"E rò wá ro ire o." Oro tí a fålà sí nídií jé oro-işe
Yoruba Past Questions
Study and practice Yoruba past questions with answers and detailed explanations. Then test your knowledge using our interactive CBT practice platform and prepare confidently for your upcoming examinations.
Take a test
Custom CBT
Create and set up a CBT environment with your preferred subjects.
JAMB CBT Simulator
Practice JAMB CBT with real UTME past questions in CBT format.
WAEC CBT Practice 2026 Simulator
CB-WASSCE styled past question practice.
NECO CBT Practice 2026 Simulator
SSCE & GCE styled past question practice.
Past Questions
794 questions"Wón tan iná sinú ilé, ó mó roro" 'roro' jé
GÍRÁMÀ
Ewo ni ó je mó isàmúlò àfòmó?
Oro àyálò afetiy á ni
Ewo ni àrànmó wáyé nínú isèdá rè?
İpín sí silébuęleméèsi ni
Ojó kan soşo òjò a máa borí òdá. Láipé Ajéwolá gbàgbé pé igbà kan wà rí tí Tóórera iyàwó òun jé àgàn ti ó ń fowó osùn nu ògiri gbígbeę, tí ó n , ń rómo léyìn adię, tí ó b puru sékún, tí àwon ń fojoojúmó sèráhùn omo. Nígbà tí ó yá omo wá pò lóodè rè, òrò rè gbogbo si dayò. Ó ti kúrò nínú o-lóńje-nilé-fi-túlààsi-gbààwè. Kò máa rù hangogo bí alágęemọ. Kò sì máa mì tíétíé bí olókůnrùn mó. Ó kúrò nínú à ń mu hàntúrú, à ń ya ojúlé ààfáà àti adáhunse kiri. Adùn sì wá gbèyin ewúro fún un
Kónsónánti àfàfàséfètèpè ni--
Ojó kan soşo òjò a máa borí òdá. Láipé Ajéwolá gbàgbé pé igbà kan wà rí tí Tóórera iyàwó òun jé àgàn ti ó ń fowó osùn nu ògiri gbígbeę, tí ó n , ń rómo léyìn adię, tí ó b puru sékún, tí àwon ń fojoojúmó sèráhùn omo. Nígbà tí ó yá omo wá pò lóodè rè, òrò rè gbogbo si dayò. Ó ti kúrò nínú o-lóńje-nilé-fi-túlààsi-gbààwè. Kò máa rù hangogo bí alágęemọ. Kò sì máa mì tíétíé bí olókůnrùn mó. Ó kúrò nínú à ń mu hàntúrú, à ń ya ojúlé ààfáà àti adáhunse kiri. Adùn sì wá gbèyin ewúro fún un.
------- máa ń jé igbése keta nínú létà àigbagbèfé
Ojó kan soşo òjò a máa borí òdá. Láipé Ajéwolá gbàgbé pé igbà kan wà rí tí Tóórera iyàwó òun jé àgàn ti ó ń fowó osùn nu ògiri gbígbeę, tí ó n , ń rómo léyìn adię, tí ó b puru sékún, tí àwon ń fojoojúmó sèráhùn omo. Nígbà tí ó yá omo wá pò lóodè rè, òrò rè gbogbo si dayò. Ó ti kúrò nínú o-lóńje-nilé-fi-túlààsi-gbààwè. Kò máa rù hangogo bí alágęemọ. Kò sì máa mì tíétíé bí olókůnrùn mó. Ó kúrò nínú à ń mu hàntúrú, à ń ya ojúlé ààfáà àti adáhunse kiri. Adùn sì wá gbèyin ewúro fún un
Aròko wo ni èniyàn méji ti máa ń sòro ní síşè-n-tèlé?
Ojó kan soşo òjò a máa borí òdá. Láipé Ajéwolá gbàgbé pé igbà kan wà rí tí Tóórera iyàwó òun jé àgàn ti ó ń fowó osùn nu ògiri gbígbeę, tí ó n , ń rómo léyìn adię, tí ó b puru sékún, tí àwon ń fojoojúmó sèráhùn omo. Nígbà tí ó yá omo wá pò lóodè rè, òrò rè gbogbo si dayò. Ó ti kúrò nínú o-lóńje-nilé-fi-túlààsi-gbààwè. Kò máa rù hangogo bí alágęemọ. Kò sì máa mì tíétíé bí olókůnrùn mó. Ó kúrò nínú à ń mu hàntúrú, à ń ya ojúlé ààfáà àti adáhunse kiri. Adùn sì wá gbèyin ewúro fún un
"Ékó ilé" jé orí-òrò fún àròko

Orí-òrò tí ó je mó àròko asàpèjúwe ni

.....niwón şe aájo fun?

Adùn tí ó gbèyin ewúro ni

"Ìgbà òdá" toka sí igbà

TA ni àgàn nígbà kan rí?
ÈDĖ: AKÀYÉ
Ka àwon àyokà isàlè wònyí, kí o si dáhùn àwon ibéèrè tí ó tèlé òkòòkan won. Ori yeye ní mògún, tàişe ló po. Idògbé omo Mèmúnà ará İlórò, sèsè ti ibi işé dé ní iròlé ojó yií. Ó jókòo'sí ita láti retí Jókòótadé omo àbúro bàbá rè, tí ó rán ní àkàrà, èyí tí yóò fi je èko. Jéjéniwà ni àbúrò bàbá idògbé. Àti pínníşín ni ó ti gba Idògbé móra, tí ó si fi sí enu ikósé mékániki nigbà tí ó pé omo odún métàlá. İdògbé já fáfá lénu ikósé, ki í pa ibi isé je, tègàn ni hèe. Omọ tó şeé mú yagàn ni. Ní ojó burúkú èşù gbomi mu yií, jijòkòó tí Idògbé jòkòó sí ita pèlú aşo işé re ti o dotí kojá ààlà, ni ó sokùnfà kíkó tí àwon olópàá kó o mó àwọn elégiri tí ó sosé ní àdúgbò keji. Kí a tó şéjú pé, İdogbé ti bá ara rè ní àtimolé olópàá
Òrò tí a le fi dipò 'pinnísín' nínú àyokà yii ni
ÈDĖ: AKÀYÉ
Ka àwon àyokà isàlè wònyí, kí o si dáhùn àwon ibéèrè tí ó tèlé òkòòkan won. Ori yeye ní mògún, tàişe ló po. Idògbé omo Mèmúnà ará İlórò, sèsè ti ibi işé dé ní iròlé ojó yií. Ó jókòo'sí ita láti retí Jókòótadé omo àbúro bàbá rè, tí ó rán ní àkàrà, èyí tí yóò fi je èko. Jéjéniwà ni àbúrò bàbá idògbé. Àti pínníşín ni ó ti gba Idògbé móra, tí ó si fi sí enu ikósé mékániki nigbà tí ó pé omo odún métàlá. İdògbé já fáfá lénu ikósé, ki í pa ibi isé je, tègàn ni hèe. Omọ tó şeé mú yagàn ni. Ní ojó burúkú èşù gbomi mu yií, jijòkòó tí Idògbé jòkòó sí ita pèlú aşo işé re ti o dotí kojá ààlà, ni ó sokùnfà kíkó tí àwon olópàá kó o mó àwọn elégiri tí ó sosé ní àdúgbò keji. Kí a tó şéjú pé, İdogbé ti bá ara rè ní àtimolé olópàá.
Ta ni Idògbé rán nísé?

. Itumò 'elégíri ni ?

. Ta ni ó fi àjèbi sun àtimólé?
Orúko miíràn fún 'aba' ni