ÈTÒ-İRÓ
Ewo ni àfojúyá nínú iwònyí?
Study and practice Yoruba past questions with answers and detailed explanations. Then test your knowledge using our interactive CBT practice platform and prepare confidently for your upcoming examinations.
Create and set up a CBT environment with your preferred subjects.
Practice JAMB CBT with real UTME past questions in CBT format.
CB-WASSCE styled past question practice.
SSCE & GCE styled past question practice.
ÈTÒ-İRÓ
Ewo ni àfojúyá nínú iwònyí?
ÈTÒ-İRÓ
Kóńsónánti akùnyùn ni
ARÒKO
"Işé atèwétà", le jé òrò-orò fún àròko
ARÒKO
"ílú Oyinbó tí mo lo" ję mó orí-orò fún àròko
ARÒKO
Aròko Aşàríyànjiyàn ni ó máa ń—
ARÒKO
Igbésè àkókó nínú àròko onílétà ni ——
Ka àwon àyokà isàlè wònyí kí o si dáhùn àwọn ibéèrè tí ó tèlé okokan won.
Oréré ayé, awo ojú
E wo òréré ayé bó ti tó ló
E Wò ó lọ sàà débi tí ó sé kónà
E wò ó bó sé lele bí omi Òkun
Agbà-ò-kogbón ló pé àkíyèsí
Omo adáríhunrun sí şàkun ayé
Nítorí ojú làgbà á yá
Àgbà kan kì í yánu
Emó kú, ojú òpó dí
E jé á bira wa léèrè òrò
İdí abájo táyé ò fi gún mó
Ekó kóbo-kan-àbò kòyó omo owó mó
Akàrà sísi kò tó adélébọ í mùkọ òódúnrún
Aşé ayé ti şé kónà mý wa lówó Ayé ò tó mó bí i tàlèyin!
İbéèrè:
Akolé tí ó bá àyokà yií mu jù lọ ni?

"sé kónà" nínú àyolò yíi túmò sí

Ayolò yií sọ pé ayé àtijó?

Ta ló ta àwọn aráyé jí nípa bí ayé şe rię?

Ewo ni ó bá ayé mulè?
Ka àwon àyokà isàlè wònyí kí o si dáhùn àwọn ibéèrè tí ó tèlé okokan won.
ÈDÈ ÀKÀYÉ
"Ékó dára! Ekó sunwòn!". Ariwo tioluko àwon Tèmiladé máa ń pa fún àwọn akékòó rè niyí ní gbogbo igbà, àmó orin imòràn yií kò tà létí Tèmiladé. Seun, Kólájo àti Kúnlé tí wón jé kòrí-kòsůn Tèmiladé ni wón jo máa ń se iranù kiri. A tilè máa fónnu pé kò digbà tí èniyàn bá kàwé kó tó lówó lówó, béè owó lòun ń fé.
Láti fa orò gùn, Jídé tó jé ègbón rè kàwé jáde ní Yunifásiti, o sìnrú ilú, ó ríşé gidi, ó si bèrệ sí í rájé jęun dáadáa. Owó rè yií fejú mó Tèmiladé ló bá pa iwé kíkà tì pé òun fé sòwò. Egbón àti àwọn òbí rè dá a lókòwò, àmó kò tó odún márùn-ún, iná sọ nílé itajà rè, ó sì.runm gbogbo ojà nấà. Báyi ni Temiladé di edun arinlè. Ó gbiyànjú láti wáşé pèlú iwònba iwé tó kà şùgbón owó isépé àti işé ègbin ni wón fi ń lộ ó. Iwájú ò şe é lo, èyìn ò sì şe é padà sí fún un; ojoojúmó ló si wá ń kábàámộ pé oun kò kàwé yanjú.
İbéèrè:
Åkolé tí ó bá àyokà yií mu jù lọ ni ——

Kólájo ni ó——

Kí ni Tèmiladé kábàámò lé lórí?

Egbón Tèmiladé ni?

Ta ló máa ń korin fún àwọn akékòó pé èkó dára?
ÀŞÀ
"Ògídiolú oníkànga àjípọn", jé ara oriki.
ÀŞÀ
İkòri jé orişíí
ÀŞÀ
Okét éje èèwò fún iran.
ÀŞÀ
Awo rirán jệ isệ.