Yoruba Past Questions

Study and practice Yoruba past questions with answers and detailed explanations. Then test your knowledge using our interactive CBT practice platform and prepare confidently for your upcoming examinations.

794 questions JAMB 79 WAEC 794 CUSTOM 1
Download PHP app Ask a Question Check Syllabus Past Question Videos Topic Video Lessons

Take a test

Past Questions

794 questions
Question 1 of 20 794 total questions
Question 221
waec 2014

ARÒKO

Aròko tí ó je mó àwijàreni aröko

Aajemó-isipayá
Basotàn
Clétà kíko
Dasàriyànjiyàn
View Explanation & Discuss
Question 222
waec 2014

ARÒKO

"Oko tó wù mí rà" jé orí-ro fún àroko

Aasotán
Basåpèjúwe
Casariyànjiyàn
Dajemó-isipayá
View Explanation & Discuss
Question 223
waec 2014

llè olóràá tí Elédàá fi jínkí àwon ará abúlé Aşaka ló sọ opolopò won di eni tí ajé ń bá jęun. Şakaşaka ni orúko baba ńlá won ti óti ilú Aperin wá, léyìn tí ó ti kokó tèdó sí abule Omóla.

 Ilè abà yií tí ó dára jé kí nnkan oko won máa se dáradára, şùgbón ầwon olè kò jé ki won ó ri owo tí wón pa ná. Awon ará abà yií náà kò fowó lérán, àwọn géńdé abà yii pin ara won sí egbeegbé ojú-lalákàn-fi-í-sórí. Won a máa jáde ní òru, won a si máa sọ ilú. eni tí ó torí èyí fura si i. Kúrá kì í lọ sí oko olè, àmó òun ló máa ń júwe ilé eni tí ó bải sèşè ta irè-oko fún àwọn apamolékún-jayé. Ojó gbogbo ni tolè, ojó kan soso ni tolóhun. Ní oru ojó kạn owó tẹ diề lára àwon igárá náà, wón si jéwó pé Amòdá jé òkan lára igi- léyin ogbà àwọn. Lógán ni wón lo mú u, b wón si fa òun àti àwon omo-isé rè lé ijoba lówó.

 Akolé tó bả àyokà yií mu jù ni 

Aİso àwon ará Aşaka
BAwon géńdé Asaka
CTite orisirisi dó
D
View Explanation & Discuss
Question 224
waec 2014

llè olóràá tí Elédàá fi jínkí àwon ará abúlé Aşaka ló sọ opolopò won di eni tí ajé ń bá jęun. Şakaşaka ni orúko baba ńlá won ti óti ilú Aperin wá, léyìn tí ó ti kokó tèdó sí abule Omóla.

 Ilè abà yií tí ó dára jé kí nnkan oko won máa se dáradára, şùgbón ầwon olè kò jé ki won ó ri owo tí wón pa ná. Awon ará abà yií náà kò fowó lérán, àwọn géńdé abà yii pin ara won sí egbeegbé ojú-lalákàn-fi-í-sórí. Won a máa jáde ní òru, won a si máa sọ ilú. eni tí ó torí èyí fura si i. Kúrá kì í lọ sí oko olè, àmó òun ló máa ń júwe ilé eni tí ó bải sèşè ta irè-oko fún àwọn apamolékún-jayé. Ojó gbogbo ni tolè, ojó kan soso ni tolóhun. Ní oru ojó kạn owó tẹ diề lára àwon igárá náà, wón si jéwó pé Amòdá jé òkan lára igi- léyin ogbà àwọn. Lógán ni wón lo mú u, b wón si fa òun àti àwon omo-isé rè lé ijoba lówó.

 "Won kò.fowó lérán" túmò sí pé

Awón múra sisé oko
Bwón fi isòro won gun lágídí
Cwón ń sí láti ibị kan sí keji
DWón wá ojútuú sí isòro won
View Explanation & Discuss
Question 225
waec 2014

llè olóràá tí Elédàá fi jínkí àwon ará abúlé Aşaka ló sọ opolopò won di eni tí ajé ń bá jęun. Şakaşaka ni orúko baba ńlá won ti óti ilú Aperin wá, léyìn tí ó ti kokó tèdó sí abule Omóla.

 Ilè abà yií tí ó dára jé kí nnkan oko won máa se dáradára, şùgbón ầwon olè kò jé ki won ó ri owo tí wón pa ná. Awon ará abà yií náà kò fowó lérán, àwọn géńdé abà yii pin ara won sí egbeegbé ojú-lalákàn-fi-í-sórí. Won a máa jáde ní òru, won a si máa sọ ilú. eni tí ó torí èyí fura si i. Kúrá kì í lọ sí oko olè, àmó òun ló máa ń júwe ilé eni tí ó bải sèşè ta irè-oko fún àwọn apamolékún-jayé. Ojó gbogbo ni tolè, ojó kan soso ni tolóhun. Ní oru ojó kạn owó tẹ diề lára àwon igárá náà, wón si jéwó pé Amòdá jé òkan lára igi- léyin ogbà àwọn. Lógán ni wón lo mú u, b wón si fa òun àti àwon omo-isé rè lé ijoba lówó.

Ta ni 'amonişeni"?

ASakasaka
BKàsúmù
CẢmòdá
Dİgárá
View Explanation & Discuss
Question 226

—— ni bàbá ńlá àwon ará Aşaka

AKàsúmù
BÀmòdá
CSakasaka
DIgárá
View Explanation & Discuss
Question 227

Amodá jệ omọ ilú 

AAperin
BAsaka
Cliòkó
D
View Explanation & Discuss
Question 228
waec 2014

Ka àwon àyokà isàlè wònyí, kí o si dáhùn àwon ibéèrè tíó tèlé 

Onirúurú: akékòó ló wà ní ilế-èkó gíga. Ảw on kan wà bí Túndé tó se pé fàáji ni wón wá lo. Awon mífràn bá ifékúfèé ara, lo bí Tóyìn tí wón si ń se é térùn. Awon kan gbájú mó egbé òkůnkü ni tiwon bí Tolả, ti àwon kan si joyè à bắ-n-kúnjo, èyí tí gbogbo èniyàn mo Tele mó. Ki i fé gbé nhkan kan se. Awoh kani ní tiwon bå imò àti iwé kíkà lo, wón sì kà á dójú àmi gégé bí Tádé, tó máa ń fi gbogbo ojó rántí omo eni ti Öun se.

Sé gbogbo ohun tí èdá bá se ló lérè. Léyin odún méta tí gbogbo wonti jáde ilé-ekó giga, Tádé di olůkó påtàki nilé-èkó gíga, ijoba si ń sanwó goboi fún un. Tele ní tirè kò rí ibi kankan bá wò ó nitorí iwé-èrí ti kò múná dóko tóń gbé kiri. Okú Tóiá ní tirè ti fére jerà tán nínú sàréè nipasè ikú gbígbónà tó sàgbákò lódò àwọn akegbé rè. Tóyin ti di eni àpati, ó si rù hán-ń- gógó nítorí ààrùn kògbóògùn tó kó. Bée ni àlsàn kíndinrín ń bá Túndé woyá ijà nilé-iwòsàn nitorí otí åti sigá àmujù rè.

Akolé tó bá àyokà yií mu jù ni

AIkú gbígbóná
BEgbékégbé
Cİkékoógboyè Tlè oló
D
View Explanation & Discuss
Question 229

 Tólá ni ó

Adi olùkó
Bkú ikú gbígbóná
Cjoyè bá-n-kúnjo
Dń se fàáji
View Explanation & Discuss
Question 230

—— ló kó ààrùn kògbóògùn.

ATóyin
BTele
CTúndé
DTólá
View Explanation & Discuss
Question 231
waec 2014

Ka àwon àyokà isàlè wònyí, kí o si dáhùn àwon ibéèrè tíó tèlé òkòòkan won(1-5).

Onirúurú: akékòó ló wà ní ilế-èkó gíga. Ảw on kan wà bí Túndé tó se pé fàáji ni wón wá lo. Awon mífràn bá ifékúfèé ara, lo bí Tóyìn tí wón si ń se é térùn. Awon kan gbájú mó egbé òkůnkü ni tiwon bí Tolả, ti àwon kan si joyè à bắ-n-kúnjo, èyí tí gbogbo èniyàn mo Tele mó. Ki i fé gbé nhkan kan se. Awoh kani ní tiwon bå imò àti iwé kíkà lo, wón sì kà á dójú àmi gégé bí Tádé, tó máa ń fi gbogbo ojó rántí omo eni ti Öun se.

Sé gbogbo ohun tí èdá bá se ló lérè. Léyin odún méta tí gbogbo wonti jáde ilé-ekó giga, Tádé di olůkó påtàki nilé-èkó gíga, ijoba si ń sanwó goboi fún un. Tele ní tirè kò rí ibi kankan bá wò ó nitorí iwé-èrí ti kò múná dóko tóń gbé kiri. Okú Tóiá ní tirè ti fére jerà tán nínú sàréè nipasè ikú gbígbónà tó sàgbákò lódò àwọn akegbé rè. Tóyin ti di eni àpati, ó si rù hán-ń- gógó nítorí ààrùn kògbóògùn tó kó. Bée ni àlsàn kíndinrín ń bá Túndé woyá ijà nilé-iwòsàn nitorí otí åti sigá àmujù rè.

 Akékòó wo ni kò kábámò ihùwàsí re?

ATádé
BTúndé
CTele
DTólá
View Explanation & Discuss
Question 232
waec 2014

Ka àwon àyokà isàlè wònyí, kí o si dáhùn àwon ibéèrè tíó tèlé .

Onirúurú: akékòó ló wà ní ilế-èkó gíga. Ảw on kan wà bí Túndé tó se pé fàáji ni wón wá lo. Awon mífràn bá ifékúfèé ara, lo bí Tóyìn tí wón si ń se é térùn. Awon kan gbájú mó egbé òkůnkü ni tiwon bí Tolả, ti àwon kan si joyè à bắ-n-kúnjo, èyí tí gbogbo èniyàn mo Tele mó. Ki i fé gbé nhkan kan se. Awoh kani ní tiwon bå imò àti iwé kíkà lo, wón sì kà á dójú àmi gégé bí Tádé, tó máa ń fi gbogbo ojó rántí omo eni ti Öun se.

Sé gbogbo ohun tí èdá bá se ló lérè. Léyin odún méta tí gbogbo wonti jáde ilé-ekó giga, Tádé di olůkó påtàki nilé-èkó gíga, ijoba si ń sanwó goboi fún un. Tele ní tirè kò rí ibi kankan bá wò ó nitorí iwé-èrí ti kò múná dóko tóń gbé kiri. Okú Tóiá ní tirè ti fére jerà tán nínú sàréè nipasè ikú gbígbónà tó sàgbákò lódò àwọn akegbé rè. Tóyin ti di eni àpati, ó si rù hán-ń- gógó nítorí ààrùn kògbóògùn tó kó. Bée ni àlsàn kíndinrín ń bá Túndé woyá ijà nilé-iwòsàn nitorí otí åti sigá àmujù rè.

İsòrí akékòó mélòó ni a ménu bà?

AMéji
BMéta
CMárùn-ún
D
View Explanation & Discuss
Question 233
waec 2013

 ÀSÀ

  "Bí oko bá mojú aya tán, alárinà a yèbá" je.mó àşà 

Aişomolórúko
Bisinkú
Cigbéyàwó
Diran-ra-eni-lówó
View Explanation & Discuss
Question 234
waec 2013

 ÀSÀ

 —— jé òkan lára irinşé odę.

ATiróò
Bİlù
CApásá
DOta
View Explanation & Discuss
Question 235
waec 2013

 ÀSÀ

 Ewo ni kì se ara èròjà obè?

AEpo
BIyo
CAta
DEfun
View Explanation & Discuss
Question 236
waec 2013

 ÀSÀ

İran wo ló ni igbá fínfín?

AÅágberí
BOlúfè
COnírèsé
DOlófà
View Explanation & Discuss
Question 237
waec 2013

İPÍN D: ÀSÀ

 "Oba tí dandan rè, kì í sélè" jé ara oríki

AOdùduwà
BSàngó
CÉşù
DOlodùdumàre
View Explanation & Discuss
Question 238
waec 2013

İPÍN D: ÀSÀ

  Ewo ni a ki í fi işu se?

AIyán
BDùndú
Cİpékeré
Dİkókoré
View Explanation & Discuss
Question 239
waec 2013

İPÍN D: ÀSÀ

 Kí ni a máańfi omi-igbín se nínú ilà kíko? 

AErò
BApààgùn
Cipèsè
D
View Explanation & Discuss
Question 240
waec 2013

İPÍN D: ÀSÀ

 Èwo ni kì í se ònà tí a fi ń gba gbèsè ní ayé àtijó?

ADídógò ti onígbèsè
BRírán elemù-ún sí onígbèsè
CDídi owó eyọ ránşé sí onígbèsè
DFifi ejó sun onígbòwó
View Explanation & Discuss
Question Navigator
Current
MathsFaculty