ÉTÒ İRO
Eni tí kò le rin ni à ń pè ní
Study and practice Yoruba past questions with answers and detailed explanations. Then test your knowledge using our interactive CBT practice platform and prepare confidently for your upcoming examinations.
Create and set up a CBT environment with your preferred subjects.
Practice JAMB CBT with real UTME past questions in CBT format.
CB-WASSCE styled past question practice.
SSCE & GCE styled past question practice.
ÉTÒ İRO
Eni tí kò le rin ni à ń pè ní
ÉTÒ İRO
Ewo ni isèdá rè je mó ipáje?
ÉTÒ İRO
"A ò je" di "A à je" nípasè
ÉTÒ İRO
"Gbangbalàsáata " jé orò onísilébů
ÉTÒ İRO
Fáwéli èbákè ni a tún ń pè ní fáwéli
ÀRÒKO
"Emi ni tiyín ní tòótó", ń je yo nínú àróko
ÀRÒKO
"Omo beere, òsi beere", jé àpeere ori orò fún àròko
ÀRÒKO
Aròko tíỏ je mó isèlè ojúkorojú ni àròko
ÀRÒKO
Eni tí a lè ko létà àigbagbèfé sí ni
Akolé tí ó bả àyokà yií mu jù ni
Olálérè ni ?.
— ni àbígbèyin Iyábo.
Ta ni ó fé İyábò fún Olálérè?
"Gbogbo ayé ló ti rò ó pin". Ta ni "ó" tóka sí ninú àyokà yii?
Akolé tó bả àyokà yií mu jù ni ?
— ni àbúrò bàbá Fadékémi.
Ibo ni Dékúnlé ti pàdé Fadékémi?
Işệ wo ni Fadékémi kókó se?
ÈDĖ: AKÀYÉ
Ka àwon àyokà isàlệ wònyí, kí o si dáhùn àwọn ibéèrè tí ó tèlé òkookan won (1-10)
. Fadékémi jé omo òrukàn tí ó si rewà lóbinrin. Láti kékeré ni ó ti ń wè nínú iyà. Ó ń gbé lódo
Adébáyo,.àbúro babá rè. eni ti o fi iyà pá a lóri doba. títí tí ó fi sá kúro níbè. ilú Aráròmí ni o så lo ni ó ti di aláàárù. Ô tun. dán isé aponmità wó , béè ló tún sisé. omoódó lódo Amòpé Oloúnje. sùgbón Sugbón.kåkà ki ewé àgbon rè rò. lile ló n le sí i.
idi isé bírisopé tí ó tún lọ : se ni Dékúnlé omooba ti pàdé rè, tí ewà rè si wò ó lóju. ó bá a soro, oro won si wo. Dékúnlé wá. bóso iyà lárarè. ó si sọ ó di iyàwó. Báyií ni orúko ro o Fadékémi. Ô di okan ninúủ iyàwó olór ilú, ó si bèrè sí ní yí ninú olá.ninú olá.
Léyin ogún odún tí Abèní ti wolé oko ni ó tó rómo bí. Ó ti relé aláwo, relé onísègùn fún òpòlopò odún. Gbogbo Aàfáà tí ó gbúròó agbára won ni ó ti dàn wò pátá. Kódà, àimoye osù ni ó ti lo lábé ààbò orísirísi wolii. sibè pàbó ni gbogbo rè já sí. ò ti so. irètí nù. pátápátá, Gbogbo ayé ni o ti ró o pin. Àwèní iyá oko rè gbàgbó pé okùnrin ki í yàgàn, Éyí ni ó mú un fé iyàwó miíràn fún omo rè. dún keji tí iyàbó wolé olálérè ni o bị Adétólá, ó si tún bí Gbóláhàn àti Dàmólá ni tàléntàlé.
Nitorí.pé.ile àánú.Olórun ki í sú.léyin ogún. odún ti.Ábèní ti wolé. oko..Olórun. dá a lóhùn. Ole.ayo.so. nínú re. Ibęta ni ó si fi oyún náà bí.
Ta ni ó ń ji yà láti kékeré rè?