Kónṣónántì tí a fi iwájú-ahón àti èrìgi
Study and practice Yoruba past questions with answers and detailed explanations. Then test your knowledge using our interactive CBT practice platform and prepare confidently for your upcoming examinations.
Create and set up a CBT environment with your preferred subjects.
Practice JAMB CBT with real UTME past questions in CBT format.
CB-WASSCE styled past question practice.
SSCE & GCE styled past question practice.
Kónṣónántì tí a fi iwájú-ahón àti èrìgi
ÈTÒ-IRÓ
Fáwẹ̀lì pẹ̀rẹ̀sè ni
"Omi lágbára ju iná lo" lè jé orí-òrò fún àròko
Èwo ni kì í ní àkolé?
ÈWO ni ó lè bá àròko ajęmó-isípayá mu?
ÀRÒKO
idánwò tí ó bà mi lerù ju l" lè jé orí-rò fün àròko
Àkolé tí ó bá àyokà yìí mu jù lọ ni
—— ni akéwi so pé kì í kó owó pé fún olójà.
Ta ni akéwi so pé ó máa gbowó èyin?
Akéwi sọ pé àwon ojíşé Olorun kan máa ń ....
Ka àwon àyokà isàlè wònyí kí o si dáhùn àwon ibéèrè tí ó tèlé òkookan wọ
II
Bó ó bá réèyàn tó fówó láfèéjù Ogbón inú ni kó ó fi máa bá a lò Kò síwà búburú kan tí irú won kò lè wù
Bá a fi wón sípò iyi, won kò jé sòótó
Bí wón jólópàá, woná gbowó èyìn
Bí wón jádájó, won a gbébi fáláre
Bí wón jólùkó, wọn a fohun burúkú kómo
Bí wón jójiíşé Olórun, won a şi opó lónà Wò wón léékan kò o kọjú sí ibi o ń lọ Mo bè ó, má tilè fara wé wọn İfé-owó şáà ni gbòngbò èşe Aláşo dúdú tó ń rìn kiri lóru
Awon tí ki í fojú róhun olóhun
Alágbàtà tó pa sísi tó pè é ní tóró fólówó
Eni tó ń bàsirí apààyàn àti kólékólé
Éyi tó ń se fåyàwó, èyí tí ń towó bàpò alápò Éyí tó ń paró fún ni bí eni láyin Önà àtiji ohun olóhun mộ tiwon ni wón ń se kiri!
Kí ni akéwi fi ilà méji àkókó ewi yii se?
Akolé tí ó bá àyokà yií mu jù lo ni
Oşù tí Titilayò wọ ilé oko ni ó
Gbádébo jé omo.
Ibo ni wón ti şe mòmí-ń-mò-ò?
Ka àwon àyokà isàlè wònyí kí o si dáhùn àwon ibéèrè tí ó tèlé òkookan wọn.
"Ako ni ògìdán ń bi" lorò Akinadé àti Tólání, aya rè. Tádé dáúdù, Tóba, Tayo àti Tolú sì tèlé e ni sísè-n-tèlé. Titílayò tí ó di iyàwó Tádé nikan ni àwon òbí tirè bí. Kó máa jé òun nikan nínú ilé, ló mú kí àwon òbí rè gba Gbádébò àti kíkélomo tí wón jé omo àbúrò bàbá rè sódo. Àbújá ni Tádé àti Tíitílayò ti pàdé ní àşikò tí wón lọ sin ilè baba wọn. BÍ eré bí àwàdà, òrò ifé gbilè láàárin won. Léyin oşù keje tí wón pàdé, wón pinnu láti fé ara won.
Tádé mú Títílayo lo sí ilú rè, Ökèehò, láti lọ sàfihàn Títilayo, olólufé rè fún àwon òbí rè. Inú Tádé dùn pé àwon òbí òun kò rí àbùkù lára àfesónà òun. Tọwó-tesę ni àwọn òbí Titilayò náà fị gba Tádé gégé bí àfésónà omo won. Omo Ofà, tí ő tún tan mó òró ni
Titilayò, Òfà ni wón si ti şe mòmí-ń-mò-ó. Oşù keta léyin èyí ni wón şe igbéyàwó alárinrin. Gbogbo àwon àbúrò Tádé ni ó péjo síbè. Títilayò kò mú oşù náà jẹ. OŞù kęsàn-án gééré léyin igbéyàwó ni Títilayò bí omokùnrin kan.
Tolú jé ?
ÁSA
Oba àkókó ní Oyó ni —
ÁSA
—— ni a ki ní "Alómájàá okùnrin násánnásán, ò yí awo inú pó mó tẹyìn tiké".
ÁSA
"Ipèsè" jé ilù fùn àwon
ÁSA
Aàrę-onà-kakànfò jé olóyè——