Yoruba Past Questions

Study and practice Yoruba past questions with answers and detailed explanations. Then test your knowledge using our interactive CBT practice platform and prepare confidently for your upcoming examinations.

63 questions JAMB 79 WAEC 794 CUSTOM 1
Download PHP app Ask a Question Check Syllabus Past Question Videos Topic Video Lessons

Take a test

Past Questions

63 questions
Question 1 of 20 63 total questions
Question 11
waec 2016

ERÉ ONÍSE

ÀJÙWÒN, B.: Irèmojé Eré İşípà Ode

——ni a máa ń sun Irèmòjé

 

AOsàn
B
COru
Dİròlé
View Explanation & Discuss
Question 12
waec 2016

ERÉ ONÍSE

ÀJÙWÒN, B.: Irèmojé Eré İşípà Ode

Örişà wo ni ó ni orin Irèmojé?

 

ASàngó
BOya
CÉŞù
DÖgún
View Explanation & Discuss
Question 13
waec 2016

EWÌ BABALOLÁ, A.: Awon Oriki Orite Métàdínlógbòn (pp.i-166)

  Nínú oriki "iran Olúfe", Ogúnsèrè jé

 

Aomi
Bigi
Cèniyàn
Deranko
View Explanation & Discuss
Question 14
waec 2016

EWÌ BABALOLÁ, A.: Awon Oriki Orite Métàdínlógbòn (pp.i-166)

 Nínú oríki "Iran Öpómúléró", kí ni wón máa ń ję nínú obè?

 

AOrí
BAdin àgbon
CEpo pupa
DYánkò
View Explanation & Discuss
Question 15
waec 2016

EWÌ BABALOLÁ, A.: Awon Oriki Orite Métàdínlógbòn (pp.i-166)

 Nínú oríki "iran Ológbin-in" òòşà idilé won jé

 

Améjidínlógún
Bmétàdínlógún
Cmérindínlógún
Dmárùndínlógún
View Explanation & Discuss
Question 16
waec 2016

 Kí ni egbè orin inú itản "Ilú Awon Eranko"? 

 

 

AAríkíjan
BOba ló dájó àre
CLilú re kín gbó
DPapakůků
View Explanation & Discuss
Question 17
waec 2016

 Nínú itàn "igbín àti japá", ore korikösùn Ijàpá ni

 

AYánníbo
BIgbín
CAbuké Osin
DEsin
View Explanation & Discuss
Question 18
waec 2016

 ITÀN ẢRÒSO AMOÓ, A.: Akójopo Aló Apagbè

——ló so ode di olókikí nínú itän Ajá ode".

 

AOba ilú
BAjá
Cilú
DIşé
View Explanation & Discuss
Question 19
waec 2016

OGBN ITOPINPIN LÍTÍRÉSO 

Ewo ni ki íse onà isowólèdè nínú iwonyi

AOrin
Bİforodárå
Cİforogbeörò
DÀfiwé
View Explanation & Discuss
Question 20
waec 2016

OGBN ITOPINPIN LÍTÍRÉSO 

 Ta.ni àwon àgbà sọ pé ipín àişe máa ń pa?

 

AOlótė
BAláròká
COdàle
D
View Explanation & Discuss
Question 21
waec 2016

OGBN ITOPINPIN LÍTÍRÉSO 

 Onà isowólèdè tó jeyo nínú "Mo wí wí wí, ó faáké kórí" ni

 

Aifohunpèniyàn
Bàwítúnwí
Ciforodárà
Dàsorégeé
View Explanation & Discuss
Question 22
waec 2016

OGBN ITOPINPIN LÍTÍRÉSO 

"Omí ki í sàn kó bojú weyin" jé åpęerę

 

Aiwúre
Bofo
Cèpė
Dèébú
View Explanation & Discuss
Question 23
waec 2016

 Túmo gbólóhůn tí ó wà ní ibéerè sí edè Yorübá.

He excelled in his chosen career.

AO mo isé se dáadáa,
BÓ mókè nínú isé tí ó yàn láäyò.
CÓ máa ń yege nínú èkó re.
DO ti lè şàşeyege lénu íşé re.
View Explanation & Discuss
Question 24
waec 2016

 Túmo gbólóhůn tí ó wà ní ibéerè sí edè Yorübá.

 Labakę is unsteady with her fiancé.

 

ALåbáké kò fi ara bale lódo àfésónà re.
BLabké ń gbon lódo àfésónà re.
CLäbáké ko mọnú ăfésónà rệ.
DLàbáké fi inú méji bá àfésónà rệ lò.
View Explanation & Discuss
Question 25
waec 2016

 Túmo gbólóhůn tí ó wà ní ibéerè sí edè Yorübá.

 The master of the ceremony fumbled.

 

A0 Adarí ètò ayeye náà kùnà.
BOgá etò ayeye náà burú.
CAsáájú ètò àríyá náà faraya.
D0 Olórí èto àríyá náà bínú.
View Explanation & Discuss
Question 26
waec 2016

 

 Túmo gbólóhůn tí ó wà ní ibéerè sí edè Yorübá.

 I love my hometown.

 

AMo moyi ilú mi.
BMo nífeé ilú mi.
CMo gbế ilú mi ga.
DMo gbára lé ilú mi
View Explanation & Discuss
Question 27
waec 2016

GİRÁMÀ

   "lyen ni mo rà". 'mo' nínú gbólóhun yii jé 

 

Aoro-arópò-orúko
BOro-àpejúwe
Coro-àpónlế
Dorò-işe
View Explanation & Discuss
Question 28
waec 2016

GİRÁMÀ

Nínú "Atégun gbé ôrùlé", Atégün' je oro-orúko

 

Aarídimú
Bàfoyemo
Caseékà
Dasoye
View Explanation & Discuss
Question 29
waec 2016

GİRÁMÀ

"İyá Bộlå ń fün omo rè lóyàn". Àpólà- orúko nipò olùwà nínủ gbólóhùn yiỉ ni

 

Aomo
BBộlå
Cİyá Bolá
Domo
View Explanation & Discuss
Question 30
waec 2016

GİRÁMÀ

Nínú Ajá bu bàbả ję", Ajá' jệ

 

Aèpón
Bolùwà
Cèyán
Dàbó
View Explanation & Discuss
Question Navigator
Current
MathsFaculty