Yoruba Past Questions

Study and practice Yoruba past questions with answers and detailed explanations. Then test your knowledge using our interactive CBT practice platform and prepare confidently for your upcoming examinations.

138 questions JAMB 79 WAEC 794 CUSTOM 1
Download PHP app Ask a Question Check Syllabus Past Question Videos Topic Video Lessons

Take a test

Past Questions

138 questions
Question 1 of 20 138 total questions
Question 11
waec 2025

Nínú òríkì "Ìràn Ọ̀rẹ́", kí ni ọkùnrin sọ pé wọ́n wáa gbà ní Okìtì Ẹ̀fọ̀n tí wọ́n kò fi relé mọ́?

AẸ̀jẹ̀
BOwó
CỌbí
DẸni
View Explanation & Discuss
Question 12
waec 2025

Nínú òríkì "Ìràn Ọlópọndá", orúkọ míìràn tí ọkùnrin pé Ìjìmeré ni

AAgánrán
BOlúgbéé
CỌ̀dùgbó
DỌ̀múlùnkú
View Explanation & Discuss
Question 13
waec 2025

Nínú òríkì "Ìràn Ọ̀lá", ta ni Ọ̀làmẹ̀kún bi ọmọ fún?

AOníṣòkùn
BSàájá
COlówu
DErinmọ́jẹ
View Explanation & Discuss
Question 14
waec 2025

Èwo ni owe tí Àdán pa nínú àló "Ìjàpá lo jẹ àsè ní ilé Àdán"?

ABí a bá ń sunkún, a máa rí ran
BÀtigùn là á kọ́ ọmọde, a kì í kọ ní àtisọ́
CAgbà tí kò lẹsẹ̀ ńlẹ̀, ò lógbón lórí
DỌ̀nà dé orí ọpẹ ò pin
View Explanation & Discuss
Question 15
waec 2025

Nínú àló "Ìjàpá àti Àdàbà jọ dá oko kan", ta ni Àdàbà fura sí pé ó ń ṣe iṣẹ́ ibi nínú oko wọn?

AỌ̀lẹ
BAlájọbi
COlódè
DYannibo
View Explanation & Discuss
Question 16
waec 2025

Nínú àló "Ìjàpá àti Ìyà Ẹlẹ̀pà", ta ni ó ran Ìjàpá lọ́wọ́ láti mú èrò ọkàn rẹ̀ ṣẹ?

ABabaláwo
BỌ̀sànyìn
CÒkété
DỌba
View Explanation & Discuss
Question 17
waec 2025

Afẹ̀nilọ́bìnrin kò fojú ire wò ní" jẹ́ àpẹẹrẹ

AÒríkì
BAló
CÌwúre
DÒwè
View Explanation & Discuss
Question 18
waec 2025

Èwo ni ó jẹ́ yọ nínú ayọ̀lọ́ yìí:
"Ọmọ ejò méta; okan n bẹ̀ nídìí ọpẹ, ọ̀kan ń bẹ̀ lẹ́gbẹ̀ẹ̀ ọpẹ, ọ̀kan ń bẹ̀ lórí ọpẹ"?

AẸdá-ọrọ
BAwítúnwí
CIfọ̀ròdára
DÀfíwẹ̀
View Explanation & Discuss
Question 19
waec 2025

Àpẹẹrẹ àṣọ̀régéé ni

AIkú ogun ni í pa akínkanjú
BẸni tí kò rọmọ bí yóò dọlómọ
CLéyìn ogun, ẹyẹ làsán kò fò ní ilú náà
DỌmọ òpó koobiti koobiti
View Explanation & Discuss
Question 20
waec 2025

Ọkùnrin kóróbótó bí oká" jẹ́ àpẹẹrẹ

Aifọ̀hùn pẹ́nìyàn
Bàfíwẹ̀ elélọ́ọ̀
Cgbólóhùn àdógba
Dàfíwẹ̀ tààrà
View Explanation & Discuss
Question 21
waec 2025

ÌTÚMỌ̀ ÈDÈ: Tumo Geesi yi si Yoruba"You do not take serious issues with levity."

AA kì í fojú bọ̀rọ̀ gbọ́mọ lọ́wọ́ ẹ̀kùrọ́
BA k i fi oro pataki fale
CỌ̀rọ̀ kò ní tóbi ká fi obẹ̀ bù ú.
DA kì í dàgbà màá ní aya
View Explanation & Discuss
Question 22
waec 2025

ÌTÚMỌ̀ ÈDÈ: Tumo Geesi yi si Yoruba"It is a case of pot calling the kettle black."

AỌ̀jọ̀ gbogbo ni tòlé, ọjọ́ kan ni tòlóhun.
BÌkòkò dúdú tí dì bọ́gbẹ́.
CṢágo ń bú igò.
DAfáráwẹ̀ kò dára.
View Explanation & Discuss
Question 23
waec 2025

ÌTÚMỌ̀ ÈDÈ: Tumo Geesi yi si Yoruba"No substitute equals the original."

AOdò tó tọjú ẹni kún, kì í gbéni lọ.
BẸ fi eléyìí tí kò tó rọ́pò rẹ̀.
COjú afòó fọ́tán, ìjà ní í dá sílẹ̀.
DOjù méwaá kò jó ojú ẹni.
View Explanation & Discuss
Question 24
waec 2025

ÌTÚMỌ̀ ÈDÈ: Tumo Geesi yi si Yoruba

AÓ wà ní etí odò
BÓ wà ní ibi tí a gbé omi pamọ́ sí.
CÓ wà ní inú odò.
DÓ wà ní ibi tí ó tin dé odò.
View Explanation & Discuss
Question 25
waec 2025

Nínu "Aṣọ funfun báláù wù mí", ọ̀rọ̀ tí a fálà sí nídìí jẹ́...

Aàpólà orúkọ agérí
Bẹyàn àṣàfihàn
Cẹyàn alálájẹ
Dàpónlẹ̀ ẹyàn
View Explanation & Discuss
Question 26
waec 2025

Èwo ni jẹ́ "ọ̀rọ̀ alálájẹ"?

AApótí idẹ
BIgo epo
CTálákà obìnrin
DEnu ọ̀nà
View Explanation & Discuss
Question 27
waec 2025

Ọ̀rọ̀ arọ́pọ̀ orúkọ tí a lè lò gẹ́gẹ́ bí ènìyàn ni...

Aò
Bó
Cwọn
Dwo
View Explanation & Discuss
Question 28
waec 2025

Èwo ni ó ní ọ̀rọ̀-ìṣe agbàbọ̀ nínú ipìlẹ̀ rẹ̀?

Aayẹsí
Bidánwò
Cìròyìn
Dìràsílẹ̀
View Explanation & Discuss
Question 29
waec 2025

Ọ̀rọ̀-orúkọ asọyé ni...

Aeyin
Báná
Cèwo
Dọ̀la
View Explanation & Discuss
Question 30
waec 2025

Oríṣìí ọ̀rọ̀-ìṣe tí ó wà nínú "Bọlá fún mi ní ìwé" ni...

Aàsínpò
Bẹlẹ́là
Calápèpadà
Dagbérún
View Explanation & Discuss
Question Navigator
Current
MathsFaculty