ÉTO IRO
Fáwéi tí a fi àigbésókè àfásé pè ni
Study and practice Yoruba past questions with answers and detailed explanations. Then test your knowledge using our interactive CBT practice platform and prepare confidently for your upcoming examinations.
Create and set up a CBT environment with your preferred subjects.
Practice JAMB CBT with real UTME past questions in CBT format.
CB-WASSCE styled past question practice.
SSCE & GCE styled past question practice.
ÉTO IRO
Fáwéi tí a fi àigbésókè àfásé pè ni
ÉTO IRO
[o) jé fáwél
ARÒKO
A ki í ko létà gbefé sí
ARÒKO
Ewo ló je mó àroko asåríyànjiyan?
ARÒKO
Aròko tí ó je mó àwijàreni aröko
ARÒKO
"Oko tó wù mí rà" jé orí-ro fún àroko
llè olóràá tí Elédàá fi jínkí àwon ará abúlé Aşaka ló sọ opolopò won di eni tí ajé ń bá jęun. Şakaşaka ni orúko baba ńlá won ti óti ilú Aperin wá, léyìn tí ó ti kokó tèdó sí abule Omóla.
Ilè abà yií tí ó dára jé kí nnkan oko won máa se dáradára, şùgbón ầwon olè kò jé ki won ó ri owo tí wón pa ná. Awon ará abà yií náà kò fowó lérán, àwọn géńdé abà yii pin ara won sí egbeegbé ojú-lalákàn-fi-í-sórí. Won a máa jáde ní òru, won a si máa sọ ilú. eni tí ó torí èyí fura si i. Kúrá kì í lọ sí oko olè, àmó òun ló máa ń júwe ilé eni tí ó bải sèşè ta irè-oko fún àwọn apamolékún-jayé. Ojó gbogbo ni tolè, ojó kan soso ni tolóhun. Ní oru ojó kạn owó tẹ diề lára àwon igárá náà, wón si jéwó pé Amòdá jé òkan lára igi- léyin ogbà àwọn. Lógán ni wón lo mú u, b wón si fa òun àti àwon omo-isé rè lé ijoba lówó.
Akolé tó bả àyokà yií mu jù ni

"Won kò.fowó lérán" túmò sí pé

Ta ni 'amonişeni"?

—— ni bàbá ńlá àwon ará Aşaka

Amodá jệ omọ ilú
Ka àwon àyokà isàlè wònyí, kí o si dáhùn àwon ibéèrè tíó tèlé
Onirúurú: akékòó ló wà ní ilế-èkó gíga. Ảw on kan wà bí Túndé tó se pé fàáji ni wón wá lo. Awon mífràn bá ifékúfèé ara, lo bí Tóyìn tí wón si ń se é térùn. Awon kan gbájú mó egbé òkůnkü ni tiwon bí Tolả, ti àwon kan si joyè à bắ-n-kúnjo, èyí tí gbogbo èniyàn mo Tele mó. Ki i fé gbé nhkan kan se. Awoh kani ní tiwon bå imò àti iwé kíkà lo, wón sì kà á dójú àmi gégé bí Tádé, tó máa ń fi gbogbo ojó rántí omo eni ti Öun se.
Sé gbogbo ohun tí èdá bá se ló lérè. Léyin odún méta tí gbogbo wonti jáde ilé-ekó giga, Tádé di olůkó påtàki nilé-èkó gíga, ijoba si ń sanwó goboi fún un. Tele ní tirè kò rí ibi kankan bá wò ó nitorí iwé-èrí ti kò múná dóko tóń gbé kiri. Okú Tóiá ní tirè ti fére jerà tán nínú sàréè nipasè ikú gbígbónà tó sàgbákò lódò àwọn akegbé rè. Tóyin ti di eni àpati, ó si rù hán-ń- gógó nítorí ààrùn kògbóògùn tó kó. Bée ni àlsàn kíndinrín ń bá Túndé woyá ijà nilé-iwòsàn nitorí otí åti sigá àmujù rè.
Akolé tó bá àyokà yií mu jù ni

Tólá ni ó

—— ló kó ààrùn kògbóògùn.
Ka àwon àyokà isàlè wònyí, kí o si dáhùn àwon ibéèrè tíó tèlé òkòòkan won(1-5).
Onirúurú: akékòó ló wà ní ilế-èkó gíga. Ảw on kan wà bí Túndé tó se pé fàáji ni wón wá lo. Awon mífràn bá ifékúfèé ara, lo bí Tóyìn tí wón si ń se é térùn. Awon kan gbájú mó egbé òkůnkü ni tiwon bí Tolả, ti àwon kan si joyè à bắ-n-kúnjo, èyí tí gbogbo èniyàn mo Tele mó. Ki i fé gbé nhkan kan se. Awoh kani ní tiwon bå imò àti iwé kíkà lo, wón sì kà á dójú àmi gégé bí Tádé, tó máa ń fi gbogbo ojó rántí omo eni ti Öun se.
Sé gbogbo ohun tí èdá bá se ló lérè. Léyin odún méta tí gbogbo wonti jáde ilé-ekó giga, Tádé di olůkó påtàki nilé-èkó gíga, ijoba si ń sanwó goboi fún un. Tele ní tirè kò rí ibi kankan bá wò ó nitorí iwé-èrí ti kò múná dóko tóń gbé kiri. Okú Tóiá ní tirè ti fére jerà tán nínú sàréè nipasè ikú gbígbónà tó sàgbákò lódò àwọn akegbé rè. Tóyin ti di eni àpati, ó si rù hán-ń- gógó nítorí ààrùn kògbóògùn tó kó. Bée ni àlsàn kíndinrín ń bá Túndé woyá ijà nilé-iwòsàn nitorí otí åti sigá àmujù rè.
Akékòó wo ni kò kábámò ihùwàsí re?
Ka àwon àyokà isàlè wònyí, kí o si dáhùn àwon ibéèrè tíó tèlé .
Onirúurú: akékòó ló wà ní ilế-èkó gíga. Ảw on kan wà bí Túndé tó se pé fàáji ni wón wá lo. Awon mífràn bá ifékúfèé ara, lo bí Tóyìn tí wón si ń se é térùn. Awon kan gbájú mó egbé òkůnkü ni tiwon bí Tolả, ti àwon kan si joyè à bắ-n-kúnjo, èyí tí gbogbo èniyàn mo Tele mó. Ki i fé gbé nhkan kan se. Awoh kani ní tiwon bå imò àti iwé kíkà lo, wón sì kà á dójú àmi gégé bí Tádé, tó máa ń fi gbogbo ojó rántí omo eni ti Öun se.
Sé gbogbo ohun tí èdá bá se ló lérè. Léyin odún méta tí gbogbo wonti jáde ilé-ekó giga, Tádé di olůkó påtàki nilé-èkó gíga, ijoba si ń sanwó goboi fún un. Tele ní tirè kò rí ibi kankan bá wò ó nitorí iwé-èrí ti kò múná dóko tóń gbé kiri. Okú Tóiá ní tirè ti fére jerà tán nínú sàréè nipasè ikú gbígbónà tó sàgbákò lódò àwọn akegbé rè. Tóyin ti di eni àpati, ó si rù hán-ń- gógó nítorí ààrùn kògbóògùn tó kó. Bée ni àlsàn kíndinrín ń bá Túndé woyá ijà nilé-iwòsàn nitorí otí åti sigá àmujù rè.
İsòrí akékòó mélòó ni a ménu bà?