Yoruba Past Questions

Study and practice Yoruba past questions with answers and detailed explanations. Then test your knowledge using our interactive CBT practice platform and prepare confidently for your upcoming examinations.

794 questions JAMB 79 WAEC 794 CUSTOM 1
Download PHP app Ask a Question Check Syllabus Past Question Videos Topic Video Lessons

Take a test

Past Questions

794 questions
Question 1 of 20 794 total questions
Question 41
waec 2024

Òkú tia gbé wojà tí kò tà tá a káşo lé lórí là ń pè ní

ALábùdànù
BÔgògò
CEégún
DOlóta
View Explanation & Discuss
Question 42
waec 2024

Ta ni akéwi so pé ó mojů òkíti?

AIná
BÀgbè
COjó
Dole
View Explanation & Discuss
Question 43
waec 2024

Ninú itàn "ijàpá kó gbogbo ogbón ayé sinú kèngbè, ta ni ó kó Ijàpå ní ogbón ti ó fi gbẻ akèħgbè rè gun igi?

AYånnibo
BOlorun
Colóde
DTirókò
View Explanation & Discuss
Question 44
waec 2024

Eranko ti ó kökó só kànga ni

 

AErin
BEfòn
Cİgalà
DOlógbò
View Explanation & Discuss
Question 45
waec 2024

________ ni ó kókó fura pé jàpá kò sí ní ibi tí wón ti gbé kànga.

AOlógbò
BIgalà
CEtu
DEgbin
View Explanation & Discuss
Question 46
waec 2024

"Na pápá bora" túmo sí

Agé oko
Bşe àişe
Csá lọ
Dtú àşírí
View Explanation & Discuss
Question 47
waec 2024

"Awòlúmátèé, iwòn ara rè ló mờ", jé àpęęrę

Aègò
BÒwe
Cofò
Dèfè
View Explanation & Discuss
Question 48
waec 2024

İbádógba gbólóhùn jeyo nínú

AKurumí Onàlú, iró Àgbowá, oko iroko
BÌrù òkéré kò jómi obà ó tòrò
Cjó ní jó, ayò níf yo
DEmi ò bá oníkàámógún nilé
View Explanation & Discuss
Question 49
waec 2024

"Aféfé tí ń fé relé Olókun, má jéé ń ráhùn lónií, Èrúufù tí ń relé olóşà, Máa jéé ń ráhùn ...".

Àyolò òkè yif jé àpęęrę

Aàwítúnwí
Bàfiwé eléloó
Càdàpè
Dàfiwé tààrà
View Explanation & Discuss
Question 50
waec 2024

Do not disturb my students

AMá jé kí inú àwọn akékoó mi bàjé.
BMá yí irísí àwon akékòó padà.
CMá jé kí àwọn akékòó jinà sí mi.
DMá da àwon akékòó mi láàmú.
View Explanation & Discuss
Question 51
waec 2024

They greeted him with little enthusiasm.

AWón kí i gán-ún
BWón yóò ki gản-ún
CWón lè kí i gán-ún
DWón féé kí i gán-ún
View Explanation & Discuss
Question 52
waec 2024

I have no intention of coming to your house. 

AMi ò ti è gbèrò láti lọ si ilé rè
BMi ò gbèrò láti wá sí ilé re.
CMi ò nií gbèrò láti wả sí ilé re
DMiò gbèrò láti lọ sí ilé rè.
View Explanation & Discuss
Question 53
waec 2024

We had just finished our evening mean when he entered.

AA sèsè je oúnje alé tán ni ỏ wolé.
BAń je oúnje alé lówó ni ó wolé.
CA féé parí oúnje alé ni.ó wolé.
DOúnje alé wa ti féé tán kí ó tóó wolé.
View Explanation & Discuss
Question 54
waec 2024

Apeere gbólóhùn àbòdé ni

AA kí i sùgbón kò dáhùn
BÓrí Olú ní àná
CMo fé kí o wá silé
DWá lo ra ata ní ojà
View Explanation & Discuss
Question 55
waec 2024

Åpólà orúkọ tí kò ní àpónlé èyán nínú ni

Ailé nlá méji
Biyàwó kan şoşo
Comi tútù nini
Deni méji péré
View Explanation & Discuss
Question 56
waec 2024

Nínú "ó pàdé mi", pådé jệ òrỳ-işe

Aaláiléní
Balápèpadà
Càkànmórúko
Dagbèrún
View Explanation & Discuss
Question 57
waec 2024

Níinú "Opộ èniyàn ló wà níbė, ġpò jé òro oruko 

Aibikan
Basoye
Càfihàn
Digba
View Explanation & Discuss
Question 58
waec 2024

İsodorúko èlò ni 

Aipara
Belégàn
Càllówó
Dosoose
View Explanation & Discuss
Question 59
waec 2024

Èyí tí ó ní aşáájú orà-işe nínú ni

AÓ pàdéè mi
BỞ rò mi ro ire
CC. Ó ń féé lọ
DÓ şe mi lóore
View Explanation & Discuss
Question 60
waec 2024

"Bóńdùrù" jé òrò àyálò tí a yá nípasè

Aòlàjú
Boro-ajé
Cètò-èkó
Dèsin
View Explanation & Discuss
Question Navigator
Current
MathsFaculty