Yoruba Past Questions

Study and practice Yoruba past questions with answers and detailed explanations. Then test your knowledge using our interactive CBT practice platform and prepare confidently for your upcoming examinations.

56 questions JAMB 79 WAEC 794 CUSTOM 1
Download PHP app Ask a Question Check Syllabus Past Question Videos Topic Video Lessons

Take a test

Past Questions

56 questions
Question 1 of 20 56 total questions
Question 11
waec 2012

EWÌ: ABÍMBÓLÁ, W.: Awon Odu Mérèrindinlógún (p52-96)

Nínú "Odù Ogúndá Méji"

 Ta ni a so pé yóò jagbòn obi?

AOrúnmilà
BOjolá
Cijòkùn
DKanranjágbón
View Explanation & Discuss
Question 12
waec 2012

LÍTÍRÉŞO ALOHÙN: iTÀN ÀRÒSO

ÖJO, O.: İjàpà Tirókò Oko Yánníbo Nínú itàn "Ajá àti Ijàpá"

 Nínú itàn "ijàpá àti Awon Eranko, ta ni Baále àwon eranko?

 

AEkùn
BKìnniún
CErin
DEfon
View Explanation & Discuss
Question 13
waec 2012

 

LÍTÍRÉŞO ALOHÙN: iTÀN ÀRÒSO

ÖJO, O.: İjàpà Tirókò Oko Yánníbo Nínú itàn "Ajá àti Ijàpá"

 Ajá so fún jàpá pé kí ó

 

Awa iwònba isu tí ó bá le rù
Bwa isu tí ó le je fün osù kan
Cwa isu púpò
Dmá wà ju isu eyo kan lọ
View Explanation & Discuss
Question 14
waec 2012

 

LÍTÍRÉŞO ALOHÙN: iTÀN ÀRÒSO

ÖJO, O.: İjàpà Tirókò Oko Yánníbo Nínú itàn "Ajá àti Ijàpá"

 Kí ni idí tí orè ijàpá àti Ajá fi wò bée?

AWon joń se egbé kan náà ní
Bİwà won jora
CAlágbára ni àwon méjèèji
DOlóyè ni àwon méjèèji
View Explanation & Discuss
Question 15
waec 2012

LÍTÍRÉŞO oGBÓN-İTỌPINPIN

Ewo ni "àló"?

AÖpá tééré kanlè ó kànrun
BOjó re á dale
CKì í burú títí kó má kenikan móni
D
View Explanation & Discuss
Question 16
waec 2012

LÍTÍRÉŞO oGBÓN-İTỌPINPIN

 Eni gíga ni à ń kì ní

AAgùntásoólò
BAtúnwonká
CAdúmáadán
DAfinjú
View Explanation & Discuss
Question 17
waec 2012

LÍTÍRÉŞO oGBÓN-İTỌPINPIN

"Ó lówó lówó bí sèkèrè" jé

 

Aàfiwé
Bàwítúnwí
Cdídógba
D
View Explanation & Discuss
Question 18
waec 2012

 

LÍTÍRÉŞO oGBÓN-İTỌPINPIN 

Ewo ni ó je àsipa òwe?

 

AOjú méwàá, kò jo ojú eni
B
CBá mi na omo mi, kò dénú olómo
DIlé oba tó jó, ewà ló bù kun
View Explanation & Discuss
Question 19
waec 2012

ITUMO EDE

Túmo gbólóhun tí ó wà ní ibéèrè yin sí èdè Yorùbá

He is trying to know  the matter.

 

AO fe láti mọ orò yen ni àmòjù re
BO ń fé láti mọ àmòjù orò náa
CÓ n gbiyànjú láti mo àtúnbotán òrò náà
Dó n gbiyànjú láti mọ òkodoro orò náà
View Explanation & Discuss
Question 20
waec 2012

ITUMO EDE

Túmo gbólóhun tí ó wà ní ibéèrè yin sí èdè Yorùbá

 I am delighted to hear from you

AInú mi dün áti gbó nipa re
BInú mi dùn láti gbó orò re
CInú mi dùn láti gbó orò tire
DInú mi dùn láti gbúró re
View Explanation & Discuss
Question 21
waec 2012

ITUMO EDE

Túmo gbólóhun tí ó wà ní ibéèrè yin sí èdè Yorùbá

 A word is enough for the wise.

AOrò kan tó fún eni tí ó ti gbón
BOro kan tó fün eni ti ó bá fe gbon
CAbò òrò là á so fömolúwàbi
DAbo oro là ả sọ féni tó bá gbón
View Explanation & Discuss
Question 22
waec 2012

GIRÁMÀ

  "Ayo ti korin". ti je ibá-isele

Aàşetán
Batererę
Caişetán
Dbárakú
View Explanation & Discuss
Question 23
waec 2012

GIRÁMÀ

 "Mo ra iwé fún Gbémi." 'Mo' jé oro- aropò-orúko

Aeni kínní òpo
Beni keji opo
Ceni keji eyo
Deni kínní eyo
View Explanation & Discuss
Question 24
waec 2012

GIRÁMÀ

 İsòrí òrò tí ó máa ń sáájú àpólà orúko nínú àpólà àpónlé ni

Aoro-atókůn
Borò-işe
Coro-àpèjůwe
Dorò-åsopo
View Explanation & Discuss
Question 25
waec 2012

GIRÁMÀ

"Olú n jeun pålàpàlà" 'palàpàlà jé

Aòrò-àpónlé
Bòrò--àpėjúwe
Còrò--atókůn
Dòrò--işe
View Explanation & Discuss
Question 26
waec 2012

GIRÁMÀ

 [o] nínú 'ogbon' jé mofimů

Aàfibò
Bipilè
Càfarahe
Dadádúró
View Explanation & Discuss
Question 27
waec 2012

ÈRÒ İRÓ

 Adako fonetiki faweli 'on' ni

A[c]
B[i]
C[u]
D[EE]
View Explanation & Discuss
Question 28
waec 2012

ÈRÒ İRÓ

Ewo ni ó bả àkotó Yorůbá òde-òní mu?

AWàdí
BWàdi
CWádií
DWáidí
View Explanation & Discuss
Question 29
waec 2012

ÈRÒ İRÓ

"Ará oko" di 'Aróoko' nípasè

Aipaje
Biyópo
Cisúnki
Dàrầnmó
View Explanation & Discuss
Question 30
waec 2012

ÈRÒ İRÓ

 Kí ni bátàni sílébù tó parí 'ipèkun?

AN
BKF
CKFN
DF
View Explanation & Discuss
Question Navigator
Current
MathsFaculty