Yoruba Past Questions

Study and practice Yoruba past questions with answers and detailed explanations. Then test your knowledge using our interactive CBT practice platform and prepare confidently for your upcoming examinations.

874 questions JAMB 79 WAEC 794 CUSTOM 1
Download PHP app Ask a Question Check Syllabus Past Question Videos Topic Video Lessons

Take a test

Past Questions

874 questions
Question 1 of 20 874 total questions
Question 331
waec 2011

 EWİ: LAYIWOLA, A.: Akòwé i wúrà àti àwon ijinlè àròfo miíràn

Nínú ewi "Erò Lobèe Gbègiri", Akéwi so pé eni tí ó mu gaàrí sùn yóò

Ayàgbé
Blálàá wakò ojú-omi
Clálàá wa kèké
D
View Explanation & Discuss
Question 332
waec 2011

 İTÀN ÀRÒSO ÈSÓ-OLÚBORODE, S.: Olorunsogo

 Eni tí ó lu Bídèmí tí ó fi dákú ni

AÍsúmáilà
BOláníyi
CÉsan
DFémi
View Explanation & Discuss
Question 333
waec 2011

 İTÀN ÀRÒSO ÈSÓ-OLÚBORODE, S.: Olorunsogo

İdí tí Gbolá fi kò láti fé Títí ni pé

Akií gbóràn
Bkò mowé
Ckò yááyi
Dkò lajú
View Explanation & Discuss
Question 334
waec 2011

 İTÀN ÀRÒSO ÈSÓ-OLÚBORODE, S.: Olorunsogo

Olólùfé Rónké ní ilé-iwé sekóndiri ni

AÀbèfé Adéníyi
BÀdisá Láyí
CFémi òòsàfúnminíyi
DKúnlé Åmòsá
View Explanation & Discuss
Question 335
waec 2011

ERE ONÍSE: ÖGÚNNÍRAN, L.: Eégún Alåré 

 Oko İyádùn-ún-ní ni

ADáşofúnjó
BÖjè Lárinnàká
CDúdúyemí
DÖjékúnlé
View Explanation & Discuss
Question 336
waec 2011

ERE ONÍSE: ÖGÚNNÍRAN, L.: Eégún Alåré 

 Ta leni tí ó kókó ru èkú eégun?

ADúdúyemí
BLáinnàká
COlógbojò
Djelànàdé
View Explanation & Discuss
Question 337
waec 2011

 ERE ONÍSE: ÖGÚNNÍRAN, L.: Eégún Alåré

. Awon àgbà òjè kò fé kí Ojéládé di èniyàn léyin tí ó di òni nítorí pé

Aòkan lára won fé gbàyàwó rè
B
Có ń pidán jù wón lo
Dkò júbà won rárá
View Explanation & Discuss
Question 338
waec 2011

EWÌ: ABÍMBÓLÁ, w.: Awon Ojú Odù Mérèrìndínlógún (p52 96)

 

Ninu odù "Ogúndá Méji", ta lo difa fun Oðyi òkòkó? 

AOge
BArugbo
COgun omo
DAemole eekan
View Explanation & Discuss
Question 339
waec 2011

EWÌ: ABÍMBÓLÁ, w.: Awon Ojú Odù Mérèrìndínlógún (p52 96)

Nínú odù "Òtúúrúpòn Méi", ta ni bàbá ré fi silè ní rèwerèwe? 

 

ATeleni
BIgbasoro
CAlapaandedę
DOyeepolu
View Explanation & Discuss
Question 340
waec 2011

EWÌ: ABÍMBÓLÁ, w.: Awon Ojú Odù Mérèrìndínlógún (p52 96)

Ta ni "okùnrin kúkúrú òkè Igeti"?

AOgún
BÒòduà
CÒrúnmilà
DObàtálá
View Explanation & Discuss
Question 341
waec 2011

. Ninú itàn "Omokùnrin kan àti Ijàpá" işé wo lomokùnrin náà sọ fún àwọn bí rè pé òun yóò se? 

Aİlù .Lİlù
BOde
COrin kiko
DOnísègùn
View Explanation & Discuss
Question 342
waec 2011

 iTÀN ÀRÒso ÔJo, O.: Ijàpà Tirókò Okọ Yánníbo Ninú tàn "ijàpá àti omobinrin-oba"

Ta ni ó gbégbá orókè nínú işé tí oba gbé fún won? 

AKannakánná
BEkùn
CAsá
DAlákàn
View Explanation & Discuss
Question 343
waec 2011

 iTÀN ÀRÒso ÔJo, O.: Ijàpà Tirókò Okọ Yánníbo Ninú tàn "ijàpá àti omobinrin-oba"

Isé wO ni oba gbé fún gbogbo àwon tí ó féé fé omo rè?

ADíde isà irè
Bkiko ebè işu
Cigi gigùn
DEkùn pipa
View Explanation & Discuss
Question 344
waec 2011

 "Okünrin kóróbótó bí oká"jé àpeere

Aaló
Boriki
Cofo
Dàwitúnwí
View Explanation & Discuss
Question 345
waec 2011

Mo wí wí wí, mo fo fo fo" jé àpeere 

Aiforodárà
Bifohunpèniyån
C. àşorégèé
Dàwitúnwí
View Explanation & Discuss
Question 346
waec 2011

Ewo ni dsipa owe?

AA. Agbàlagbà ki í şe lángbáláńgbắ
BAgbà tó jin sí kòtò, ojú re ló fó
CAgbà letù, omodé lawó
DAgbà tó rofó ikà, omọ rè yóò jẹ níbę
View Explanation & Discuss
Question 347
waec 2011

Tumo gbölóhùn ti ó wà ni ibéère sí èdè Yorùbá 

 He was reluctant to ask for help 

AỞ lora láti béèrè irànlówó
Bó lóra láti béèrè àtiléyin
CÔ sòro fún un láti bèèrè àtiléyin
Dó sòro fún un láti béèrè irànlówó
View Explanation & Discuss
Question 348
waec 2011

 Tumo gbölóhùn ti ó wà ni ibéère sí èdè Yorùbá 

 A good name is better than riches 

AOnuko rere ferę dára ju owó lọ
BOrúko rere ni owó eni
COrúko rere dára ju oro lo
DOrúko rere wùnmí ju orò
View Explanation & Discuss
Question 349
waec 2011

 Tumo gbölóhùn ti ó wà ni ibéère sí èdè Yorùbá 

My father built five houses

 

ABàbá mi ni ó kỏ márùn-ún ninủ ilé wonyí
BBabá mi kó lé márùn-ủn
CBàbả mi fé kó ilé márùn-un
DBàbá mi ń gbiyànjú láti kó lé márùn-un
View Explanation & Discuss
Question 350
waec 2011

"Bộlá ra eja sè je" jé àpeere gbólóhün

Aeléyo oro-ise
Balákànpò
Colóro-ise
Dàsinpo
View Explanation & Discuss
Question Navigator
Current
MathsFaculty