Yoruba Past Questions

Study and practice Yoruba past questions with answers and detailed explanations. Then test your knowledge using our interactive CBT practice platform and prepare confidently for your upcoming examinations.

58 questions JAMB 79 WAEC 794 CUSTOM 1
Download PHP app Ask a Question Check Syllabus Past Question Videos Topic Video Lessons

Take a test

Past Questions

58 questions
Question 1 of 20 58 total questions
Question 11
waec 2018

 Ewi: Babalolá, A.: Àwon orikì oríle métàdínlógbòn (pp.iii-116)

 İyá Alááfin òpómúléró ni.

Aİwànù omọ pa- wón-dà
BMorejè n'Murệ
CObàrànbirí
DMóríléwá
View Explanation & Discuss
Question 12
waec 2018

 Ewi: Babalolá, A.: Àwon orikì oríle métàdínlógbòn (pp.iii-116)

Nínú oriki "Ìran opómúléró", ta ni ó lọ sógun tí kò padà mộ? .

AAbímbéşú ,
BAfibirin
CÀbídòrí
DÀfonjá. ,
View Explanation & Discuss
Question 13
waec 2018

LÍTÍRÉŞO ALOHÙN -İTÀN ÀRÒSO Àmoó, A.: Àkójopò Àló Åpagbè
  Nínú itàn "ilệ àti Olórun", ta ni ó gbé èbọ lọ sorun? 

 

Ababaláwo
BOba
Ceyę iğún
Deku emó.
View Explanation & Discuss
Question 14
waec 2018

LÍTÍRÉŞO ALOHÙN -İTÀN ÀRÒSO Àmoó, A.: Àkójopò Àló Åpagbè
Kí ni oba şe fún eni tí ó pa Abuké Oşin?  

Aó pa á
Bó sọ ó doré kòríkòsùn
Có dá a lóla
Dó fún un ní eşin ńlá kan.
View Explanation & Discuss
Question 15
waec 2018

LÍTÍRÉŞO ALOHÙN -İTÀN ÀRÒSO Àmoó, A.: Àkójopò Àló Åpagbè
Nínú "ijapá àti Ajá", ta ni ó pa Abuké Oşin? 

 

AOba
Bigbín
Conilù
Dijàpá
View Explanation & Discuss
Question 16
waec 2018

LÍTÍRÉŞO - OGBÓ N - İTOPINPIN LÍTÉRÉŞO 

Èwo ni ó jé ikíni ?  

Aigbà á ro
Bmá şe fîrú foná
Cojú ló mọ ohun to yonu y8
Dmåá gbéná wojú rẹ.
View Explanation & Discuss
Question 17
waec 2018

LÍTÍRÉŞO - OGBÓ N - İTOPINPIN LÍTÉRÉŞO 

Parí òwe yií: "Láiku Èkiri, enikan kò lè— " .

Ayájú sí i
Bfawo rè şe gbedu
Cfawo rè şeré
Dgbéná wojú rè
View Explanation & Discuss
Question 18
waec 2018

LÍTÍRÉŞO - OGBÓ N - İTOPINPIN LÍTÉRÉŞO 

"Álírá lóra rélá" jé àpęệrę .

Aaló āpamò
Boriki
Corò akónilénu
Dofo
View Explanation & Discuss
Question 19
waec 2018

 Şolá visits once in a blue moon. 

 

ASolá ń şàbèwò lópò igbà
BŞolá lè şàbèwò bóşůpá bá yọ
CŞolá ń şàbèwò léékòòkan
DŞọlả máa ń șàbèwò nínú òşupá.
View Explanation & Discuss
Question 20
waec 2018

Sadé is the apple of her father's eyes.

AŞadé jé aşojú bàbá re
BŞadé jè eyin-lójú bàbá rè
CŞadé jė ápù bàbả rè
DBàbá Şadé jè ápù rè
View Explanation & Discuss
Question 21
waec 2018

Do not cry over spilt milk. 

 

 

Amá sunkún lórí mílîki tó dànù
Bmá bara jé lórí mílfiki tó danu
Cmá bara je lórí ohun tí ko ní åtúnse
Dmá so irètí nù lórí ohun tí kò tí i bàje.
View Explanation & Discuss
Question 22
waec 2018

İTúmo okookan gbólóhùn tí ó wà ibéèrè yii  si èdė Yorůbá.

It serves you right.

 

Aó şe o dáadáa
Bó tójú rẹ tó
Cohun ojú wá lójú ri
Dó pèsè ohun dídára fún o
View Explanation & Discuss
Question 23
waec 2018

GİRÁMÀ

Nínú "orò náà kò şe é gbó séti"a lo 'naa' gégé bí èyán.

Aaşàfihàn
Bajórúkọ
Caşàpėjúwe
Dasònkà.
View Explanation & Discuss
Question 24
waec 2018

GİRÁMÀ

Nínú "Dipò rí mi lánàá" a lo 'mi' gégé bí orò arópò orúko.

 

Aeni kiiní, eyo, nípò olùwà
Beni kiiní, opo, nípò olùwà
Ceni kiní, eyo, nípò àbo
Deni kiní, opo, nípò àbo
View Explanation & Discuss
Question 25
waec 2018

GİRÁMÀ

 Èwo ni a lè fi dí àlàfo  inú gbólóhùn yií? "Omọ obinrin náà pupa "

Atónítóní
Bnini
Cfòò
Dláú.
View Explanation & Discuss
Question 26
waec 2018

GİRÁMÀ

 Nínú "Adé wà ní İbàdàn" oro atókùn ni.

 

AAdé
Bní
Cwà
Dbàdàn.
View Explanation & Discuss
Question 27
waec 2018

GİRÁMÀ

 Ộrò-arópò orúko, enikiíni, àbò, òpò ni

 

Ami
Bmo
Cwon
Dwa
View Explanation & Discuss
Question 28
waec 2018

 GİRÁMÀ

Ipin sí mofîümù "asunsuję" ni.

Aasun-işu-ję
Ba-sun-işu-je
Ca-sunşu-ję
D
View Explanation & Discuss
Question 29
waec 2018

ÈTÒ ÌRÓ

Arànmó iwájú wáyé nínú işèdá

 

Aèkóolé
Bèbèèbá
Codoodún
Daróoko
View Explanation & Discuss
Question 30
waec 2018

ÈTÒ ÌRÓ

 "Ệtù ibọn" di 'ệtùùbon' nípaşè

 

Aijeyopò fáwèli
Bàrànmó
Cànkóò fáwèli
Dipaję
View Explanation & Discuss
Question Navigator
Current
MathsFaculty