Yoruba Past Questions

Study and practice Yoruba past questions with answers and detailed explanations. Then test your knowledge using our interactive CBT practice platform and prepare confidently for your upcoming examinations.

794 questions JAMB 79 WAEC 794 CUSTOM 1
Download PHP app Ask a Question Check Syllabus Past Question Videos Topic Video Lessons

Take a test

Past Questions

794 questions
Question 1 of 20 794 total questions
Question 281
waec 2012

Ohun gbogbo ló ní àsikò tirè. Nígbà tí àsikò tó fún àwon egbeegbé wònyí láti jó kỉ oba ni a sesè tó wå ríran wò. Sé ní ti egbé, wón pò lo súà bỉ olá Olórun: idándè, Omoladé, Ominira, Omóyèlú, Bóbakeye, Ajagungbadé, Obatėkóbò, Qbanibàşírí, Bóbagùnté àti béệ bée lọ. TỈ a bá ní kí a máa to àwon orúko egbé wònyí bí wón şe pò tó, yóð gba odindin ojú-iwé méji níbi tí wón pò dé. Bí oníkálůkù won ti ń jáde lo síwájú Kábíyèsí pèlú èbùn wọn lówó ni àwon òsèré wọn ń lù tèlé won léyìn. Músílíù omo Hárúnà İsòlá ko kísà lórin. Eléré ibílè kan tí won ń pè ní İdàgèrè náà kọ sége lórin. Orí esin funfun ni Jenera Ayinlá wà tó ń korin fún Egbé idándè.

 won'" tí a fàlà sí nídií ń tóka sí

Aoba
Begbé
Cakorin
Dònwòran
View Explanation & Discuss
Question 282
waec 2012

Ohun gbogbo ló ní àsikò tirè. Nígbà tí àsikò tó fún àwon egbeegbé wònyí láti jó kỉ oba ni a sesè tó wå ríran wò. Sé ní ti egbé, wón pò lo súà bỉ olá Olórun: idándè, Omoladé, Ominira, Omóyèlú, Bóbakeye, Ajagungbadé, Obatėkóbò, Qbanibàşírí, Bóbagùnté àti béệ bée lọ. TỈ a bá ní kí a máa to àwon orúko egbé wònyí bí wón şe pò tó, yóð gba odindin ojú-iwé méji níbi tí wón pò dé. Bí oníkálůkù won ti ń jáde lo síwájú Kábíyèsí pèlú èbùn wọn lówó ni àwon òsèré wọn ń lù tèlé won léyìn. Músílíù omo Hárúnà İsòlá ko kísà lórin. Eléré ibílè kan tí won ń pè ní İdàgèrè náà kọ sége lórin. Orí esin funfun ni Jenera Ayinlá wà tó ń korin fún Egbé idándè.

 Ta ló korin fún egbé Idándè?

AJęnera Àyinlá
Bidàgèrè
CHárúnà Işòlá
DMúsílíů
View Explanation & Discuss
Question 283
waec 2012

 ÈDÈ: AKÀYÉ

Ka àwon àyokà isàlè wònyí, kí o si dáhùn àwọn ibéèrè tí ó tèlé okookan won.

BÍ ó tilè jé pé Asàké ni ààyò Délé, Olórun kò tètè yònda omo fún un. İyáálé rè, Ảjoké ti bí isun, iyàwó tí Délé e, Anikè, náà ti bí iwàlė. Awon méjèèji a si máa wo Asàké bí olowó-sibí tó kàn wá bá oko won jeun lasan. Gbogbo igbà ni Délé máa ń gbàdúrà kí Olórun tètè dá Aşàké lóhùn. Iparí osù tí isé pàjáwiri gbé Délé lo sí òkè-òkun ni Àsàké déédéé rí i pé òun ti féra kù! Wéré ló te oko rè láago láti fún un ní ì Kàyéfi ni ó jé fún àwon orogún rè láti rí i ní ipò tó wà, wón si ń fojú ilara wò ó. Osù méfà ni Délé lò léyin odi kí ó tó padà wá sílé. Osù keji tó dé ni Áşàké bímo, omọ náà sì jo Délé bí imumu. Ó so ỏ ní Omoniyi. Aşàké so ó ní Olúwajůwá.

Ayokà yií je mó.

Ailé olórogún
Bsise iròyìn
Cobè síşè
Dşişe iyòhda
View Explanation & Discuss
Question 284

"Kàyééfi" túmò sí .

Ailara
Biyònda
Ciyàlénu
Dayò
View Explanation & Discuss
Question 285

 Aşàké ni ó  

Ajé ààyò Délé
Bjé iyáálé Délé
Cse ilara orogún
Drin irin-àjò
View Explanation & Discuss
Question 286
waec 2012

 ÈDÈ: AKÀYÉ

Ka àwon àyokà isàlè wònyí, kí o si dáhùn àwọn ibéèrè tí ó tèlé okookan won.

BÍ ó tilè jé pé Asàké ni ààyò Délé, Olórun kò tètè yònda omo fún un. İyáálé rè, Ảjoké ti bí isun, iyàwó tí Délé e, Anikè, náà ti bí iwàlė. Awon méjèèji a si máa wo Asàké bí olowó-sibí tó kàn wá bá oko won jeun lasan. Gbogbo igbà ni Délé máa ń gbàdúrà kí Olórun tètè dá Aşàké lóhùn. Iparí osù tí isé pàjáwiri gbé Délé lo sí òkè-òkun ni Àsàké déédéé rí i pé òun ti féra kù! Wéré ló te oko rè láago láti fún un ní ì Kàyéfi ni ó jé fún àwon orogún rè láti rí i ní ipò tó wà, wón si ń fojú ilara wò ó. Osù méfà ni Délé lò léyin odi kí ó tó padà wá sílé. Osù keji tó dé ni Áşàké bímo, omọ náà sì jo Délé bí imumu. Ó so ỏ ní Omoniyi. Aşàké so ó ní Olúwajůwá.

. 'Féra kừ túmò sí ?

Alóyún
Brin irin-àjò
Cbímo
Dmọ obè í şè
View Explanation & Discuss
Question 287

 Kí ni ó gbé Délé lo sí òkè-òkun?

AAájo omo
BIşé pàjáwiri
Cİròyin ayò
Dİpè orí aago
View Explanation & Discuss
Question 288
waec 2011

Ewo ni obìnrin nínú àwon wònyí? 

AApènà
BAjànà
COlúwo
DErelú
View Explanation & Discuss
Question 289
waec 2011

 "Ìka tó bá sè loba ń gé" je mó àsà

Aòràn dídá àti ijiyà
Bikíni àti ibòw fágbà
Ciranraenilówó
Dogún pinpín
View Explanation & Discuss
Question 290
waec 2011

Ewo ni odún ibilè? 

Aodún kérési
Bodún itúnu ààwè
Codún Osun Osogbo
Dodún àjíñde
View Explanation & Discuss
Question 291
waec 2011

Eni ti ó seni ní idí bàbá tàbí iyá ni.

Aalábàárò eni
Biserun eni
Colówó eni
Diwòfà eni
View Explanation & Discuss
Question 292
waec 2011

PÍN D: À

 Bi a bả fi osùn ránsé sí èniyàn, ó túmo si pẻ  rè ti bím

Aó léjó láti jé
Bòré re kan ti kú
Coba ń pè é
Daboyún rè ti bímo
View Explanation & Discuss
Question 293
waec 2011

PÍN D: ÀSA

 Aláboyún kò gbódò rin lósàn-án jé eewo

Aaàbò
Bimótótó
Cèsin
D
View Explanation & Discuss
Question 294
waec 2011

Àbèó İPÍN D: ÀSA

Ewo nínú àwon wònyí ni ó jé iwà rere?

AIfaradà
BOfófó
COlè
Dimele
View Explanation & Discuss
Question 295
waec 2011

Àbèó İPÍN D: ÀSA

 Ilepa je yo nínú àsà

Aigbéyàwó
Bisomolórúko
Ciranraenilówó
Disinkú
View Explanation & Discuss
Question 296
waec 2011

ERÉ ONÍTAN: Awé, D.: Ápótí Alákàrà

........ni iyàwó Kàrímù

ASèrí
BAńwòó
CAlàké
DÀbèó
View Explanation & Discuss
Question 297
waec 2011

ERÉ ONÍTAN: Awé, D.: Ápótí Alákàrà

"Rèi, làwon okùnrin ń dà léyin rè bí àgbébò adię olómọ yoyo". 

AAńwòó
BAbèó
CAàké
DŞèrí
View Explanation & Discuss
Question 298
waec 2011

ERÉ ONÍTAN: Awé, D.: Ápótí Alákàrà

Ta ni alága nibi ayeyę ikékòó-gboyè Arówólò?

AKàrímù
BOyè
CÖjògbede
D
View Explanation & Discuss
Question 299
waec 2011

 EWİ: LAYIWOLA, A.: Akòwé i wúrà àti àwon ijinlè àròfo miíràn

Ninú ewi "òle ", akéwi so pé òle kò nisé sùgbon ole ni

Aariwo enu
Bako ajá
Cojú àánú
Doko lójúde
View Explanation & Discuss
Question 300
waec 2011

 EWİ: LAYIWOLA, A.: Akòwé i wúrà àti àwon ijinlè àròfo miíràn

 Nínú ewi "Akowé ko wúà", kí ni akéwi fi ikojúsíni alákòwé wé?

AAko irè
Bobe òsikí
COde etilé
DEyin díndín
View Explanation & Discuss
Question Navigator
Current
MathsFaculty