Yoruba Past Questions

Study and practice Yoruba past questions with answers and detailed explanations. Then test your knowledge using our interactive CBT practice platform and prepare confidently for your upcoming examinations.

874 questions JAMB 79 WAEC 794 CUSTOM 1
Download PHP app Ask a Question Check Syllabus Past Question Videos Topic Video Lessons

Take a test

Past Questions

874 questions
Question 1 of 20 874 total questions
Question 41
jamb 2025

Ka àwọn ayokà isàlè yil, ki o si dáhún àwọn ibéèrè tí ó tèlé won.
Òpò ọdún séyìn, àșà Yorùbá jẹ́ àfihàn ìdánimọ̀, ìbùkún àti ìpẹ̀yà fún àwọn tí wọ́n bá tẹ̀síwájú nínú rẹ̀. Àșà àti ìṣe Yorùbá dá lórí ìbáșepọ̀ rere, ìbùkún
àwọn àgbà, ìtẹ́lọ́run ìdílé, àti ìmọ̀ràn tí ó dá lórí ọgbọ́n àwọn baba-nlá wa. Ní gbogbo agbondan Yorùbá, ìyàwó tí a fẹ́ sílẹ, orúkọ tí a fún ọmọ, àwọn
àșà bí a șe ń sajọyọ̀, tàbí bó ṣe yẹ kí a șe ìrántí ẹni tó kú, gbogbo wọ́n ní ìtumọ̀ púpọ̀.
Șùgbọ́n, ní àgbáyé òde-òní, pẹ̀lú ìtẹ̀síwájú ìmọ̀ ìjìnlẹ̀ àti imọ̀-ẹrọ, ọ̀pọ̀ àwọn ọmọde àti àwọn ọdọ ti kọ̀ ẹ̀kọ́ àti àșà àwọn baba wọn sílẹ̀. Wón ń fi ẹ̀sùn
kàn an pé àșà jẹ́ ohun ateyinwa, kó sì ní ọ̀rọ̀ tó wúlò mọ́. Kíákíá ni wọ́n fi ń gbàgbọ́ pé àwọn àșà tó jẹ́ ti àwọn orílẹ̀-èdè yòókù dàgbà ju tiwọn lọ.
Ọpọ̀ àwọn obi àti olùkọ́ ló ti wá fìdí re mulẹ̀ bayi pé àìmọ̀ àșà lórí àwọn ọmọde ń fa ìjìyà àti ìtànkálẹ̀ ìbànújẹ nínú awujọ. Bí àpẹẹrẹ, ọmọ tí kò mọ̀
ìtẹ́ríba, kò ní lè mọyì àgbà, kó sì ní ifọkàn tán láti fi ọgbọ́n gbà ìpinnu. Nípa bẹ́ẹ̀, àṣà Yorùbá kò yẹ kí ó kú tàbí di aimo, ó yẹ kí a fi ran àwọn ọmọ wa
lọ́wọ́ nínú ẹ̀kọ́, isé, àti ìgbésí-ayé won.

Báwo ni àwọn ọmọde șe ń wo àșà àwọn baba wọn?

AGégé bí ohun tí kò ní itumo mó
BGgẹ́ bí ẹ̀sùn tí kò dáa
CGge bí ohun tí o yẹ ki wọ́n mọ̀
DGége bí ohun tó péye tó yẹ ká fọkàn tán
View Explanation & Discuss
Question 42
jamb 2025

Ka àwọn ayokà isàlè yil, ki o si dáhún àwọn ibéèrè tí ó tèlé won.
Òpò ọdún séyìn, àșà Yorùbá jé àfihàn ìdánimọ̀, ìbùkún àti ìpẹ̀yà fún àwọn tí wọ́n bá tẹ̀síwájú nínú rẹ̀. Àșà àti ìṣe Yorùbá dá lórí ìbáșepọ̀ rere, ìbùkún
àwọn àgbà, ìtẹ́lọ́run ìdílé, àti ìmọ̀ràn tí ó dá lórí ọgbọ́n àwọn baba-nlá wa. Ní gbogbo agbondan Yorùbá, ìyàwó tí a fẹ́ sílẹ, orúkọ tí a fún ọmọ, àwọn
àșà bí a șe ń sajọyọ̀, tàbí bó ṣe yẹ kí a ṣe ìrántí ẹni tó kú, gbogbo wọ́n ní ìtumọ̀ púpọ̀.
Șùgbọ́n, ní àgbáyé òde-òní, pẹ̀lú ìtẹ̀síwájú ìmọ̀ ìjìnlẹ̀ àti imọ̀-ẹrọ, ọ̀pọ̀ àwọn ọmọde àti àwọn ọdọ ti kọ̀ ẹ̀kọ́ àti àșà àwọn baba wọn sílẹ̀. Wón ń fi ẹ̀sùn
kàn an pé àșà jẹ́ ohun ateyinwa, kó sì ní ọ̀rọ̀ tó wúlò mọ́. Kíákíá ni wọ́n fi ń gbàgbọ́ pé àwọn àșà tó jẹ́ ti àwọn orílẹ̀-èdè yòókù dàgbà ju tiwọn lọ.
Ọpọ̀ àwọn obi àti olùkọ́ ló ti wá fìdí re mulẹ̀ bayi pé àìmọ̀ àșà lórí àwọn ọmọde ń fa ìjìyà àti ìtànkálẹ̀ ìbànújẹ nínú awujọ. Bí àpẹẹrẹ, ọmọ tí kò mọ̀
ìtéríba, kò ní lè mọyì àgbà, kó sì ní ifọkàn tán láti fi ọgbọ́n gbà ìpinnu. Nípa bẹ́ẹ̀, àṣà Yorùbá kò yẹ kí ó kú tàbí di aimo, ó yẹ kí a fi ran àwọn ọmọ wa
lọ́wọ́ nínú ẹ̀kọ́, isé, àti ìgbésí-ayé won.

Kí ni ó jẹ́ kí àwọn ọmọde ode-òní bẹ̀rẹ̀ sí í kọ àṣà sílẹ̀?

AIwà ẹ̀sùn
BKíkọ ọ̀rọ̀ ẹ̀sìn
CÌmọ̀ ìjìnlẹ̀ àti imọ̀ ẹrọ
DIrawọ̀ oríburúkú
View Explanation & Discuss
Question 43
jamb 2025

Ka àwọn ayokà isàlè yil, ki o si dáhún àwọn ibéèrè tí ó tèlé won.
Òpọ̀ ọdún sẹ́yìn, àșà Yorùbá jẹ́ àfihàn ìdánimọ̀, ìbùkún àti ìpẹ̀yà fún àwọn tí wọ́n bá tẹ̀síwájú nínú rẹ̀. Àșà àti ìṣe Yorùbá dá lórí ìbáșepọ̀ rere, ìbùkún
àwọn àgbà, ìtẹ́lọ́run ìdílé, àti ìmọ̀ràn tí ó dá lórí ọgbọ́n àwọn baba-nlá wa. Ní gbogbo agbondan Yorùbá, ìyàwó tí a fẹ́ sílẹ, orúkọ tí a fún ọmọ, àwọn
àșà bí a șe ń sajọyọ̀, tàbí bó ṣe yẹ kí a șe ìrántí ẹni tó kú, gbogbo wọ́n ní ìtumọ̀ púpọ̀.
Șùgbón, ní àgbáyé òde-òní, pẹ̀lú ìtẹ̀síwájú ìmọ̀ ìjìnlẹ̀ àti imọ̀-ẹrọ, ọ̀pọ̀ àwọn ọmọde àti àwọn ọdọ ti kọ̀ kọ́ àti àșà àwọn baba wọn sílẹ̀. Wón ń fi ẹ̀sùn
kàn an pé àșà jẹ́ ohun ateyinwa, kó sì ní ọ̀rọ̀ tó wúlò mọ́. Kíákíá ni wọ́n fi ń gbàgbọ́ pé àwọn àșà tó jẹ́ ti àwọn orílẹ̀-èdè yòókù dàgbà ju tiwọn lọ.
Ọpọ̀ àwọn obi àti olùkọ́ ló ti wá fìdí re mulẹ̀ bayi pé àìmọ̀ àșà lórí àwọn ọmọde ń fa ìjìyà àti ìtànkálẹ̀ ìbànújẹ nínú awujọ. Bí àpẹẹrẹ, ọmọ tí kò mọ̀
ìtéríba, kò ní lè mọyì àgbà, kó sì ní ifọkàn tán láti fi ọgbọ́n gbà ìpinnu. Nípa bẹ́ẹ̀, àṣà Yorùbá kò yẹ kí ó kú tàbí di aimo, ó yẹ kí a fi ran àwọn ọmọ wa
lọ́wọ́ nínú ẹ̀kọ́, isé, àti ìgbésí-ayé won.

Kí ni àpilẹ̀kọ sọ pé àșà Yorùbá jẹ́?

AÀfihàn ìdánimọ̀
BO̧mọlúwàbí
CÌmọ̀-ẹrọ tuntun
DÌtàn èsìn àwọn ará Egypt
View Explanation & Discuss
Question 44
jamb 2025

Kínní àpẹẹrẹ gbolohun àșẹ?

AKó lọ ra akara.
BKí lo fẹ́?
CÓ ra akara.
DȘé o ti lọ?
View Explanation & Discuss
Question 45
jamb 2025

Ewì ìbànújẹ máa ń fi ...?

AAyọ̀
BÈrín
CInú dídùn
DIrunú hàn
View Explanation & Discuss
Question 46
jamb 2025

Kí ló jẹ́ àkópọ̀ gbolohun: Ọmọ náà wà ní ilé. Ó ń ka iwe rẹ?

AỌmọ náà ni ó wà ní ilé ka iwe rẹ.
BỌmọ náà wà ní ilé, ó sì ń ka iwe rẹ.
CỌmọ náà wà ní ilé tí ó ń ka iwe rẹ.
DỌmọ náà tí ó wà ní ilé ń ka iwe rẹ.
View Explanation & Discuss
Question 47
jamb 2025

Kínni orúkọ fífi ohun bí ẹranko ṣàpẹẹrẹ?

AÀfihàn
BApęẹrę
CÀròko
DÌsàlẹ̀
View Explanation & Discuss
Question 48
jamb 2025

Irú orin tí àwọn agbẹ maa ń kọ́ ni ...?

AÀlàyé
BÌjálá
COrin ìșé
DOrin aréké
View Explanation & Discuss
Question 49
jamb 2025

Gbólóhùn wo lórí àìtọ́ àfikún?

AÓ lọ s'òun òun
BWón dé, won sì lọ
CÓ lọ, ó sì rà á
DÓ șișẹ́, ó sì sùn
View Explanation & Discuss
Question 50
jamb 2025

"Ìyàwó tí kò mọ ibi tí ọkọ rẹ̀ ti ń ra ẹran, yóò jẹ ẹran ẹlẹ́dẹ̀.” Òwe yìí túmọ̀ sí:

ATí obìnrin kò bá kó ẹ̀kọ́ ilé, yóò bákú
BObìnrin gbódọ̀ mọ ohun tí ọkọ rẹ̀ ń ṣe
CỌkọ àti ìyàwó gbọ́dọ̀ jẹun pọ̀
DỌmọkùnrin gbọ́dọ̀ șe iranlọwọ
View Explanation & Discuss
Question 51
jamb 2025

Kí ni ìtumọ̀ "ṣíṣe"?

AIșẹ́
BIlé
Cẹ́tọ́
DRíran
View Explanation & Discuss
Question 52
jamb 2025

Kí ló jẹ́ afihan-an lẹ́tà àtọ́ka?

AÌmúlò
BÀwọn òwe
CÌjọpọ̀ gbolohun
DÈrọ
View Explanation & Discuss
Question 53
jamb 2025

Kínní ọ̀rọ̀ ìfarapa nínú gbolohun Bí mo șe jí, mo rí pe mo ti rẹ̀?

ABí
BRẹ̀
CMo
DȘe
View Explanation & Discuss
Question 54
jamb 2025

Ębí Yorùbá máa ń șe pẹ̀lú ...?

Aọ̀mọ-ìyá
BÌpinnu
CIjọba
DÌtàn
View Explanation & Discuss
Question 55
jamb 2025

Èsìn ibẹilẹ̀ Yorùbá ni ...?

AKérúbù
BÌjọsìn tebiliki
CÌjọsìn Ọbàtálá
DGurumaraji
View Explanation & Discuss
Question 56
jamb 2025

Alárìnjó máa ń ṣe ...?

AÌtàkùn
BEré pèlú orin
CIjó
DOrin ewì
View Explanation & Discuss
Question 57
jamb 2025

Kí ni ipa ọ̀rọ̀ "sí" nínú gbolohun Ó fi èbùn náà fún mi sí orí tabili?

AÀmì ìfọkànsìn
Bọ̀rọ̀ amúlò
Cọ̀rọ̀ àfihàn
DÒrọ̀ ìtàn
View Explanation & Discuss
Question 58
jamb 2025

Kí ló jẹ́ ohun ìjà Yoruba?

AO̧bẹ
BÒpá
Cọ̀fà
DAbẹ̀
View Explanation & Discuss
Question 59
jamb 2025

Kí ni àpẹẹrẹ ìjálá?

AOrin ìdarayà
BÌtàn orò
CO̧rọ șíșé
DÌyìn akíkanjú
View Explanation & Discuss
Question 60
jamb 2025

Oríkì jé ...?

AÌyin eni
BÌròyìn
CÀlàyé oníșe
DÌmọ̀ ayé
View Explanation & Discuss
Question Navigator
Current
MathsFaculty