ÈTÒ ÌRÓ
Olóòót6' jé òrò onísilébù
Study and practice Yoruba past questions with answers and detailed explanations. Then test your knowledge using our interactive CBT practice platform and prepare confidently for your upcoming examinations.
Create and set up a CBT environment with your preferred subjects.
Practice JAMB CBT with real UTME past questions in CBT format.
CB-WASSCE styled past question practice.
SSCE & GCE styled past question practice.
ÈTÒ ÌRÓ
Olóòót6' jé òrò onísilébù
ÈTÒ ÌRÓ
Fáwẹ̀lì aránmúpẹ̀, àyanudìẹ̀pẹ̀, robọ́tò ni.
ÈTÒ ÌRÓ
Kóńsónàhtì àfàfàşé pé ni
ÈTÒ ÌRÓ
Èwo ni ó lè so iró di aránmúpė?
ÀRÒKO
Déèti kíko pọn dandan nínú àröko
ÀRÒKO
"Işé olůkó" ję mó orí ro fún àròko
ÀRÒKO
Ewo ni ó je mó àròko asàríyànjiyàn?
ÀRÒKO
"Ayęye igbéyàwó kan tí ó sojú mi" ję àpęęrę orí òrò fún àròko
Åkolė tŕ ó bá àyòká yii mu jùlo ni
Ohun tí ó je Adéagbo lógún ni
Traka nínú àyòká yií túmo sí
Akóbí idíle yíí ni ó di.
Ka àyokà isàlè wònyii, kí o sì dáhùn àwon ibéèrè tí ó tèlé òkòòkan won.
Ojó mánigbàgbé, ojó ayò, lójó ti Adétutù gbé Adéagbo àti Ajibikèé tí wón jé òbí rè lo sí ilú oyinbó. Awon méjèèji si fopé fún Olorun pé àwon ti ipase omọ là.
Wón kò bả olá nílé şùgbón èkó àwon omo won je wón lògún Wón tiraka láti rán àwon omo won nílé èko. Âwon omọ náà sì kàwé yanjú. Akíntòmídé, àkóbí won, di ògá onímò èrọ. Adétutů gba oyè imo ijinlè nínú işé iségun: Olúwaşeun di Omowé nínú isé olůkoni. Abiímbolá, àbikéyin won yan işé nóosi láàyò. Oun nikan ni ó ń şişé ní orilè èdè Nàijíríà. Àwon yà yòókù si fi Okè Ökun şe ibùgbé. BÍ Adéagbo àti Ajibíkėé, iyàwó rè şe padà sí orílè èdè Nàijíríà, ilé tí Abímbolá kó fún won ni wón dé sí. Motò obokùn olóyé tí Olúwaşeun rà fún wọn ni ó wá gbé wọn ní pápáko ofurufú.
—— ni ó ń şişè ní orile èdè Nåijiriä?
İmòràn tí a fún Şàngó ni pé kí ó
Orúko iyá Şàngó ni
Timi Àgbàlé àti gbonkaaebiri
—— ni iyá Şàngó ni féràn jů
Ka àyokà isàlè wònyii, kí o sì dáhùn àwon ibéèrè tí ó tèlé òkòòkan won.
İtàn àbláyé so pé Oba ni Şàngó lóde Oyó nígbà ayé rè. Omo İlú Tápà ti Elénpe ni Torosí iyá rè. Àwọn iyàwó métèèta tí Şàngó fé ni wón di odò léyiìn ikú won: Oya bíņú di odo Oya, Obà di odò Obà tí ó la İwổ kòja Sun sì di odò Oşun tí ó la Òsogbo kojá, Aágbára ni Şàngó, ó láyà, ó sì lóògùn débi pé ó máa ń yoná lénu bí inú bá ń bí i, Éyi mủ kí èrù rè máa bá tẹrú tọmọ láşikò náà. lóde Òyó tó, Tìmì Ágbàlé àti Gbòńkáà Ebiri. tí won si jé kí inú Şàngó dun rárá. ó forò náà tó Oya tí ó jé ààyò rè létí. ya si gbà á nímoràn láti wá onà tí yóò fi yęjú àwon méjèèji.he
Ohun ti ó mú erù Sàngó bả âwon ará ilú ni pé Ú.