Yoruba Past Questions

Study and practice Yoruba past questions with answers and detailed explanations. Then test your knowledge using our interactive CBT practice platform and prepare confidently for your upcoming examinations.

794 questions JAMB 79 WAEC 794 CUSTOM 1
Download PHP app Ask a Question Check Syllabus Past Question Videos Topic Video Lessons

Take a test

Past Questions

794 questions
Question 1 of 20 794 total questions
Question 181
waec 2015

İTÀN ÀRÒSO: ÒJ0, O.: İjàpà Tìrókò Oko Yánníbo

Nínú itàn "Omokùnrin àti İjàpá"

Nínú itàn "Erin àti ljàpá", otá ilú ni

Aerin
Bİjàpá
COba
DEye
View Explanation & Discuss
Question 182
waec 2015

İTÀN ÀRÒSO: ÒJ0, O.: İjàpà Tìrókò Oko Yánníbo

Nínú itàn "Omokùnrin àti İjàpá"

 Ta ni ó bá omokùnrin yií fenu fa ikun imú rè?

 

Aİjàpá
Bbàbá rè
Cİjòyè
Diyá rè
View Explanation & Discuss
Question 183
waec 2015

İTÀN ÀRÒSO: ÒJ0, O.: İjàpà Tìrókò Oko Yánníbo

Nínú itàn "Omokùnrin àti İjàpá"

 Işé wo ni omokùnrin yií yàn láàyờ?

 

 

Aİlù lílů
BOde síse
CEran sísin
DOrin kiko
View Explanation & Discuss
Question 184
waec 2015

OGBÓN-ÌTOPINPIN LÍTÍRÉSO

"Ájànàkú sùn bí òkè

Erín wó kò le dide..."  

 "Nígbà tí gjó ń pofirí, ó padà pèlú irònú". "Ojó ń pofirí" túmò sí

 

Ailè ń sú lo
Bojúmó ń mó
Còòrùn ti kanrí
Dójó fè ró
View Explanation & Discuss
Question 185
waec 2015

OGBÓN-ÌTOPINPIN LÍTÍRÉSO

"Ájànàkú sùn bí òkè

Erín wó kò le dide..."  

"Ojú gbooro" jé àpeerę

 

Aòwe
Bàló
Cikíni
Dipolówó
View Explanation & Discuss
Question 186
waec 2015

 OGBÓN-ÌTOPINPIN LÍTÍRÉSO

"Ájànàkú sùn bí òkè

Erín wó kò le dide..."  

Sísun ni a máa ń sun ijálá, pípè ni a

Aewi
Bàló
Cèşà
Dòwe
View Explanation & Discuss
Question 187
waec 2015

 OGBÓN-ÌTOPINPIN LÍTÍRÉSO

"Ájànàkú sùn bí òkè

Erín wó kò le dide..."  

'Àjànàkứ àti 'Erin' nínú àyolò yií tóka sí

Aeni ibèrù
Bolórí eranko
Cèniyàn pàtàkì
Deni àimò
View Explanation & Discuss
Question 188
waec 2015

İTUMÒ ÈDĖ

Túmò gbólóhùn  tí ó wà ní ibéèrè yii sí èdė Yorübá

The food is nutritious.

AOúnje náà ládùn.
BOúnje náà sara lóre.
COúnję náà ta sánsán
DOúnje náà fani móra
View Explanation & Discuss
Question 189
waec 2015

İTUMÒ ÈDĖ

Túmò gbólóhùn  tí ó wà ní ibéèrè yii sí èdė Yorübá

Where there is life, there is hope.

ABÍ a bå wà láyé, irètí lè wà
BBí a ò kú, irètí si le wà.
CIbi tí èmí bá wà ni ó nirètí
DBí èmí bá wà, irètí ń bę.
View Explanation & Discuss
Question 190
waec 2015

İTUMÒ ÈDĖ

Túmò gbólóhùn  tí ó wà ní ibéèrè yii sí èdė Yorübá

The road may be  slippery.

AOnà náa lè máa yò.
BOnà náà le ti máa yò.
CÒnà náà ń yò.
DOnà náà máa ń yò
View Explanation & Discuss
Question 191
waec 2015

 

İTUMÒ ÈDĖ

Túmò gbólóhùn  tí ó wà ní ibéèrè yii sí èdė Yorübá

The fear of God is the beginning of wisdom ogbón

 

 

Aİbèrù Olórun ni ipilèsè ogbón
BIbèrů olórun lè jé iberę ogbón
Cİbèrù ti Olórun ni ó bèrè ogbón
Dibèrù fún Olórun ti pilè ogbón
View Explanation & Discuss
Question 192
waec 2015

 GİRÄMÀ

  "Omọdé gbón, àgbà gbón ni a fi dálé Ifệ wú mi lórí jojo"

Aomodé gbon
Bagba gbón
Ctí a fi dálé Ifè
Dwú mi lóri jojo
View Explanation & Discuss
Question 193
waec 2015

 GİRÄMÀ

  Nínú "olůkó ti jáde",  ti jé atóka ibáisèlè  

Aàdáwà
Bbárakú
Catérerę
Dasetán
View Explanation & Discuss
Question 194
waec 2015

 GİRÄMÀ

Ewo ni ó fi ibá-isèle bárakú hàn?

AŞadé ję işu
BSadé máa ň ję işu
CŞadé ti ń je isu
DŞadé a ti máa ję isu
View Explanation & Discuss
Question 195
waec 2015

 GİRÄMÀ

"Yálà Téjú lówó tàbí ko ní, oun ni máa fé." orò-àsopò inú gbólóhùn yií ni

 

AYálà.Tejú
BTejú.lówó
Ctàbí...kò
DYálà..tàbí
View Explanation & Discuss
Question 196
waec 2015

 GİRÄMÀ

"Aso náà fàya" fàya' jé oro-ise

Aàkànmórúko
Beléla
Calápėpadà
Dasèbéèrè
View Explanation & Discuss
Question 197
waec 2015

 GİRÄMÀ

 Bàtà tuntun ni mo wo" tuntun je eyán

 

Aasàpèjủwe
Bajórúko
Casàfihàn
Dasònkà
View Explanation & Discuss
Question 198
waec 2015

ÉTÒ İRO

  Eni tí kò le rin ni à ń pè ní

 

Aarọ
Baro
Càro
D
View Explanation & Discuss
Question 199
waec 2015

ÉTÒ İRO

  Ewo ni isèdá rè je mó ipáje?

 

Aodoodun
BObèelá
COmokómo
DAróoko
View Explanation & Discuss
Question 200
waec 2015

ÉTÒ İRO

 "A ò je" di "A à je" nípasè

Aijeyopò fáwéli
Bàrànmó
Ciyópo fáwéli
D
View Explanation & Discuss
Question Navigator
Current
MathsFaculty