn omọ rệ nl èkó-iwe nitorí pé?
Ka àwon àyokà isàlệ wònyí, kí o si dáhùn àwọn ibéèrè tí ó tèlé òkóókan won.
Omo bibí lú Béyiòşe ni İşòlá. Òun àti àbúrò rè, Foláhànmí, nikan ni Bádéjo, bàbá wọn bí. Agbè onikòkó aládàáńlá ni Bádéjo. Bólátitó, aya rè, sì jé oníşòwò obi. Bádėjo kò kàwé şùgbón ó pinnu láti tó àwọn omo rè méjèèji débi tí wón bá lè kàwẻ dé láyé, nítorí pé iyà àikàwé je é púpò nídií òwò tí ó ń şe. Léyin ti İşolá parí iwé méwàá ní ilú ibòdi ni ó gba ilú Arómisá lo láti tè síwájú nínú èkó rè ní fásiti. ilú ọba ni ó si ti gba oyè imó ijinlè keji nínú òfin. İşòlá padà sí ilú Bėyiòşe, ở si di gbajúgbajà agbęjórò kájkiri agbègbè náà.
Ilú abinibi Bådéjo ni ?
Àkolé tí ó bá àyọkà yiỉ mu jùlo ni.
Ki ni ànfààní tỉ ó şe pàtàkì jù lára işèlè- işé yii?
Adépitàn ni ó
2. Eka mélòó ni ó wà nílé-isé náà?
Ka àwon àyokà isàlè wònyí, kí o sì dáhùn àwọn ibéèrè tí o wa tèlé òkoòkan wọn.(1-5)
Ódún kejilả rèé tí Adébáre, Adéyanjú àti Adéoyè ti wà ní Tòròńtò, ilú gba. Gbogbo wọn ló ti lówó. Adébåre nikan ni ó pinnu láti wá dá ilé-işé silè ni Ajélàńwă, ilú rè, nítorí pé ilé làbò isinmi oko.Ó si tun rò pẻ yóò fún àwọn ará ilú rè ní ànfààní láti rişé òwò şe. Ní ojó işilé-işé yií, ilú kún fófó ayẻ gbỏ, òrun sì mò. Màlúù méji ni oba Akànni, Alájé ti Ajélàńwá fà kalè nítorí idùnnú tí cở ở şubú layò fún un pẻ àsikò òun ni ilé-işé wòlú. Ó dúpé lówó Adébáre fún àigbàgbé ilé. ó si şí ilé-işé nåà nípa gigé aşo tééřé tí a ta sí enu ònà,
Ninú ilé-işé yii ni a ti rí oríşiríşi èka bí aşo híhun, ike şişe, búredi şíşe, abó ijęun şíşe àti şişe omi amólöló. Adépitàn tí ó jé ògá olópàá ní agbègbè yii şèlėrí ipèsè ààbò tó péye fún ilé-isé náà.
1. Adébáre nikan ni o.
ÀŞÀ
Ewiri je mó işệ odę ——
ÀŞÀ
——ni ó je mó awo Ifá.
ÀŞÀ
Éwo ni ó je mó igbàgbó nínú àşèyinwáyé?