Adépitàn ni ó
Study and practice Yoruba past questions with answers and detailed explanations. Then test your knowledge using our interactive CBT practice platform and prepare confidently for your upcoming examinations.
Create and set up a CBT environment with your preferred subjects.
Practice JAMB CBT with real UTME past questions in CBT format.
CB-WASSCE styled past question practice.
SSCE & GCE styled past question practice.
Adépitàn ni ó
2. Eka mélòó ni ó wà nílé-isé náà?
Ka àwon àyokà isàlè wònyí, kí o sì dáhùn àwọn ibéèrè tí o wa tèlé òkoòkan wọn.(1-5)
Ódún kejilả rèé tí Adébáre, Adéyanjú àti Adéoyè ti wà ní Tòròńtò, ilú gba. Gbogbo wọn ló ti lówó. Adébåre nikan ni ó pinnu láti wá dá ilé-işé silè ni Ajélàńwă, ilú rè, nítorí pé ilé làbò isinmi oko.Ó si tun rò pẻ yóò fún àwọn ará ilú rè ní ànfààní láti rişé òwò şe. Ní ojó işilé-işé yií, ilú kún fófó ayẻ gbỏ, òrun sì mò. Màlúù méji ni oba Akànni, Alájé ti Ajélàńwá fà kalè nítorí idùnnú tí cở ở şubú layò fún un pẻ àsikò òun ni ilé-işé wòlú. Ó dúpé lówó Adébáre fún àigbàgbé ilé. ó si şí ilé-işé nåà nípa gigé aşo tééřé tí a ta sí enu ònà,
Ninú ilé-işé yii ni a ti rí oríşiríşi èka bí aşo híhun, ike şişe, búredi şíşe, abó ijęun şíşe àti şişe omi amólöló. Adépitàn tí ó jé ògá olópàá ní agbègbè yii şèlėrí ipèsè ààbò tó péye fún ilé-isé náà.
1. Adébáre nikan ni o.