LÍTÍRÉSÒ OGBÓN-İTOPINPIN LÍTÍRÉSÒ
Irú onà-èdè wo ni a rí nínú àyolà yií?
"İwájú òkun
Okun ni won-ón şe
Eyin Ökun
Okun ni won-ón şe..."
Study and practice Yoruba past questions with answers and detailed explanations. Then test your knowledge using our interactive CBT practice platform and prepare confidently for your upcoming examinations.
Create and set up a CBT environment with your preferred subjects.
Practice JAMB CBT with real UTME past questions in CBT format.
CB-WASSCE styled past question practice.
SSCE & GCE styled past question practice.
LÍTÍRÉSÒ OGBÓN-İTOPINPIN LÍTÍRÉSÒ
Irú onà-èdè wo ni a rí nínú àyolà yií?
"İwájú òkun
Okun ni won-ón şe
Eyin Ökun
Okun ni won-ón şe..."
İTUMO ÈDE
Túmò gbólóhùn tí ó wà ní ibéèrè wòn yí sí èdè Yorùbá
Bola washed our dirty linen in public.
İTUMO ÈDE
Túmò gbólóhùn tí ó wà ní ibéèrè wòn yí sí èdè Yorùbá
It rained cats and dogs in Lagos yesterday.
İTUMO ÈDE
Túmò gbólóhùn tí ó wà ní ibéèrè wòn yí sí èdè Yorùbá
Charity begins at home.
İTUMO ÈDE
Túmò gbólóhùn tí ó wà ní ibéèrè wòn yí sí èdè Yorùbá
You can't have your cake and eat it.
GÍRÁMÀ
"Folá kò féràn oúnje" jé àpeere gbölóhun
GÍRÁMÀ
"Mo mò pé Olùdáħdè mi ń be láyè Awé gbólóhùn wo ni a fålà sídii rè yi?
GÍRÁMÀ
Ewo ni ó ní ibá-isėlè bárakú nínú?
GÍRÁMÀ
"Bùnmi pa ejo." Orò-arópò-orúko tí a le fi rópò 'ejò' ni
GÍRÁMÀ
"Bùkólá féràn emu ogídi." Orò-ise inú gbólóhùn yií ni
GÍRÁMÀ
Oro-orúko tí a fi àpètúnpè elébe sèdá rè ni
ÈTÒ İRÓ
Èwo ni kì í bèrè orò Yorùbá?
ÈTÒ İRÓ
"Rán aşo" di 'ránso' nípasè
ÈTÒ İRÓ
ipín-sí-silébù 'agánnigàn' ni
ÈTÒ İRÓ
Silébù métòó ni ó wà nínú Bèlèntàsé?
ÈTÒ İRÓ
Kóńsónànti akùnyùn ni
ÈTÒ İRÓ
Afipè àsúnsí ni
ÀRÒKO
"Bá mi kí gbogbo ilé" lè jeyo nínú àròko
ÀRÒKO
Orí-òrò wo ló je mó àròko asotàn jů?
ÀRÒKO
'İyá' jé orí-orò fún