Yoruba Past Questions

Study and practice Yoruba past questions with answers and detailed explanations. Then test your knowledge using our interactive CBT practice platform and prepare confidently for your upcoming examinations.

874 questions JAMB 79 WAEC 794 CUSTOM 1
Download PHP app Ask a Question Check Syllabus Past Question Videos Topic Video Lessons

Take a test

Past Questions

874 questions
Question 1 of 20 874 total questions
Question 351
waec 2011

Mótò méfà ni Awódélé ní: Pijó kan, Mésidísi méj, Isúsů kan, Toyótà kan àti Jipů kan. Mésidisi ni ó máa ń gbé lo síbi isé. Tó bá fé rin irinàjò pàtàki, Jipů ló máa ń gbé lo. Kåsálí awakò rè ń wa kísà. Omo mérin ni Awódélé bí: Kládé làkóbí, Ådůké làtèlé, Kólájo lomo keta ń jé, Yéwándé làbikéyin won lénjélénje. Wón jé okùnrin méji àti obinrin méji. Gbogbo rè se wékú bí idodo èfon. Gbogbo omo tí Omóyeni bí fún Awódélé ló yàn tó yanjú. Awon àgbà ní "Ojú tó ríbi tí kò fó, ire ló ń dúró dè". Kò sí eni tí ó lè rí Awódélé lónií kó gbàgbó wí pé alágbe ni bàbá re. Odún keta gééré tí bàbá re kú ni nhkan bèrè sí ní senu re fún un. ó si ti wà nínú yòtòmi yii fún odún méwàá gbáko.

 Ákolé tí ó bá àyokà yií mu jù ni 

AÂwon okò Awódélé
BÅwon omo Awódélé
CEdá kò láròpin
DIkú alágbe
View Explanation & Discuss
Question 352
waec 2011

Mótò méfà ni Awódélé ní: Pijó kan, Mésidísi méj, Isúsů kan, Toyótà kan àti Jipů kan. Mésidisi ni ó máa ń gbé lo síbi isé. Tó bá fé rin irinàjò pàtàki, Jipů ló máa ń gbé lo. Kåsálí awakò rè ń wa kísà. Omo mérin ni Awódélé bí: Kládé làkóbí, Ådůké làtèlé, Kólájo lomo keta ń jé, Yéwándé làbikéyin won lénjélénje. Wón jé okùnrin méji àti obinrin méji. Gbogbo rè se wékú bí idodo èfon. Gbogbo omo tí Omóyeni bí fún Awódélé ló yàn tó yanjú. Awon àgbà ní "Ojú tó ríbi tí kò fó, ire ló ń dúró dè". Kò sí eni tí ó lè rí Awódélé lónií kó gbàgbó wí pé alágbe ni bàbá re. Odún keta gééré tí bàbá re kú ni nhkan bèrè sí ní senu re fún un. ó si ti wà nínú yòtòmi yii fún odún méwàá gbáko.

"se wékú" nínú àyokà yií túmo sí.

Adógba
Bjora
Cdára
Dyanjú
View Explanation & Discuss
Question 353

ni Awódélé máa ń gbé lo sibi isé.

AJipů
BPijó
CTòyótà
DMésidísi
View Explanation & Discuss
Question 354
waec 2011

Mótò méfà ni Awódélé ní: Pijó kan, Mésidísi méj, Isúsů kan, Toyótà kan àti Jipů kan. Mésidisi ni ó máa ń gbé lo síbi isé. Tó bá fé rin irinàjò pàtàki, Jipů ló máa ń gbé lo. Kåsálí awakò rè ń wa kísà. Omo mérin ni Awódélé bí: Kládé làkóbí, Ådůké làtèlé, Kólájo lomo keta ń jé, Yéwándé làbikéyin won lénjélénje. Wón jé okùnrin méji àti obinrin méji. Gbogbo rè se wékú bí idodo èfon. Gbogbo omo tí Omóyeni bí fún Awódélé ló yàn tó yanjú. Awon àgbà ní "Ojú tó ríbi tí kò fó, ire ló ń dúró dè". Kò sí eni tí ó lè rí Awódélé lónií kó gbàgbó wí pé alágbe ni bàbá re. Odún keta gééré tí bàbá re kú ni nhkan bèrè sí ní senu re fún un. ó si ti wà nínú yòtòmi yii fún odún méwàá gbáko.

. Odún kélòó ni bàbá Awódélé ti kú?

AKétàlá
BKéwàá
CKeje
DKeta
View Explanation & Discuss
Question 355
waec 2011

Mótò méfà ni Awódélé ní: Pijó kan, Mésidísi méj, Isúsů kan, Toyótà kan àti Jipů kan. Mésidisi ni ó máa ń gbé lo síbi isé. Tó bá fé rin irinàjò pàtàki, Jipů ló máa ń gbé lo. Kåsálí awakò rè ń wa kísà. Omo mérin ni Awódélé bí: Kládé làkóbí, Ådůké làtèlé, Kólájo lomo keta ń jé, Yéwándé làbikéyin won lénjélénje. Wón jé okùnrin méji àti obinrin méji. Gbogbo rè se wékú bí idodo èfon. Gbogbo omo tí Omóyeni bí fún Awódélé ló yàn tó yanjú. Awon àgbà ní "Ojú tó ríbi tí kò fó, ire ló ń dúró dè". Kò sí eni tí ó lè rí Awódélé lónií kó gbàgbó wí pé alágbe ni bàbá re. Odún keta gééré tí bàbá re kú ni nhkan bèrè sí ní senu re fún un. ó si ti wà nínú yòtòmi yii fún odún méwàá gbáko.

Ta ni ó kéré jù lójó ori?

AKólájo
BYéwandé
CÁduké
DKóládé
View Explanation & Discuss
Question 356
waec 2010

 AŞÀ

 FÍfi òòyà ránsé sí òré túmỳ sí pé 

Aòun kò bá a soré mó
Bòun fé fé e
Còun ti rí àşişe re
Dòun fé rí i.
View Explanation & Discuss
Question 357
waec 2010

 AŞÀ

  Ní ayé àtijó, Yorùbá a máa sọ omokùnrin lórúko ní ojó

Akarùn-ún
Bkeje
Ckęjo
Dkesàn-án
View Explanation & Discuss
Question 358
waec 2010

 AŞÀ

  Orúkọ miiràn fún eni tí ó ń singbà ni

Aonígbòwó
Balárinnà
Cerú
DÎwòfà
View Explanation & Discuss
Question 359
waec 2010

 AŞÀ

 Òkan nínú àwon ònà ìran-ara-eni-lówó ni

Aişíde
Bààlè
Cişipà
Dàáró
View Explanation & Discuss
Question 360
waec 2010

 AŞÀ

Ewo ni ó fi igbàgbó nínú isèyinwáyé hàn?

AAdébóyè
BYétúndé
CÀtàndá
DTààb
View Explanation & Discuss
Question 361
waec 2010

 AŞÀ

 Eré òşupá ni

Aayò
Bbojúbojú
Còkòtó
Dàrín
View Explanation & Discuss
Question 362
waec 2010

 AŞÀ

Awon wo ni ó máa ń pa okó ní ilè Yorùbá? 

AAlágbèdé
BOlóólà
CAláró
DOnígbàjámo
View Explanation & Discuss
Question 363
waec 2010

ERÉ ONÍTÀN: ÈSÓ-OLÚBÓRÒDÉ, S.: İyàwó Alárédè

Ta ni Mojèrè kókó ń fé? 

AAdéyemo
BOládélé
COláwùmí
DAtéré
View Explanation & Discuss
Question 364
waec 2010

ERÉ ONÍTÀN: ÈSÓ-OLÚBÓRÒDÉ, S.: İyàwó Alárédè

Màmá Ségun fé lọ sí Ôsogbo nítorí igbéyàwó

Aàbúrò rè
Boré oko rè
Como rè
Dàbúrò oko rè
View Explanation & Discuss
Question 365
waec 2010

ERÉ ONÍTÀN: ÈSÓ-OLÚBÓRÒDÉ, S.: İyàwó Alárédè

Ta ni Oláwùmí pè ní "omo ijoba"?

ADàpò
BMojèrè
CFúnmi
DOládélé
View Explanation & Discuss
Question 366
waec 2010

EWÌ: ADÉBÒWÁLÉ, Lonígbàá Ká 

Nàkan èèwò tí bàbá se nínú Wón ń wò yín" ni pé ó 

Abe omo
Bdòbálè fún omo
Cmu otí yó
Dna omọ
View Explanation & Discuss
Question 367
waec 2010

EWÌ: ADÉBÒWÁLÉ, Lonígbàá Ká 

 Nínú àkólé "wón i wò yín"wón' tóka sí

Aedun
Bomo
Cèsin
Dòbí
View Explanation & Discuss
Question 368
waec 2010

EWÌ: ADÉBÒWÁLÉ, Lonígbàá Ká 

 Nínú ewi 'Bíntín Layé'

Èkó tí a rí kó nip é kí a

Awayé máyà oot níwonba
Bjégbádùn ara wa
Cyera fún iwà lile
Dse iwonba ti wa
View Explanation & Discuss
Question 369
waec 2010

LÍTÍRÉŞÒ APILÈKO: İWÉ İTÀN ÅRÖSO: ÒNÍ, K.: Ojú Rí

  Ögúngbèmí rérin-ín títí omi fi ń dà lójú rè nígbà tí

Aorí rè yí
Bó rí omo rè
Cinú rè dùn-ún
Dórí owó he
View Explanation & Discuss
Question 370
waec 2010

LÍTÍRÉŞÒ APILÈKO: İWÉ İTÀN ÅRÖSO: ÒNÍ, K.: Ojú Rí

 Àdúgbò wo ni Iná-ń-ió kólé sí ní tlú Ekó?

AAgége
BOko-0ba
CAbúlé- Egbá
Disolo
View Explanation & Discuss
Question Navigator
Current
MathsFaculty