Yoruba Past Questions

Study and practice Yoruba past questions with answers and detailed explanations. Then test your knowledge using our interactive CBT practice platform and prepare confidently for your upcoming examinations.

874 questions JAMB 79 WAEC 794 CUSTOM 1
Download PHP app Ask a Question Check Syllabus Past Question Videos Topic Video Lessons

Take a test

Past Questions

874 questions
Question 1 of 20 874 total questions
Question 281
waec 2013

LÍTÍRÉSÒ OGBÓN-İTOPINPIN LÍTÍRÉSÒ

 Irú onà-èdè wo ni a rí nínú àyolà yií?

"İwájú òkun

Okun ni won-ón şe

Eyin Ökun 

Okun ni won-ón şe..."  

 

Aİforòdárà
BÀwítúnwí
CÀsorégèé
Dİfohunpèniyàn
View Explanation & Discuss
Question 282
waec 2013

İTUMO ÈDE

Túmò gbólóhùn tí ó wà ní ibéèrè wòn yí  sí èdè Yorùbá

 Bola washed our dirty linen in public.

 

ABólá fo àwon aso idòtí wa ní ita
BBólá tú àşírí wa ní ita
CBólá bá wa jà ní ita
DBólá sorò wa láida ní ita.
View Explanation & Discuss
Question 283
waec 2013

İTUMO ÈDE

Túmò gbólóhùn tí ó wà ní ibéèrè wòn yí  sí èdè Yorùbá

It rained cats and dogs in Lagos yesterday.

AÖjò rò pa ológbò àti ajá ní Ékó lánàá
BÒjò rò ní Èkó lánàá
CÒjò rò, ó fée wú òkú òle ní Èkó lánàá
DÖjò ro díệ lánàá ní Èkó
View Explanation & Discuss
Question 284
waec 2013

İTUMO ÈDE

Túmò gbólóhùn tí ó wà ní ibéèrè wòn yí  sí èdè Yorùbá

Charity begins at home.

AIwà rere bèrè láti ilé
Bİwà rere lèsó ilé
CIlé la ti ń késòó ròde
DIlé la ti ń késòó iwà ròde.
View Explanation & Discuss
Question 285
waec 2013

İTUMO ÈDE

Túmò gbólóhùn tí ó wà ní ibéèrè wòn yí  sí èdè Yorùbá

You can't have your cake and eat it.

 

AA kií je méji lábà Àlàdé,
BJe àkàrà òyinbó rę kí o sì gbà á padà
CA lè ję àkàrà méji papo
D
View Explanation & Discuss
Question 286
waec 2013

GÍRÁMÀ

 "Folá kò féràn oúnje" jé àpeere gbölóhun  

Aàyísódi
Balákànpò
Conibò
Dàkíyèsí-alátenumó
View Explanation & Discuss
Question 287
waec 2013

GÍRÁMÀ

  "Mo mò pé Olùdáħdè mi ń be láyè Awé gbólóhùn wo ni a fålà sídii rè yi? 

 

 

AAwé gbólóhùn-àfarahe-asàpónlé
BAwé gbólóhùn-àfarahe-asàpèjúwe
CAwé gbólóhùn-àfarahe-oníbá
DAwe gbólóhůn-àfarahe-àsodorúko
View Explanation & Discuss
Question 288
waec 2013

GÍRÁMÀ

  Ewo ni ó ní ibá-isėlè bárakú nínú?

ADoyin á lo sí Ekó
BTósin a máa gbálè
CLádùn ń jeun lówó
DYemisí ti lo
View Explanation & Discuss
Question 289
waec 2013

GÍRÁMÀ

 "Bùnmi pa ejo." Orò-arópò-orúko tí a  le fi rópò 'ejò' ni

Ami
Bwon
Cę
Dá
View Explanation & Discuss
Question 290
waec 2013

GÍRÁMÀ

"Bùkólá féràn emu ogídi." Orò-ise inú gbólóhùn yií ni

ABùkólá
Bféràn
Cemu
Dogídi
View Explanation & Discuss
Question 291
waec 2013

GÍRÁMÀ

  Oro-orúko tí a fi àpètúnpè elébe sèdá rè ni

 

Aodoodún
Bawòràwò
Csísùn
Dgbómogbómo
View Explanation & Discuss
Question 292
waec 2013

ÈTÒ İRÓ

Èwo ni kì í bèrè orò Yorùbá?  

Aİró kóńsónànti
BIró olóhùn kè
Cİró fáwéli
DIró olóhùn isàlè
View Explanation & Discuss
Question 293
waec 2013

ÈTÒ İRÓ

  "Rán aşo" di 'ránso' nípasè

 

Aànkóò fáwéli
Biyópò fáwél
Cijeyopò fáwéli
Dipaje fáwéli
View Explanation & Discuss
Question 294
waec 2013

ÈTÒ İRÓ

 ipín-sí-silébù 'agánnigàn' ni

 

Aagán- nigàn
Bagán-ni-gàn
Ca-gán-ni-gàn
Da-gánni-gàn
View Explanation & Discuss
Question 295
waec 2013

ÈTÒ İRÓ

Silébù métòó ni ó wà nínú Bèlèntàsé?  

 

AMésàn-án
BMéjo
CMéfà
DMárùn- ún
View Explanation & Discuss
Question 296
waec 2013

ÈTÒ İRÓ

Kóńsónànti akùnyùn ni

 

A[kl]
B[g]
C[h]
D[t]
View Explanation & Discuss
Question 297
waec 2013

ÈTÒ İRÓ

 Afipè àsúnsí ni

 

Aètè òkè
Bètè isàlè
Càjà enu
Dògiri ofun
View Explanation & Discuss
Question 298
waec 2013

ÀRÒKO

 "Bá mi kí gbogbo ilé" lè jeyo nínú àròko

Aaşàríyànjiyàn
Başàpèjúwe
Conílétà
Doníròyn
View Explanation & Discuss
Question 299
waec 2013

ÀRÒKO

Orí-òrò wo ló je mó àròko asotàn jů?

 

Ajà ilú mi
BIgi òpę
Cowó ju omo lo
Dİdíjé bóolù kan tí mo wò
View Explanation & Discuss
Question 300
waec 2013

ÀRÒKO

 'İyá' jé orí-orò fún

Aasàpèjúwe
Boníròyin
Casotàn
Dajemó-isipayá
View Explanation & Discuss
Question Navigator
Current
MathsFaculty