Yoruba Past Questions

Study and practice Yoruba past questions with answers and detailed explanations. Then test your knowledge using our interactive CBT practice platform and prepare confidently for your upcoming examinations.

874 questions JAMB 79 WAEC 794 CUSTOM 1
Download PHP app Ask a Question Check Syllabus Past Question Videos Topic Video Lessons

Take a test

Past Questions

874 questions
Question 1 of 20 874 total questions
Question 291
waec 2013

ÀRÒKO

 Ewo ni létà gbèfe?

ALétà sí ilé-isé olópàá
BLétà isé wíwá
CLétà sí òré
DD. Létà èhónú sí Góminà
View Explanation & Discuss
Question 292
waec 2013

Agbè pàtàki ni Oyèjidé ní agbègbè ibóse. Ki i gbin kòkó, béè ni ki í gbin ògède. Ohun ti ó fi ta àwon egbé rè yọ ni oko àlò tí ó ń dá. A máa tó egbàá mérin. O máa ń gbin ewùrà die, sùgbón èsúrú rè kì í pò púpò. Yàtò sí pé ó jé àgbè, ó tùn gbówó. Lára àwon tí ó bá a pààlà ni Àdisá, Dérin, Arèmú àti Sùúrù. Ogbìn àgbàdo ni ti Àdisá; Dérin a máa dáko rodo; Arèmú àti Sùúrù sì gbádùn gbágùúdá àti ilá ní tiwon. Olè a mảa jà púpò ní agbègbè yií. Púpo nínú àwon àgbè ibóse ti dode àwon olè náà titi sùgbón pàbó ló já si. Ojó tỉ owó pálábả olè kan máa ségi, oko Oyèjidéni ó lo. Léyin tí ó ti palè oko mó láàjin, ó gbé erù; ó fé máa lo. Bí ó ti gbé erù karí ni ó bèrè sí pòòyi lójú kan náà, bệè ni erù kò seẻ sò. Ibè ni ilè mó bả olórò tí àwon olóko dé bá a; wón sì mu un lo sí ilé baálè.

 Òrò miíràn fún 'dode' ninú àyokà yii ni

Asó
Bpa
Cyo
Dnà
View Explanation & Discuss
Question 293

Àkolé tí ó bá àyokà yii mu jù ni

Aoko
BQgbin àgbàdo
CAwọn àgbà İbóse
DÂWọn olè Ibóse
View Explanation & Discuss
Question 294
waec 2013

Agbè pàtàki ni Oyèjidé ní agbègbè ibóse. Ki i gbin kòkó, béè ni ki í gbin ògède. Ohun ti ó fi ta àwon egbé rè yọ ni oko àlò tí ó ń dá. A máa tó egbàá mérin. O máa ń gbin ewùrà die, sùgbón èsúrú rè kì í pò púpò. Yàtò sí pé ó jé àgbè, ó tùn gbówó. Lára àwon tí ó bá a pààlà ni Àdisá, Dérin, Arèmú àti Sùúrù. Ogbìn àgbàdo ni ti Àdisá; Dérin a máa dáko rodo; Arèmú àti Sùúrù sì gbádùn gbágùúdá àti ilá ní tiwon. Olè a mảa jà púpò ní agbègbè yií. Púpo nínú àwon àgbè ibóse ti dode àwon olè náà titi sùgbón pàbó ló já si. Ojó tỉ owó pálábả olè kan máa ségi, oko Oyèjidéni ó lo. Léyin tí ó ti palè oko mó láàjin, ó gbé erù; ó fé máa lo. Bí ó ti gbé erù karí ni ó bèrè sí pòòyi lójú kan náà, bệè ni erù kò seẻ sò. Ibè ni ilè mó bả olórò tí àwon olóko dé bá a; wón sì mu un lo sí ilé baálè.

Akókò wo ni olè yii jà? 

AOru
BÀárò
CIròlé
Dldájí
View Explanation & Discuss
Question 295

Ta lo ń gbin ata?

AAdisá
BDérin
CSùúrù
DOyèjídé
View Explanation & Discuss
Question 296

ni Oyèjidé máa ń gbìn. 

AAgbàdo
BGbảgùúdá
CIsu
DIlá
View Explanation & Discuss
Question 297
waec 2013

Ka àwon àyokà isàle wộnyí, kí o si dáhùn  àwon ibéèrè tí ó tèlé okookan wọn.

Omo meta ni Bájo bi. Adàrán ni àkóbí,  Dáúdà ó tèlé e;ni Adépégà si ni àbikéyin won. Ojó pé tí Adépégà ti bá Adàrán lo sí Owódé lébàá  Itamògån nibi tí Adàrán ti ń şişé. Egbón rè fi i senu ekósé. Léyin tíó kósé si tí ó si yege, o KOja si Orímedù nítòsí Lekí..

 O rówó mú níbè. Ibè ni Fádípe tí ó si ti ri Fádéke omo Fádipe ti o wá fi saya. Olórun fi opò omo won: Jedá, Fémi, Elisá, Bósè, Koyà àti Kolá. Bi ibe şe gbè é tó, kò gbàgbé ilé. Ở pinnu lati padà sí Isòmù, ilú abínibí rè; gbogbo àwon omo re si tèlé e. 

 Akolé tí ó bá àyokà yii mu jù ni 

Algbé avé Adépégà
BIriri àwon omọ Adépégà
CIsé ajé
Dİkóséyege
View Explanation & Discuss
Question 298
waec 2013

Ka àwon àyokà isàle wộnyí, kí o si dáhùn  àwon ibéèrè tí ó tèlé okookan wọn.

Omo meta ni Bájo bi. Adàrán ni àkóbí,  Dáúdà ó tèlé e;ni Adépégà si ni àbikéyin won. Ojó pé tí Adépégà ti bá Adàrán lo sí Owódé lébàá  Itamògån nibi tí Adàrán ti ń şişé. Egbón rè fi i senu ekósé. Léyin tíó kósé si tí ó si yege, o KOja si Orímedù nítòsí Lekí..

 O rówó mú níbè. Ibè ni Fádípe tí ó si ti ri Fádéke omo Fádipe ti o wá fi saya. Olórun fi opò omo won: Jedá, Fémi, Elisá, Bósè, Koyà àti Kolá. Bi ibe şe gbè é tó, kò gbàgbé ilé. Ở pinnu lati padà sí Isòmù, ilú abínibí rè; gbogbo àwon omo re si tèlé e. 

 Omo mélòó ni Fádékę bi?

Améji
Bmérin
Cméfà
Dméjo
View Explanation & Discuss
Question 299

"Rówó mú" nínú àyokà yií túmò sí

Asisé
Bní ilé
Cbímo
Drí se
View Explanation & Discuss
Question 300
waec 2013

Ka àwon àyokà isàle wộnyí, kí o si dáhùn  àwon ibéèrè tí ó tèlé okookan wọn.

Omo meta ni Bájo bi. Adàrán ni àkóbí,  Dáúdà ó tèlé e;ni Adépégà si ni àbikéyin won. Ojó pé tí Adépégà ti bá Adàrán lo sí Owódé lébàá  Itamògån nibi tí Adàrán ti ń şişé. Egbón rè fi i senu ekósé. Léyin tíó kósé si tí ó si yege, o KOja si Orímedù nítòsí Lekí..

 O rówó mú níbè. Ibè ni Fádípe tí ó si ti ri Fádéke omo Fádipe ti o wá fi saya. Olórun fi opò omo won: Jedá, Fémi, Elisá, Bósè, Koyà àti Kolá. Bi ibe şe gbè é tó, kò gbàgbé ilé. Ở pinnu lati padà sí Isòmù, ilú abínibí rè; gbogbo àwon omo re si tèlé e. 

Ta ni ó bí Adépégà?

ADáúdà
BAdàrán
CBàjò
DFádíp
View Explanation & Discuss
Question 301

 Ibo ni ilú Adépégà?

AOwódé
Bİsòmù
Cİtamògàn
DOriímèdú
View Explanation & Discuss
Question 302
waec 2012

ÀSA

 Olóri awo oro ni à ń pè ní

AAlápin-ín- ni
BErelú
CElegun
DAjànà
View Explanation & Discuss
Question 303
waec 2012

ÀSA

  Ewo ni orúko 'àbikú?

ABabátúndé
BMälomo
CEkúndayò
DOgínní
View Explanation & Discuss
Question 304
waec 2012

ÀSA

 Oro wo ni a lè fi dipò 'omidan'?

Aomoge
BIlémosú
COrogún
Dİyáálé
View Explanation & Discuss
Question 305
waec 2012

ÀSA

Ewo ni à n pè ní òrisà ojà?

ABàbá
BOre
Clyå
DEgbon
View Explanation & Discuss
Question 306
waec 2012

 ÀSA

 Fifi ètù pàrokò ránşé túmò si pé

Aoba ti wàjà
Bàşirí tú
Cijà parí
Dogun ń bo
View Explanation & Discuss
Question 307
waec 2012

 ÀSA

 Awon tí ó máa ń lo edan ni

AOníşàngó
BEléégún
COlóya
DBabaláwo
View Explanation & Discuss
Question 308
waec 2012

ERÉ ONÍTẦN: AWÉ, D.: Àpótí Alákàrà

  Okan nínú àwon àgbà ilé Kàrimù ni 

ASààmú
BÀlàké
CAdió
DLálókun
View Explanation & Discuss
Question 309
waec 2012

ERÉ ONÍTẦN: AWÉ, D.: Àpótí Alákàrà

 Isé wO ni Kàrímù yàn láàyò?

AAgbòn hihun
BOlùkó
CÀgbè
DOwó sise
View Explanation & Discuss
Question 310
waec 2012

ERÉ ONÍTẦN: AWÉ, D.: Àpótí Alákàrà

Olú èdá-itàn iwé yií ni

AKàrímù
BOyè
CAbèó
DAńwòó
View Explanation & Discuss
Question Navigator
Current
MathsFaculty