Yoruba Past Questions

Study and practice Yoruba past questions with answers and detailed explanations. Then test your knowledge using our interactive CBT practice platform and prepare confidently for your upcoming examinations.

794 questions JAMB 79 WAEC 794 CUSTOM 1
Download PHP app Ask a Question Check Syllabus Past Question Videos Topic Video Lessons

Take a test

Past Questions

794 questions
Question 1 of 20 794 total questions
Question 231
waec 2013

ERÉ ONÍTÀN: AWÉ, D.: Åpótí Alákàrà

 Isé wo ni ijoba fi ń lo àwọn dó?

 

AAsóbodè
BTíşà
CẢgbè
DBísíneesi
View Explanation & Discuss
Question 232
waec 2013

ERÉ ONÍTÀN: AWÉ, D.: Åpótí Alákàrà

  Ta ni olùdarí ètò ayeyę ikékoógboyè?

 

AOyè
Bİbitóyè
COjògbędę
Dİbikúnlé
View Explanation & Discuss
Question 233
waec 2013

ERÉ ONÍTÀN: AWÉ, D.: Åpótí Alákàrà

Lásúnkànmí ni ó

 

Ań bá Ảńwòó wá işé tíşà
Bjé olórí àwọn àgbà ilé Kàrímù
Cşe ayęye ikékòógboyè
Dgba Åńwòó síşé
View Explanation & Discuss
Question 234
waec 2013

EWİ: OLAYIWOLA, A.: Akòwé kọ wúrà àti àwon ijinlè ảrofò mniiran

Ninú ewì Obìnrin', ohun tí ó máa ń wáyé bí obinrin bá diyàwó tán ni pé won á

 

Amáa ja geerege bíi torí epo pupa
Bmáa jábè
Cní igba ogbón
Dgbàràwò bíi tògá sójà
View Explanation & Discuss
Question 235
waec 2013

EWİ: OLAYIWOLA, A.: Akòwé kọ wúrà àti àwon ijinlè ảrofò mniiran

—— ni ó máa ń fi orí tirè  jàjàagbilà.

 

AElédè
BAgbò
CItú
DEku
View Explanation & Discuss
Question 236
waec 2013

EWİ: OLAYIWOLA, A.: Akòwé kọ wúrà àti àwon ijinlè ảrofò mniiran

 Eranko wo ni ó máa ó fi orí rè lànà níjů?

 

AEku
BItú
CÀgbò
DElédè
View Explanation & Discuss
Question 237
waec 2013

LÍTÍRÉŞO ÀPILÈKO: İTÀN ÀRÒSO

ÈSÓ-OLÚBÓRÒDÉ, S.: Olórunsògo

 —— ni ó lòògùn tí ó ba ilé-omo rè jé.

 

AMúbò
BRónkę
CLolá
DTítí
View Explanation & Discuss
Question 238
waec 2013

LÍTÍRÉŞO ÀPILÈKO: İTÀN ÀRÒSO

ÈSÓ-OLÚBÓRÒDÉ, S.: Olórunsògo

  Ta ni ó mú Rónkę ní olè?

 

ABímbó
BFèyí
CMúbò
DFémi
View Explanation & Discuss
Question 239
waec 2013

LÍTÍRÉŞO ÀPILÈKO: İTÀN ÀRÒSO

ÈSÓ-OLÚBÓRÒDÉ, S.: Olórunsògo

Femí kékòó ní Ifáfiti tó wà nílùú 

 

AIlé- Ifè
Bİbàdàn
COgbómosó
DÔşogbo
View Explanation & Discuss
Question 240
waec 2013

 ERÉ ONÍŞE: ÒGÚNNÍRAN, L.: Eégún Aláré

 

—— ni wòn fĩi je Baálè Arèkú-eégún.

AÖjélàdé
BDúdúyemí
COjèw Lárinnàká
DÖjékúnlé
View Explanation & Discuss
Question 241
waec 2013

 ERÉ ONÍŞE: ÒGÚNNÍRAN, L.: Eégún Aláré

Bàbá Ảńséétù ni

 

AỘjè Lárinnàká
BOjélàdé
CDáşofúnjó
DDúdúyemí
View Explanation & Discuss
Question 242
waec 2013

 ERÉ ONÍŞE: ÒGÚNNÍRAN, L.: Eégún Aláré

 İran Irèmògún omo Àwúsė ni Awúşe

 

ADáşofúnjó
BDúdúyemí
Cİyádùn-únní
DOjè Lárinnàká
View Explanation & Discuss
Question 243
waec 2013

EWÌ: ABÍMBÓLÁ, W.: AWOon Odù Mérèrindínlógún (p52-96)

Nínú "Odù Osà Méji"

 Ninú "Odù İká Méji", kí ni a so sínú ojà lóde İlàká?

 

AAso
BEdun
CAkàrà
Dİkarahun
View Explanation & Discuss
Question 244
waec 2013

EWÌ: ABÍMBÓLÁ, W.: AWOon Odù Mérèrindínlógún (p52-96)

Nínú "Odù Osà Méji"

 Omo Alárá wo ni a dífá fún?  

AÖbítúsi
BAjibolá
CMoníyere
DMóbÓwú
View Explanation & Discuss
Question 245
waec 2013

EWÌ: ABÍMBÓLÁ, W.: AWOon Odù Mérèrindínlógún (p52-96)

Nínú "Odù Osà Méji"

Öpe yèkètè difá nítori

 

Aagbòn ide
B
Cajé
Doriire
View Explanation & Discuss
Question 246
waec 2013

LÍTỈRÉŞÒ ALOHÙN: İTÀN ÀRÒSO

ÒJO, O.: İjàpà Tirókò Oko Yánníbo Nínú itàn "İjàpá àti Erin"

   Ta ló jin sí kòtò?

 

AGéńdé
BErin
CIjàpá
DOnílů
View Explanation & Discuss
Question 247
waec 2013

LÍTỈRÉŞÒ ALOHÙN: İTÀN ÀRÒSO

ÒJO, O.: İjàpà Tirókò Oko Yánníbo Nínú itàn "İjàpá àti Erin"

  İjàpá ni ó

Aşèlérí láti pa òtá lú
Bpe ipàdé gbogbo ilú
Cgbààwè nítorí àtişégun tá
Dń fò tí ó si ń jó
View Explanation & Discuss
Question 248
waec 2013

LÍTỈRÉŞÒ ALOHÙN: İTÀN ÀRÒSO

ÒJO, O.: İjàpà Tirókò Oko Yánníbo Nínú itàn "İjàpá àti Erin"

 ni otá ilú?

AOdę
B
CAjá
DErin
View Explanation & Discuss
Question 249
waec 2013

LÍTÍRÉSÒ OGBÓN-İTOPINPIN LÍTÍRÉSÒ 

 "Oníjà Oòlè, Ejemu Olúwonran A-di-girigiri-rebi-ijà" je

 

Aèébú
Bikín
Coríki
Dèpè
View Explanation & Discuss
Question 250
waec 2013

LÍTÍRÉSÒ OGBÓN-İTOPINPIN LÍTÍRÉSÒ 

"Ó dúdú bí i kóró isin" jé àpeere  

Aàsorégèé
Bàfidípò
Càfiwé
Dàdàpè
View Explanation & Discuss
Question Navigator
Current
MathsFaculty