Yoruba Past Questions

Study and practice Yoruba past questions with answers and detailed explanations. Then test your knowledge using our interactive CBT practice platform and prepare confidently for your upcoming examinations.

794 questions JAMB 79 WAEC 794 CUSTOM 1
Download PHP app Ask a Question Check Syllabus Past Question Videos Topic Video Lessons

Take a test

Past Questions

794 questions
Question 1 of 20 794 total questions
Question 351
waec 2009

 EWİ ALOHÙN: ABÍMBOLÁ, w.: ÀWọn Ojú Odù Mérèèrindinlógún

Orisà tí Ifá so pé ó soroo bè nínú Odù "ikå Méji"ni 

AŞàngó
BEégún
CEsù
DAgbonmirègún
View Explanation & Discuss
Question 352
waec 2009

 Ta ni ó yo Ijàpá àti àwon ará ilú nínú wàhálà náà?

ABabaláwo
BOba
Ckété
Digbin
View Explanation & Discuss
Question 353
waec 2009

 Eran wo ló dá wàhálà sílè? 

AÉèmò
BAgbònrín
CTúüpú
DÖyà
View Explanation & Discuss
Question 354
waec 2009

LİTİRÉSò ALOHÙN: ITÀN ABÁLÁYE:

ÖJ0, 0.: İjàpà Tirókò Oko Yánníbo

Nínú itàn "lgbin àti ljäpá"

 Eran wo ni èbiti pa nijó keji?

AEku
BOyà
COkété
DTúùpú
View Explanation & Discuss
Question 355
waec 2009

. "Kúnlé lè je bàsíà iresi kan" jé àpeere 

Aàsorégèé
Bàfiwé
Càdåpè
Dèdá-oro
View Explanation & Discuss
Question 356
waec 2009

Òjédélé dåbåti alàpà" jé àpeere 

Atààrà ifòròdárà.
Bàfiwé
Cfohùngbohủn
Dàfiwé elélòó.
View Explanation & Discuss
Question 357
waec 2009

. "Igba esinsin ki í dènå dowo" jé åpeere 

Aiwúre
B, ikéde
C. ofò
D. iroyin
View Explanation & Discuss
Question 358
waec 2009

 ÒGBÓN iTOPINPIN LITÍRÉSO :

 "Ảpáàdi-èèbó-tí -somo-nů-bí-ök" jé oriki 

Agóðlů
Bdigí
Cfàdákå
Dowó
View Explanation & Discuss
Question 359
waec 2009

iTUMÒ ÈDĖ Túmò gbólóhun tí ó wà ní ibéère si èdè Yorùbá

Border disputes claimed many lives.

AWon ti le korin
BWón ti lè máa korin
CWon à Wón á ti korin
DWón h korin IPIN
View Explanation & Discuss
Question 360
waec 2009

iTUMÒ ÈDĖ

Túmò gbólóhun tí ó wà ní ibéère si èdè Yorùbá

Border dispute claimed many lives. 

AOpò èmí sòfò ní ààlà ilề
Bljà ààlà ile gbèmí enikan
COpò èmí sòfò nítorí ijà àalà llè
Djà ààlà ilè femí sòfò
View Explanation & Discuss
Question 361
waec 2009

iTUMÒ ÈDĖ

Túmò gbólóhun tí ó wà ní ibéère  tó wà ní ìsàlẹ̀ si èdè Yorùbá

The economy will be buoyant this year. 

AOro-ajé ń fè sí i, lódún yii
BOro-ajé yóò búrekè sí i lódún yií
COro-ajé yóo yípadà, lódún yií
DOrò-ajé ń fé àtúnse, lódún yií
View Explanation & Discuss
Question 362
waec 2009

 iTUMÒ ÈDĖ

Túmò gbólóhun tí ó wà ní Ìbéèrè tó wà ní ìsàlẹ̀
si èdè Yorùbá


 I' believe him

AMo gbà ó gbó
BMo le gbà á gbó
CMo gbà ả gbó
DMo le gbà ó gbó
View Explanation & Discuss
Question 363
waec 2009

. "Dide dúró" jé gbolóhùn 

Aibéèrè
Başeròyin
Càlàyé
Dase
View Explanation & Discuss
Question 364
waec 2009

 "E má bínú mi", 'mi' jé 

Aoro-àpèjúwe
Boro-aropo-oruko
Coro-ise
Doro- àsopo
View Explanation & Discuss
Question 365
waec 2009

 Ninú "Mo lo sí ibi igbéyàwó" 'st jé 

Aoro-atókùn
Borò -orúko
Coro-àsopò
Dorò-ápèjúwe
View Explanation & Discuss
Question 366
waec 2009

 Èwo ló ni òro-iše ní ipilė? 

AOnisu
BAasè
COmokómo
DOdoodủn
View Explanation & Discuss
Question 367
waec 2009

Orò isèdá ni 

Apéńpé
Bdùgbè
Cijó
Dara
View Explanation & Discuss
Question 368
waec 2009

GİRMA

 Ewo ló ni àfömó-ibèrè nínú àwon wònyí? 

AAyérayé
BAgbára
CAtije
DAlaalé
View Explanation & Discuss
Question 369
waec 2009

Ewo ló parí àmi ohùn àárín? 

AIyán
BOfin
CEbè
DAsà
View Explanation & Discuss
Question 370
waec 2009

 Ewo ni bátani silébù Yorùbá nínú àwon wonyí 

AK-KF
BF-KF
CK-FK
DF-FK
View Explanation & Discuss
Question Navigator
Current
MathsFaculty