Yoruba Past Questions

Study and practice Yoruba past questions with answers and detailed explanations. Then test your knowledge using our interactive CBT practice platform and prepare confidently for your upcoming examinations.

874 questions JAMB 79 WAEC 794 CUSTOM 1
Download PHP app Ask a Question Check Syllabus Past Question Videos Topic Video Lessons

Take a test

Past Questions

874 questions
Question 1 of 20 874 total questions
Question 301
waec 2012

EWÌ: OLAYIWOLA, A ; Akówé  kò wúrà àti àwọn ijìnlè àrofò miràn Nínú ewi "Baba Dáriji Wón"

 Ninú ewi "Ori", Akéwi so pé: Irèké ni ó máa ń dáràn

 

Aatánràn
Bagbálè
Colóko
Dabenilórí
View Explanation & Discuss
Question 302
waec 2012

EWÌ: OLAYIWOLA, A ; Akówé  kò wúrà àti àwọn ijìnlè àrofò miràn Nínú ewi "Baba Dáriji Wón"

Odún mélòó ni wón ní kí Aláàmù omo Şäiná kókó lò lórí oyè?

 

AMéji
BMéta
CMérin
DMárùn-ún
View Explanation & Discuss
Question 303
waec 2012

EWÌ: OLAYIWOLA, A ; Akówé  kò wúrà àti àwọn ijìnlè àrofò miràn Nínú ewi "Baba Dáriji Wón"

Wón ní kí Aláàmù omo Sàiná rú ebo

 

Aàseyorí
Benu
Càsedànù
Dimowàáhù
View Explanation & Discuss
Question 304
waec 2012

LÍTİRÉŞÒ ÀPILÈKO: İTÀN ÀRÒSO 

ÈSÓ-OLÚBÓRÒDÉ, S.: Olorunşogo

 Ta ni Títí lóyún fún?

 

AFémi
BJídé
CGbolá
DAkin
View Explanation & Discuss
Question 305
waec 2012

LÍTİRÉŞÒ ÀPILÈKO: İTÀN ÀRÒSO 

ÈSÓ-OLÚBÓRÒDÉ, S.: Olorunşogo

 Ösė kélòó léyin igbéyàwó ni Fúnké bimo?

AÖsè kejì
BOsè keta
COsè kerin
DÖsè karùn-ún
View Explanation & Discuss
Question 306
waec 2012

LÍTİRÉŞÒ ÀPILÈKO: İTÀN ÀRÒSO 

ÈSÓ-OLÚBÓRÒDÉ, S.: Olorunşogo

 jé olólůfé Lolá lbidùn

 

AOgbéni Èsan
BOgbéni Omódiyà
COgbéni Awé
DOgbéni Oláníyì
View Explanation & Discuss
Question 307
waec 2012

ERÉ ONÍSE: ÒGÚNNÍRAN, L.: Eégún Aláré

  Ta ni Ojélàdé rán kó mú èro  wá fún ðun?

 

AAńséétù
BOjékúnlé
CDásofúnjó
Diyádùn-únní
View Explanation & Discuss
Question 308
waec 2012

ERÉ ONÍSE: ÒGÚNNÍRAN, L.: Eégún Aláré

  idí tí Dắsofúnjó kò fi tèlé òré rè lo si àjo ni pé

 

Aiyàwó rè wà nínú ún
Bó gba işéní àsikò nåà
Ckò nífee si ká máa rin irin-àjò
Didíwó ilé pò fún oun
View Explanation & Discuss
Question 309
waec 2012

ERÉ ONÍSE: ÒGÚNNÍRAN, L.: Eégún Aláré

Ta ni olú èdá-itàn iwé yii? 

A0je Láinnàká
BDúdúyemí
CDásofúnjó
DOjélàdé
View Explanation & Discuss
Question 310
waec 2012

EWÌ: ABÍMBÓLÁ, W.: Awon Odu Mérèrindinlógún (p52-96)

Nínú "Odù Ogúndá Méji"

  jé okan lára àwon tó dífá fún Erigi Àlo

AIgbó
BKanranjágbón
CÖdàn
DÒjöla
View Explanation & Discuss
Question 311
waec 2012

EWÌ: ABÍMBÓLÁ, W.: Awon Odu Mérèrindinlógún (p52-96)

Nínú "Odù Ogúndá Méji"

 Okan nínú ohun tí Ifá ní kí Öòyi òkókó fi rúbo ni

Aòjolá
Bagbòn
Cadie
Dobi
View Explanation & Discuss
Question 312
waec 2012

EWÌ: ABÍMBÓLÁ, W.: Awon Odu Mérèrindinlógún (p52-96)

Nínú "Odù Ogúndá Méji"

 Ta ni a so pé yóò jagbòn obi?

AOrúnmilà
BOjolá
Cijòkùn
DKanranjágbón
View Explanation & Discuss
Question 313
waec 2012

LÍTÍRÉŞO ALOHÙN: iTÀN ÀRÒSO

ÖJO, O.: İjàpà Tirókò Oko Yánníbo Nínú itàn "Ajá àti Ijàpá"

 Nínú itàn "ijàpá àti Awon Eranko, ta ni Baále àwon eranko?

 

AEkùn
BKìnniún
CErin
DEfon
View Explanation & Discuss
Question 314
waec 2012

 

LÍTÍRÉŞO ALOHÙN: iTÀN ÀRÒSO

ÖJO, O.: İjàpà Tirókò Oko Yánníbo Nínú itàn "Ajá àti Ijàpá"

 Ajá so fún jàpá pé kí ó

 

Awa iwònba isu tí ó bá le rù
Bwa isu tí ó le je fün osù kan
Cwa isu púpò
Dmá wà ju isu eyo kan lọ
View Explanation & Discuss
Question 315
waec 2012

 

LÍTÍRÉŞO ALOHÙN: iTÀN ÀRÒSO

ÖJO, O.: İjàpà Tirókò Oko Yánníbo Nínú itàn "Ajá àti Ijàpá"

 Kí ni idí tí orè ijàpá àti Ajá fi wò bée?

AWon joń se egbé kan náà ní
Bİwà won jora
CAlágbára ni àwon méjèèji
DOlóyè ni àwon méjèèji
View Explanation & Discuss
Question 316
waec 2012

LÍTÍRÉŞO oGBÓN-İTỌPINPIN

Ewo ni "àló"?

AÖpá tééré kanlè ó kànrun
BOjó re á dale
CKì í burú títí kó má kenikan móni
D
View Explanation & Discuss
Question 317
waec 2012

LÍTÍRÉŞO oGBÓN-İTỌPINPIN

 Eni gíga ni à ń kì ní

AAgùntásoólò
BAtúnwonká
CAdúmáadán
DAfinjú
View Explanation & Discuss
Question 318
waec 2012

LÍTÍRÉŞO oGBÓN-İTỌPINPIN

"Ó lówó lówó bí sèkèrè" jé

 

Aàfiwé
Bàwítúnwí
Cdídógba
D
View Explanation & Discuss
Question 319
waec 2012

 

LÍTÍRÉŞO oGBÓN-İTỌPINPIN 

Ewo ni ó je àsipa òwe?

 

AOjú méwàá, kò jo ojú eni
B
CBá mi na omo mi, kò dénú olómo
DIlé oba tó jó, ewà ló bù kun
View Explanation & Discuss
Question 320
waec 2012

ITUMO EDE

Túmo gbólóhun tí ó wà ní ibéèrè yin sí èdè Yorùbá

He is trying to know  the matter.

 

AO fe láti mọ orò yen ni àmòjù re
BO ń fé láti mọ àmòjù orò náa
CÓ n gbiyànjú láti mo àtúnbotán òrò náà
Dó n gbiyànjú láti mọ òkodoro orò náà
View Explanation & Discuss
Question Navigator
Current
MathsFaculty