Yoruba Past Questions

Study and practice Yoruba past questions with answers and detailed explanations. Then test your knowledge using our interactive CBT practice platform and prepare confidently for your upcoming examinations.

58 questions JAMB 79 WAEC 794 CUSTOM 1
Download PHP app Ask a Question Check Syllabus Past Question Videos Topic Video Lessons

Take a test

Past Questions

58 questions
Question 1 of 20 58 total questions
Question 11
waec 2011

EWÌ: ABÍMBÓLÁ, w.: Awon Ojú Odù Mérèrìndínlógún (p52 96)

 

Ninu odù "Ogúndá Méji", ta lo difa fun Oðyi òkòkó? 

AOge
BArugbo
COgun omo
DAemole eekan
View Explanation & Discuss
Question 12
waec 2011

EWÌ: ABÍMBÓLÁ, w.: Awon Ojú Odù Mérèrìndínlógún (p52 96)

Nínú odù "Òtúúrúpòn Méi", ta ni bàbá ré fi silè ní rèwerèwe? 

 

ATeleni
BIgbasoro
CAlapaandedę
DOyeepolu
View Explanation & Discuss
Question 13
waec 2011

EWÌ: ABÍMBÓLÁ, w.: Awon Ojú Odù Mérèrìndínlógún (p52 96)

Ta ni "okùnrin kúkúrú òkè Igeti"?

AOgún
BÒòduà
CÒrúnmilà
DObàtálá
View Explanation & Discuss
Question 14
waec 2011

. Ninú itàn "Omokùnrin kan àti Ijàpá" işé wo lomokùnrin náà sọ fún àwọn bí rè pé òun yóò se? 

Aİlù .Lİlù
BOde
COrin kiko
DOnísègùn
View Explanation & Discuss
Question 15
waec 2011

 iTÀN ÀRÒso ÔJo, O.: Ijàpà Tirókò Okọ Yánníbo Ninú tàn "ijàpá àti omobinrin-oba"

Ta ni ó gbégbá orókè nínú işé tí oba gbé fún won? 

AKannakánná
BEkùn
CAsá
DAlákàn
View Explanation & Discuss
Question 16
waec 2011

 iTÀN ÀRÒso ÔJo, O.: Ijàpà Tirókò Okọ Yánníbo Ninú tàn "ijàpá àti omobinrin-oba"

Isé wO ni oba gbé fún gbogbo àwon tí ó féé fé omo rè?

ADíde isà irè
Bkiko ebè işu
Cigi gigùn
DEkùn pipa
View Explanation & Discuss
Question 17
waec 2011

 "Okünrin kóróbótó bí oká"jé àpeere

Aaló
Boriki
Cofo
Dàwitúnwí
View Explanation & Discuss
Question 18
waec 2011

Mo wí wí wí, mo fo fo fo" jé àpeere 

Aiforodárà
Bifohunpèniyån
C. àşorégèé
Dàwitúnwí
View Explanation & Discuss
Question 19
waec 2011

Ewo ni dsipa owe?

AA. Agbàlagbà ki í şe lángbáláńgbắ
BAgbà tó jin sí kòtò, ojú re ló fó
CAgbà letù, omodé lawó
DAgbà tó rofó ikà, omọ rè yóò jẹ níbę
View Explanation & Discuss
Question 20
waec 2011

Tumo gbölóhùn ti ó wà ni ibéère sí èdè Yorùbá 

 He was reluctant to ask for help 

AỞ lora láti béèrè irànlówó
Bó lóra láti béèrè àtiléyin
CÔ sòro fún un láti bèèrè àtiléyin
Dó sòro fún un láti béèrè irànlówó
View Explanation & Discuss
Question 21
waec 2011

 Tumo gbölóhùn ti ó wà ni ibéère sí èdè Yorùbá 

 A good name is better than riches 

AOnuko rere ferę dára ju owó lọ
BOrúko rere ni owó eni
COrúko rere dára ju oro lo
DOrúko rere wùnmí ju orò
View Explanation & Discuss
Question 22
waec 2011

 Tumo gbölóhùn ti ó wà ni ibéère sí èdè Yorùbá 

My father built five houses

 

ABàbá mi ni ó kỏ márùn-ún ninủ ilé wonyí
BBabá mi kó lé márùn-ủn
CBàbả mi fé kó ilé márùn-un
DBàbá mi ń gbiyànjú láti kó lé márùn-un
View Explanation & Discuss
Question 23
waec 2011

"Bộlá ra eja sè je" jé àpeere gbólóhün

Aeléyo oro-ise
Balákànpò
Colóro-ise
Dàsinpo
View Explanation & Discuss
Question 24
waec 2011

 Ewo ni ó ní awé-gbólóhůn àsodorúko?

AA kò mò pé Bùnmi ti dé
BOmo tí a bí lánàá ti ń rin
CSèyí sisé tán kí ó tó gbowó
DOmo náà ń sorò bí eni tí ko jeun kånú
View Explanation & Discuss
Question 25
waec 2011

  Wón je èbà gbigböná. "ebà gbigbóná" jé àpólà

Aise
Bàpèjúwe
Corúko
Datókùn
View Explanation & Discuss
Question 26
waec 2011

Adé lo sí oko. 'si' jé

 

Aoro-àpèjuwe
Bòro-orúko
Coro-àpónlé
Doro-atókùn
View Explanation & Discuss
Question 27
waec 2011

 Bàbá Olú ti dé. Olứ jé èyán 

Aaşàpėjúwe
Bajórúko
Casàfihàn
Daşonkà
View Explanation & Discuss
Question 28
waec 2011

 A sèdá ökúůgbé nípasė 

Afifi àfòmó àárin bo, oro-orúko
Bsise àpètúnpè oro-orúko
Cfif àfomó ibèrệ kun òrò- orúko
Dkikan oro-orúkp méji pò
View Explanation & Discuss
Question 29
waec 2011

"Orí òkéré koko láwo, báa wí fómo eni a gbo", èyí ni gbólóhùn tí ó jáde lénu Àkàndé tí í şe bàbá Àlàó, bí omo rè ti ń japoro ikú lóri ibùsùn ní ilé-iwòsàn Márapé ní ilú Dòho. Alàó jé omọ ilú Ôkè-Egàn. Láti kékeré ni İyápé, iyá Alàó ti bà á jé, nítorí pé ó jé ògúnná kan soso ti ó ní. Gbogbo akitiyan Akàndé ní tító Alàó sónà ló já sí pàbó. Àlàó ń jayé alákátá, ó gbé iwà isekúse wò bí èwù. Bí dúdú ti ń wá, ni pupa ń wá sóodè rè, kódà ó férę lè máa gbé wèrè ni àgbésùn. Ayèwò tí ó lọ şe ni ó fi hàn pé Alàó gbà pé iků yá ju èsín, èyí ni ó mú un gbé májèlé je, èyí ti ó so ó di èrò ilé-iwòsàn.

 

 Ewo ni ki í se orò Yorùbá .

AAgbon
BAgbòn
CÁgbon
DAgbon
View Explanation & Discuss
Question 30
waec 2011

 "Orí òkéré koko láwo, báa wí fómo eni a gbo", èyí ni gbólóhùn tí ó jáde lénu Àkàndé tí í şe bàbá Àlàó, bí omo rè ti ń japoro ikú lóri ibùsùn ní ilé-iwòsàn Márapé ní ilú Dòho. Alàó jé omọ ilú Ôkè-Egàn. Láti kékeré ni İyápé, iyá Alàó ti bà á jé, nítorí pé ó jé ògúnná kan soso ti ó ní. Gbogbo akitiyan Akàndé ní tító Alàó sónà ló já sí pàbó. Àlàó ń jayé alákátá, ó gbé iwà isekúse wò bí èwù. Bí dúdú ti ń wá, ni pupa ń wá sóodè rè, kódà ó férę lè máa gbé wèrè ni àgbésùn. Ayèwò tí ó lọ şe ni ó fi hàn pé Alàó gbà pé iků yá ju èsín, èyí ni ó mú un gbé májèlé je, èyí ti ó so ó di èrò ilé-iwòsàn.

 

 Ami ohün tí ó tonà fún 'Ekun' tí ó jé eranko kan ni

 

AEkún
BEkùn
CÉkún
DÉkún
View Explanation & Discuss
Question Navigator
Current
MathsFaculty