Yoruba Past Questions

Study and practice Yoruba past questions with answers and detailed explanations. Then test your knowledge using our interactive CBT practice platform and prepare confidently for your upcoming examinations.

874 questions JAMB 79 WAEC 794 CUSTOM 1
Download PHP app Ask a Question Check Syllabus Past Question Videos Topic Video Lessons

Take a test

Past Questions

874 questions
Question 1 of 20 874 total questions
Question 61
jamb 2025

"Ìpalára" túmò sí ...?

AÈsùn
BÌfarapa
CÌrun
DÀìlera
View Explanation & Discuss
Question 62
jamb 2025

Àșà Ayeye omọ tuntun ni ...?

AÌkálẹ̀
BÌsomọlórúkọ
CÌpẹ̀yà
DÌjíròrò
View Explanation & Discuss
Question 63
jamb 2025

Alágbẹ̀dę lásán kì í fi àgùnbánirọ̀ sùn jẹ́ ...?

AÈsìn
BOríkì
CEwì
DÒwe
View Explanation & Discuss
Question 64
jamb 2025

Ka àwọn ayokà isàlè yil, ki o si dáhún àwọn ibéèrè tí ó tèlé won.
Nínú abúlé aláàánú kan tí ó wà láàárín àwọn òkè aláwo ewé, ìșẹ̀lẹ̀ abàmì kan șẹlẹ̀ tí ó yà àwọn àgbàlagbà abúlé lénu. Ní gbogbo òwúrọ̀, àwọn ará
abúlé máa ń jí láti rí pé ọgbà wọn ti bàjẹ́, oúnjẹ wọn sì dínkù láìníye. Ní ìbẹ̀rẹ̀, wọ́n fi ẹ̀sùn kàn àwọn ẹranko igbó. Sùgbọ́n ọdẹ abúlé sọ pé kò sí ipa ẹsẹ̀
kankan tí wọ́n rí láti fihàn pé ẹranko ni . Olórí abúlé pè gbogbo ènìyàn jọ, ó sì dá ẹgbẹ figilanté tó máa ń sọ́ alẹ́ sílẹ̀.
Àwọn tó yá ara wọn sílẹ̀ fún isé yí mú atupa àti ọpá, wọ́n jókòó nínú òkùnkùn. ọ̀pọ̀ alẹ́ ni kò sí ìșẹ̀lẹ̀ kankan. Șùgbọ́n ní alẹ́ karùn-ún, nígbà tí òșùpá ń
tan lójú ọ̀run, won gbo kìkún légbeé abà èlùbọ̀ olórí abúlé. Wọn sare lọ, wọ́n sì rí àwọn ọmọkùnrin àti ọmọbìnrin kan láti abúlé kejì, tí wọ́n ń sa lọ
Ní ọjọ kejì, àwọn àgbàlagbà abúlé lọ sí abúlé yẹn láti bá wọn sọrọ. Ó hàn kedere pé àwọn ọmọ yìí jẹ aláìní, tí ìkànlù omi burúkú kan ti run gbogbo
pẹ̀lú oúnjẹ tí wọ́n jí.
ọgbà wọn. Kódà, ó jẹ́ pé wọ́n ń jì oúnjẹ kí wọ́n lè yè. Eleyi jẹ̀ ohun ti o bani lọkan jẹ̀, wọn si pinnu láti fi oúnjẹ tí wọ́n ní kù fún wọn dipo ìjíyà. Láti ọjọ́
yẹn lọ, ìbáșepọ̀ àti àjọșe dájú láàárín àwọn abúlé méjèèjì.

Kí ni akori pàtàkì tí ìtàn náà ńi tabi ori oro ti a le fun itan naa?

AÀdánù tí ìkànlù omi máa n fa
BÌdáj pẹ̀lú ìyà
CPataki șíșọ abúlé
DÀánú ati ìbájọsepọ̀
View Explanation & Discuss
Question 65
jamb 2025

Ka àwọn ayokà isàlè yil, ki o si dáhún àwọn ibéèrè tí ó tèlé won.
Nínú abúlé aláàánú kan tí ó wà láàárín àwọn òkè aláwo ewé, ìșẹ̀lẹ̀ abàmì kan sẹlẹ̀ tí ó yà àwọn àgbàlagbà abúlé lẹ́nu. Ní gbogbo òwúrọ̀, àwọn ará
abúlé máa ń jí láti rí pé ọgbà wọn ti bàjẹ́, oúnjẹ wọn sì dínkù láìníye. Ní ìbrẹ̀, wọ́n fi ẹ̀sùn kàn àwọn ẹranko igbó. Șùgbọ́n ọdẹ abúlé sọ pé kò sí ipa ẹsẹ̀
kankan tí wọ́n rí láti fihàn pé ẹranko ni . Olórí abúlé pè gbogbo ènìyàn jọ, ó sì dá ẹgbẹ figilanté tó máa ń ṣọ́ alẹ́ sílẹ̀.
Àwọn tó yá ara wọn sílẹ̀ fún isé yí mú atupa àti ọpá, wọ́n jókòó nínú òkùnkùn. ọ̀pọ̀ alẹ́ ni kò sí ìșẹ̀lẹ̀ kankan. Șùgbọ́n ní alẹ́ karùn-ún, nígbà tí òșùpá ń
tan lójú ọ̀run, won gbo kìkún legbeé abà ẹ̀lùbọ̀ olórí abúlé. Wọn sare lọ, wón sì rí àwọn ọmọkùnrin àti ọmọbìnrin kan láti abúlé kejì, tí wọ́n ń sa lọ
Ní ọjọ kejì, àwọn àgbàlagbà abúlé lọ sí abúlé yẹn láti bá wọn sọrọ. Ó hàn kedere pé àwọn ọmọ yìí jẹ aláìní, tí ìkànlù omi burúkú kan ti run gbogbo
pẹ̀lú oúnjẹ tí wọ́n jí.
ọgbà wọn. Kódà, ó jẹ́ pé wọ́n ń jì oúnjẹ kí wọ́n lè yè. Eleyi jẹ̀ ohun ti o bani lọkan jẹ̀, wọn si pinnu láti fi oúnjẹ tí wọ́n ní kù fún wọn dipo ìjíyà. Láti ọjọ́
yẹn lọ, ìbáșepọ̀ àti àjọșe dájú láàárín àwọn abúlé méjèèjì.

Kí ni abajade tó yọ láti inú iṣẹlẹ̀ yìí?

AÌbáșepò to dan móran
BÌbànúję
CÌbàje oúnjẹ tó pọ̀ síi
DOlè jíjà
View Explanation & Discuss
Question 66
jamb 2025

Ka àwọn ayokà isàlè yil, ki o si dáhún àwọn ibéèrè tí ó tèlé won.
Nínú abúlé aláàánú kan tí ó wà láàárín àwọn òkè aláwo ewé, ìșẹ̀lẹ̀ abàmì kan șẹlẹ̀ tí ó yà àwọn àgbàlagbà abúlé lénu. Ní gbogbo òwúrọ̀, àwọn ará
abúlé máa ń jí láti rí pé ọgbà wọn ti bàjẹ́, oúnjẹ wọn sì dínkù láìníye. Ní ìbẹ̀rẹ̀, wọ́n fi sùn kàn àwọn ẹranko igbó. Șùgbọ́n ọdẹ abúlé sọ pé kò sí ipa ẹsẹ̀
kankan tí wọ́n rí láti fihàn pé ẹranko ni . Olórí abúlé pè gbogbo ènìyàn jọ, ó sì dá ẹgbẹ figilanté tó máa ń ṣọ́ alẹ́ sílẹ̀.
Àwọn tó yá ara wọn sílẹ̀ fún isé yí mú atupa àti ọpá, wọ́n jókòó nínú òkùnkùn. Òpọ̀ alẹ́ ni kò sí ìșẹ̀lẹ̀ kankan. Șùgbọ́n ní alẹ́ karùn-ún, nígbà tí òșùpá ń
tan lójú ọ̀run, won gbo kìkún légbèé abà èlùbọ̀ olórí abúlé. Wọn sare lọ, wọ́n sì rí àwọn ọmọkùnrin àti ọmọbìnrin kan láti abúlé kejì, tí wọ́n ń sa lọ
Ní ọjọ kejì, àwọn àgbàlagbà abúlé lọ sí abúlé yẹn láti bá wọn sọrọ. Ó hàn kedere pé àwọn ọmọ yìí jẹ aláìní, tí ìkànlù omi burúkú kan ti run gbogbo
pẹ̀lú oúnjẹ tí wọ́n jí.
ọgbà wọn. Kódà, ó jẹ́ pé wọ́n ń jì oúnjẹ kí wọ́n lè yè. Eleyi jẹ̀ ohun ti o bani lọkan jẹ̀, wọn si pinnu láti fi oúnjẹ tí wọ́n ní kù fún wọn dipo ìjíyà. Láti ọjọ́
yẹn lọ, ìbáșepọ̀ àti àjọṣe dájú láàárín àwọn abúlé méjèèjì.

Kí ni àwọn àgbàlagbà șe lẹ́yìn tí wọ́n mọ ohun tó ṣẹlẹ̀ gangan?

AWón foju kọ ọ
BWón fi inú rere pín oúnjẹ
CWón dá wọn lẹ́bi
DWon lọ kó ọlọ́pàá
View Explanation & Discuss
Question 67
jamb 2025

Ka àwọn ayokà isàlè yil, ki o si dáhún àwọn ibéèrè tí ó tèlé won.
Nínú abúlé aláàánú kan tí ó wà láàárín àwọn òkè aláwo ewé, ìșẹ̀lẹ̀ abàmì kan sẹlẹ̀ tí ó yà àwọn àgbàlagbà abúlé lẹ́nu. Ní gbogbo òwúrọ̀, àwọn ará
abúlé máa ń jí láti rí pé ọgbà wọn ti bàjẹ́, oúnjẹ wọn sì dínkù láìníye. Ní ìbẹ̀rẹ̀, wọ́n fi ẹ̀sùn kàn àwọn ẹranko igbó. Șùgbọ́n ọdẹ abúlé sọ pé kò sí ipa ẹsẹ̀
kankan tí wọ́n rí láti fihàn pé ẹranko ni . Olórí abúlé pè gbogbo ènìyàn jọ, ó sì dá ẹgbẹ figilanté tó máa ń ṣọ́ alẹ́ sílẹ̀.
Àwọn tó yá ara wọn sílẹ̀ fún isé yí mú atupa àti ọpá, wọ́n jókòó nínú òkùnkùn. Òpọ̀ alẹ́ ni kò sí ìșlẹ̀ kankan. Șùgbọ́n ní alẹ́ karùn-ún, nígbà tí òșùpá ń
tan lójú ọ̀run, won gbó kìkún légbèé abà èlùbọ̀ olórí abúlé. Won sare lọ, wón sì rí àwọn ọmọkùnrin àti ọmọbìnrin kan láti abúlé kejì, tí wọ́n ń sa lọ
pẹ̀lú oúnjẹ tí wọ́n jí.
Ní ọjọ kejì, àwọn àgbàlagbà abúlé lọ sí abúlé yẹn láti bá wọn sọrọ. Ó hàn kedere pé àwọn ọmọ yìí jẹ aláìní, tí ìkànlù omi burúkú kan ti run gbogbo
ọgbà wọn. Kódà, ó jẹ́ pé wọ́n ń jì oúnjẹ kí wọ́n lè yè. Eleyi jẹ̀ ohun ti o bani lọkan jẹ̀, wọn si pinnu láti fi oúnjẹ tí wọ́n ní kù fún wọn dipo ìjíyà. Láti ọjọ́
yẹn lọ, ìbáșepọ̀ àti àjọșe dájú láàárín àwọn abúlé méjèèjì.

Kí ni ipo àwọn ọmọ tí wọ́n ń jí oúnjẹ?

AWójẹ̀ ọdaluru
BWo jẹ́ ọmọ tí a kọ́ sílẹ̀
CWójẹ́ ọmọ tí ìkún omi tì ba nkan wọn jẹ
DWo jẹ́ ọmọ ajẹ
View Explanation & Discuss
Question 68
jamb 2025

Ka àwọn ayokà isàlè yil, ki o si dáhún àwọn ibéèrè tí ó tèlé won.
Nínú abúlé aláàánú kan tí ó wà láàárín àwọn òkè aláwo ewé, ìșẹ̀lẹ̀ abàmì kan sẹlẹ̀ tí ó yà àwọn àgbàlagbà abúlé lẹ́nu. Ní gbogbo òwúrọ̀, àwọn ará
abúlé máa ń jí láti rí pé ọgbà wọn ti bàjẹ́, oúnjẹ wọn sì dínkù láìníye. Ní ìbẹ̀rẹ̀, wọ́n fi ẹ̀sùn kàn àwọn ẹranko igbó. Șùgbọ́n ọdẹ abúlé sọ pé kò sí ipa ẹsẹ̀
kankan tí wón rí láti fihàn pé ẹranko ni . Olórí abúlé pè gbogbo ènìyàn jọ, ó sì dá ẹgbẹ figilanté tó máa ń ṣọ́ alẹ́ sílẹ̀.
Àwọn tó yá ara wọn sílẹ̀ fún isé yí mú atupa àti ọpá, wọ́n jókòó nínú òkùnkùn. ọ̀pọ̀ alẹ́ ni kò sí ìșẹ̀lẹ̀ kankan. Șùgbọ́n ní alẹ́ karùn-ún, nígbà tí òșùpá ń

Ní ọjọ kejì, àwọn àgbàlagbà abúlé lọ sí abúlé yẹn láti bá wọn sọrọ. Ó hàn kedere pé àwọn ọmọ yìí jẹ aláìní, tí ìkànlù omi burúkú kan ti run gbogbo
pẹ̀lú oúnjẹ tí wọ́n jí.
tan lójú ọ̀run, won gbo kìkún legbeé abà ẹ̀lùbọ̀ olórí abúlé. Wọn sare lọ, wọ́n sì rí àwọn ọmọkùnrin àti ọmọbìnrin kan láti abúlé kejì, tí wọ́n ń sa lọ

ọgbà wọn. Kódà, ó jẹ́ pé wọ́n ń jì oúnjẹ kí wọ́n lè yè. Eleyi jẹ̀ ohun ti o bani lọkan jẹ̀, wọn si pinnu láti fi oúnjẹ tí wọ́n ní kù fún wọn dipo ìjíyà. Láti ọjọ́
yẹn lọ, ìbáșepọ̀ àti àjọṣe dájú láàárín àwọn abúlé méjèèjì.

Kí ni àwọn olùșọ́ rí ní alẹ́ yẹn?

AỌdẹ tó ń hu iwa àjèjì
BAtupa tó dàná rẹ̀
CÀwon omọ tí ń jí oúnjẹ
DEranko tí ń jẹ ọgbà
View Explanation & Discuss
Question 69
jamb 2025

Ka àwọn ayokà isàlè yil, ki o si dáhún àwọn ibéèrè tí ó tèlé won.
Nínú abúlé aláàánú kan tí ó wà láàárín àwọn òkè aláwo ewé, ìẹ̀lẹ̀ abàmì kan sẹlẹ̀ tí ó yà àwọn àgbàlagbà abúlé lẹ́nu. Ní gbogbo òwúrọ̀, àwọn ará
abúlé máa ń jí láti rí pé ọgbà wọn ti bàjẹ́, oúnjẹ wọn sì dínkù láìníye. Ní ìbẹ̀r, wọ́n fi èsùn kàn àwọn ẹranko igbó. Șùgbọ́n ọdẹ abúlé sọ pé kò sí ipa ẹsẹ̀
kankan tí wọ́n rí láti fihàn pé ẹranko ni . Olórí abúlé pè gbogbo ènìyàn jọ, ó sì dá ẹgbẹ figilanté tó máa ń ṣọ́ alẹ́ sílẹ̀.
Àwọn tó yá ara wọn sílẹ̀ fún isé yí mú atupa àti ọpá, wọ́n jókòó nínú òkùnkùn. Òpọ̀ alẹ́ ni kò sí ìșẹ̀lẹ̀ kankan. Șùgbọ́n ní alẹ́ karùn-ún, nígbà tí òșùpá ń
tan lójú ọ̀run, won gbó kìkún légbèé abà ẹ̀lùbọ̀ olórí abúlé. Wọn sare lọ, wọ́n sì rí àwọn ọmọkùnrin àti ọmọbìnrin kan láti abúlé kejì, tí wọ́n ń sa lọ
Ní ọjọ kejì, àwọn àgbàlagbà abúlé lọ sí abúlé yẹn láti bá wọn sọrọ. Ó hàn kedere pé àwọn ọmọ yìí jẹ aláìní, tí ìkànlù omi burúkú kan ti run gbogbo
pẹ̀lú oúnjẹ tí wọ́n jí.
ọgbà wọn. Kódà, ó jẹ́ pé wọ́n ń jì oúnjẹ kí wọ́n lè yè. Eleyi jẹ̀ ohun ti o bani lọkan jẹ̀, wọn si pinnu láti fi oúnjẹ tí wọ́n ní kù fún wọn dipo ìjíyà. Láti ọjọ́
yẹn lọ, ìbáșepọ̀ àti àjọșe dájú láàárín àwọn abúlé méjèèjì.

Ní alẹ̀ wo ni wọ́n rí ohun tó ń ṣẹlẹ̀?

AAlé karùn-ún
BAl kẹta
CAlé kẹfà
DAlé àkọ́kọ́
View Explanation & Discuss
Question 70
jamb 2025

Ka àwọn ayokà isàlè yil, ki o si dáhún àwọn ibéèrè tí ó tèlé won.
Nínú abúlé aláàánú kan tí ó wà láàárín àwọn òkè aláwo ewé, ìșẹ̀lẹ̀ abàmì kan sẹlẹ̀ tí ó yà àwọn àgbàlagbà abúlé lẹ́nu. Ní gbogbo òwúrọ̀, àwọn ará
abúlé máa ń jí láti rí pé ọgbà wọn ti bàjẹ́, oúnj wọn sì dínkù láìníye. Ní ìbẹ̀rẹ̀, wọ́n fi ẹ̀sùn kàn àwọn ẹranko igbó. ùgbọ́n ọdẹ abúlé sọ pé kò sí ipa ẹsẹ̀
kankan tí wọ́n rí láti fihàn pé ẹranko ni . Olórí abúlé pè gbogbo ènìyàn jọ, ó sì dá ẹgbẹ figilanté tó máa ń sọ́ alẹ́ sílẹ̀.
Àwọn tó yá ara wọn sílẹ̀ fún isé yí mú atupa àti ọpá, wọ́n jókòó nínú òkùnkùn. Òpọ̀ alẹ́ ni kò sí ìșẹ̀lẹ̀ kankan. Șùgbọ́n ní alẹ́ karùn-ún, nígbà tí òșùpá ń
tan lójú ọ̀run, won gbó kìkún lẹ́gbeé abà ẹ̀lùbọ̀ olórí abúlé. Wọn sare lọ, wọ́n sì rí àwọn ọmọkùnrin àti ọmọbìnrin kan láti abúlé kejì, tí wọ́n ń sa lọ
Ní ọjọ kejì, àwọn àgbàlagbà abúlé lọ sí abúlé yẹn láti bá wọn sọrọ. Ó hàn kedere pé àwọn ọmọ yìí jẹ aláìní, tí ìkànlù omi burúkú kan ti run gbogbo
pẹ̀lú oúnjẹ tí wọ́n jí.
ọgbà wọn. Kódà, ó jẹ́ pé wọ́n ń jì oúnjẹ kí wọ́n lè yè. Eleyi jẹ̀ ohun ti o bani lọkan jẹ̀, wọn si pinnu láti fi oúnjẹ tí wọ́n ní kù fún wọn dipo ìjíyà. Láti ọj
yẹn lọ, ìbáșepọ̀ àti àjọșe dájú láàárín àwọn abúlé méjèèjì.

Kí ni olórí abúlé șe láti mọ ẹni tó ń bà ogbà wọn jẹ́?

AÓ lọ sí abúlé kejì
BÓ pașẹ pé kí wọ́n șe ìwádìí
CÓ dá egbé ìs alé sílè
DÓ dá ayeyẹ kan
View Explanation & Discuss
Question 71
jamb 2025

Ka àwọn ayokà isàlè yil, ki o si dáhún àwọn ibéèrè tí ó tèlé won.
Nínú abúlé aláàánú kan tí ó wà láàárín àwọn òkè aláwo ewé, ìșẹ̀lẹ̀ abàmì kan sẹlẹ̀ tí ó yà àwọn àgbàlagbà abúlé lẹ́nu. Ní gbogbo òwúrọ̀, àwọn ará
abúlé máa ń jí láti rí pé ọgbà wọn ti bàjẹ́, oúnjẹ wọn sì dínkù láìníye. Ní ìbẹ̀rẹ̀, wọ́n fi ẹ̀sùn kàn àwọn ẹranko igbó. Sùgbọ́n ọdẹ abúlé sọ pé kò sí ipa ẹsẹ̀
kankan tí wọ́n rí láti fihàn pé ẹranko ni . Olórí abúlé pè gbogbo ènìyàn jọ, ó sì dá ẹgbẹ figilanté tó máa ń sọ́ alẹ́ sílẹ̀.
Àwọn tó yá ara wọn sílẹ̀ fún isé yí mú atupa àti ọpá, wọ́n jókòó nínú òkùnkùn. ọ̀pọ̀ alẹ́ ni kò sí ìșẹ̀lẹ̀ kankan. Șùgbọ́n ní alẹ́ karùn-ún, nígbà tí òșùpá ń
tan lójú ọ̀run, won gbo kìkún légbèé abà ẹ̀lùbọ̀ olórí abúlé. Wọn sare lọ, wọ́n sì rí àwọn ọmọkùnrin àti ọmọbìnrin kan láti abúlé kejì, tí wọ́n ń sa lọ
Ní ọjọ kejì, àwọn àgbàlagbà abúlé lọ sí abúlé yẹn láti bá wọn sọrọ. Ó hàn kedere pé àwọn ọmọ yìí jẹ aláìní, tí ìkànlù omi burúkú kan ti run gbogbo
pẹ̀lú oúnjẹ tí wọ́n jí.
ọgbà wọn. Kódà, ó jẹ́ pé wọ́n ń jì oúnjẹ kí wọ́n lè yè. Eleyi jẹ̀ ohun ti o bani lọkan jẹ̀, wọn si pinnu láti fi oúnjẹ tí wọ́n ní kù fún wọn dipo ìjíyà. Láti ọjọ́
yẹn lọ, ìbáșepọ̀ àti àjọșe dájú láàárín àwọn abúlé méjèèjì.

Kí ló jẹ́ kí wọ́n mọ̀ pé kì í șe ẹranko ni?

AKò sí ọgbà tí a jẹ
BWón ti mú ẹranko náà
CKò sí ariwo kankan tí ẹranko le dá
DOde so pé kò sí ipa ẹsẹ̀ eranko kankan
View Explanation & Discuss
Question 72
jamb 2025

Ka àwọn ayokà isàlè yil, ki o si dáhún àwọn ibéèrè tí ó tèlé won.
Nínú abúlé aláàánú kan tí ó wà láàárín àwọn òkè aláwo ewé, ìșẹ̀lẹ̀ abàmì kan sẹlẹ̀ tí ó yà àwọn àgbàlagbà abúlé lẹ́nu. Ní gbogbo òwúrọ̀, àwọn ará
abúlé máa ń jí láti rí pé ọgbà wọn ti bàj, oúnjẹ wọn sì dínkù láìníye. Ní ìbẹ̀rẹ̀, wọ́n fi ẹ̀sùn kàn àwọn ẹranko igbó. Șùgbọ́n ọdẹ abúlé sọ pé kò sí ipa ẹsẹ̀
kankan tí wọ́n rí láti fihàn pé ẹranko ni . Olórí abúlé pè gbogbo ènìyàn jọ, ó sì dá ẹgbẹ figilanté tó máa ń sọ́ alẹ́ sílẹ̀.
Àwọn tó yá ara wọn sílẹ̀ fún isé yí mú atupa àti ọpá, wọ́n jókòó nínú òkùnkùn. Òpọ̀ alẹ́ ni kò sí ìșẹ̀l kankan. Șùgbọ́n ní alẹ́ karùn-ún, nígbà tí òșùpá ń
tan lójú ọ̀run, won gbó kìkún légbèé abà èlùbọ̀ olórí abúlé. Won sare lọ, wón sì rí àwọn ọmọkùnrin àti ọmọbìnrin kan láti abúlé kejì, tí wọ́n ń sa lọ
Ní ọjọ kejì, àwọn àgbàlagbà abúlé lọ sí abúlé yẹn láti bá wọn sọrọ. Ó hàn kedere pé àwọn ọmọ yìí jẹ aláìní, tí ìkànlù omi burúkú kan ti run gbogbo
pẹ̀lú oúnjẹ tí wọ́n jí.
ọgbà wọn. Kódà, ó jẹ́ pé wọ́n ń jì oúnjẹ kí wọ́n lè yè. Eleyi jẹ̀ ohun ti o bani lọkan jẹ̀, wọn si pinnu láti fi oúnjẹ tí wọ́n ní kù fún wọn dipo ìjíyà. Láti ọjọ́
yẹn lọ, ìbáșepọ̀ àti àjọșe dájú láàárín àwọn abúlé méjèèjì.

Ta ni wón kókó fi èsùn kàn pé ó ń bà ogbà wọn jẹ́?

AÀwọn ọmọ abúlé míì
BỌdẹ abúlé
CÀwọn jàgùdà ìlú
DÀwọn ẹranko igbó
View Explanation & Discuss
Question 73
jamb 2025

Ka àwọn ayokà isàlè yil, ki o si dáhún àwọn ibéèrè tí ó tèlé won.
Nínú abúlé aláàánú kan tí ó wà láàárín àwọn òkè aláwo ewé, ìṣẹ̀lẹ̀ abàmì kan șẹlẹ̀ tí ó yà àwọn àgbàlagbà abúlé lénu. Ní gbogbo òwúrọ̀, àwọn ará
abúlé máa ń jí láti rí pé ọgbà wọn ti bàjẹ́, oúnjẹ wọn sì dínkù láìníye. Ní ìbẹ̀rẹ̀, wọ́n fi sùn kàn àwọn ẹranko igbó. Șùgbọ́n ọdẹ abúlé sọ pé kò sí ipa ẹsẹ̀
kankan tí wọ́n rí láti fihàn pé ẹranko ni . Olórí abúlé pè gbogbo ènìyàn jọ, ó sì dá ẹgbẹ figilanté tó máa ń ṣọ́ alẹ́ sílẹ̀.
Àwọn tó yá ara wọn sílẹ̀ fún isé yí mú atupa àti ọpá, wọ́n jókòó nínú òkùnkùn. ọ̀pọ̀ alẹ́ ni kò sí ìșẹ̀lẹ̀ kankan. Șùgbọ́n ní alẹ́ karùn-ún, nígbà tí òșùpá ń
tan lójú ọ̀run, won gb kìkún legbeé abà ẹ̀lùbọ̀ olórí abúlé. Wọn sare lọ, wọ́n sì rí àwọn ọmọkùnrin àti ọmọbìnrin kan láti abúlé kejì, tí wọ́n ń sa lọ
Ní ọjọ kejì, àwọn àgbàlagbà abúlé lọ sí abúlé yẹn láti bá wọn sọrọ. Ó hàn kedere pé àwọn ọmọ yìí jẹ aláìní, tí ìkànlù omi burúkú kan ti run gbogbo
pẹ̀lú oúnję tí wọ́n jí.
ọgbà wọn. Kódà, ó jẹ́ pé wọ́n ń jì oúnjẹ kí wọ́n lè yè. Eleyi jẹ̀ ohun ti o bani lọkan jẹ̀, wọn si pinnu láti fi oúnjẹ tí wọ́n ní kù fún wọn dipo ìjíyà. Láti ọjọ́
yẹn lọ, ìbáșepọ̀ àti àjọṣe dájú láàárín àwọn abúlé méjèèjì.

Kí ni ișòro tí àwọn ará abúlé kókọ́ dojukọ?

AEranko igbó tí n wọ abúlé wọ́n
BÀrùn kogboogun
CAìrì omi tó tó
DIparun ọgbà àti piparẹ oúnjẹ láìniye
View Explanation & Discuss
Question 74
jamb 2025

Kí ni àfojúsùn orin ewì to pataki?

AIkegan
BIdaraya
CIkeko
DIfigagbaga
View Explanation & Discuss
Question 75
jamb 2025

Àyọkà tí ó ni àfihàn àìtọ́ ẹ̀sùn ni ...?

AKì í șe òun ló jà.
BÓ dájú pé òun ló jà.
CKó tí ẹnikẹ́ni mọ ọ.
DȘé o sọ pé òun ló jà?
View Explanation & Discuss
Question 76
jamb 2025

"Ę má șe je kí ẹ̀mí yín lè” jé ...

AÌbànúję
BÌrírí
CÌmọ̀ràn
DÀkíyèsí
View Explanation & Discuss
Question 77
jamb 2025

Kínní ìtumọ̀ "sáló"?

AGbé
BKó lọ
CBọ̀
DSá asala
View Explanation & Discuss
Question 78
jamb 2025

Àșà ayęyę omọde ní ...?

AÌkàwé
BÌkórè
CÌko ọmọ
DÌpẹ̀yà
View Explanation & Discuss
Question 79
waec 2024

".. lákáayé, Oşinmolė", jé àrà oriki

AEsů
BÖgún
CObàtálá
DOrúnmilà
View Explanation & Discuss
Question 80
waec 2024

______ jé òkan lára àwọn ohun èlò fún híhun

AIgi ewé iran
BIgi oparun
CIgi opę
DIgi ewé akòko
View Explanation & Discuss
Question Navigator
Current
MathsFaculty