"Aṣọ òkè di aṣọòkè" nípasẹ̀ ìgbésẹ̀...
Yoruba Past Questions
Study and practice Yoruba past questions with answers and detailed explanations. Then test your knowledge using our interactive CBT practice platform and prepare confidently for your upcoming examinations.
Take a test
Custom CBT
Create and set up a CBT environment with your preferred subjects.
JAMB CBT Simulator
Practice JAMB CBT with real UTME past questions in CBT format.
WAEC CBT Practice 2026 Simulator
CB-WASSCE styled past question practice.
NECO CBT Practice 2026 Simulator
SSCE & GCE styled past question practice.
Past Questions
874 questionsỌ̀kan lára àwọn iṣúwọn tí a fi ń ṣe àpèjúwe fáwẹ́lì ni...
...jẹ́ ọ̀kan lára oríṣi afipẹ̀ tí ó wà:
Ìrò fáwẹ́lì àhánupẹ̀ iwájú ni...
Nígbà tí a bá ń ṣe afọ, aláfọ tán-án-ná lè wà ní ipò...
Àpapọ̀ àwọn ẹ̀yà-ara tí a fi ń gbé ìrò jáde ni a ń pè ní
Èwo lo jẹ́ orí-òrò fún àrọ̀kọ àṣàpẹ̀júwe?
"Ọjọ́ tí mo kọ́kọ́ di ọmọ ilé-ékó̀ Girama" lè jẹ́ orí-òrò fún àrọ̀kọ...
Àrọ̀kọ tí ó fi ojú ìhà méjì tí ó ta kó rà wọ́ orí-òrò kan ni àrọ̀kọ...
Èwo ni a máa ń lò láti fi kí ẹni tí a kọ lẹ́tà àìgbagbefẹ́ sí?
Ka ayoka yi ki o si dahun awon ibeere ti otelee.
Ni igba kan, ní ilu Ayegbajeje, orúko inagije ni won fi máa ń pe Asá áti Awodi. İkuloogun ni wón máa ń pe Aşá, Iku-wolé-awo ni wớn si máa ń pe Awòdi. Bi wón bá féệ sảlàye nkankan nípa àwọn méjèèji wónyi, wón lè sọ pé órómodiyę, ęyę kéékėčké, eku áti alángbá ni Ikúlóògún máa ń ję. İşépé igi áti įka-igi tí kò gbó ni o fi máa ń şe ité ré si ori ęka-igi tí ó ti gbó. Eyin méta sí mrin ni ó máa ń yẻ. Àwọ funfun tí ó dàbí igbà pé a fi àwọ pupa áti sán-án-yán kùn lára bálabála ni eyin rẻ yii máa ń ní. Tí abo bá sába lórí ęyin yii dię tỉ ở bả dide, ako náà yóò sába lé e. Eyo kookan tàbí méji ni wón máa ń rin. Ikúlóògùn lẻ dúró ní ojú òfurufü fün igbả pípé láijábó.
Ni ti Iku-wolé-awo, ó máa ń ję órómodiye, eku, alángbá, ákéré àti esú; ó sì lẻ máa jęun bí ở bá n fô lọ. İtệ rẻ máa ń ga sókè diệ lórí ęka igi nígbả çęrün. Eyin kan sí méta nì ở máa ń yẻ. Ảwợ ewé àti funfun ni eyin yii máa ń nỉ șugbón ảwo pupa tóótòòtó tún máa ń wà lára çyin yii. Ó fi igbe jo igbe ológbò. Ó lẻ då rin, wộn lè rìn ní méjiméji, ní igbà miírăn, àwọn tỉ wón jọ máa ń rìn lè pé igba.
Apėjá Ikúlóögùn ni Ikúlóògun-jawo-lọ nígbà tí àpėjá lkú-wolé-awo jé Ikú-wolé-awo-sákálá, ęni-ti-kò-lóbinrin-ana-re-ki-i-kú.
Kí ni àbùdá àdání Ikú-wòlẹ̀-awò?

Ẹni tí ó le dúró sójú òfurufú fún ìgbà pípẹ̀ ni:

Ikúlóògùn túmọ̀ sí pé:

Èwo ni èyìn rẹ ní sán-án-yán lára?

Èwo ni ó ń jẹ esù?
Ka ayoka yi ki o si dahun awon ibeere ti o wa nibe.
Ka àwọn ayokà ìsalę winyi ki o si dáhùn àwọn ìbéèrè tíó tělé okookan wọn.
Orişií àwọ méfa ni oluko wa ko wa bí a şe ń po àwọ mìíràn pò mộ ara wọn láti șědá wọn. Àwọ kin-ín-ní ti wọn ko wa bí wọn şe n sędá rẻ ni sán-án-yán, ekeji ni ofèéfèé, ękęta ni àwọ ewé, ękęrin ni àwò eérú, ekarùn-ún ni àwọ gbúre nígbà tí ękęta jé àwọ omi osản. A ó mú àwọn àwò náà ní șísę-n-tělé láti șàlàyé bí wọn şe n şędá wọn.
Àwọ méta ni a popò láti șędá àwọ kìn-in-ní, àwọn àwọ tí a pò pò náà ni àwò aró, pupa àti òfeéféé. Ní ti àwọ kejì, a po àwò pupa pọ mọ àwọ ewé. Ní ti ękęta, a po àwọ òfeéfèé mó àwọ aró. Ní ti àwọ kẹrin, a po àwọ dúdú pộ mó funfun. Ní ti àwọ karùn-ún, a po àwọ pupa mọ funfun. Ní ti ękęfà, a wáá po àwò pupa mó òfèéfèé.
Bí ìdánilékỳó wa lórí oríşirişi àwọ àti ộnà tí à ígbà şędá wọn șe lọ ní ọjọ náà nìyện.
Àwọ̀ tí a lò lẹ́ẹ̀kan ṣoṣo ni

Ìgbà mélòó ni a po àwọ̀ pupa pọ̀ mọ́ àwọ̀ míìrán nínú àyọkà yìí?

Àwọ̀ wo ni a pọ̀ pọ̀ láti ṣe àwọ̀ òfèéfèé?

Àwọ̀ tí a ṣe dá kejì jẹ́

Èwo ni iye àwọ̀ tí a pọ̀ pọ̀ láti ṣe àwọ̀ pọ̀ jù?